Obìnrin àti ọkùnrin kan tí ń ṣe òwò Bitcoin lórí àwọn fóònù alágbèéká wọn. Obìnrin àti ọkùnrin kan tí ń ṣe òwò Bitcoin lórí àwọn fóònù alágbèéká wọn.

Di olùtajà Bitcoin lórí Paxful

Pawó wọlé nípasẹ títa Bitcoin rẹ lórí Paxful nípa lílo àwọn ìlànà ìsanwó 350+ wa

Pẹlú Paxful, bẹ̀rẹ̀ òwò tìrẹ gan-an ní kánmọ́kánmọ́. Ṣẹdá àwọn ìnájà pẹ̀lú Bitcoin rẹ, ṣètò àwọn èrè, kí o ṣàgbékalẹ̀ ìrírí alábàárà aláìlẹ́gbẹ́ láti mú àwọn èrè rẹ pọ̀ síi. Forúkọsílẹ̀ bíi olùtajà lónìí kí o ṣẹdá ìnájà àkọ́kọ́ rẹ..*

Forúkọ mi sílẹ̀!
 • Icon depicting multiple features on Paxful.

  Ètò tí ó tọ ti àwọn ẹyà láti ṣàkóso àwọn òwò rẹ, àwọn ìnájà, àti àwọn ìṣirò

 • Icon depicting Paxful's large user base.

  Àwọn àṣàmúlò tó ju mílíọ̀nù 6 lọ, ní wọ́n forúkọsílẹ̀ káríayé

 • Icon showing multiple registered vendors on Paxful.

  Àwọn olùtajà Bitcoin tí o forukọsilẹ ti o ju12,000 lọ ló gbẹ́kẹ̀lée

 • Chat icon implying the high-quality support offered by Paxful.

  Àtìlẹyìn Ojúlówó fún ìrírí ìdókòwò àìlálébù

The Paxful vendor dashboard showing various useful metrics, details of active trades and also the verification status of the vendor. The Paxful vendor dashboard showing various useful metrics, details of active trades and also the verification status of the vendor.

Mú Bitcoin rẹ wa sí Paxful kí o táá láti jèrè

 • Àwọn Ìlànà ìsanwó 350+
 • Owósan ìdúnàádúrà 0-2%
 • Àtìlẹ́yìn VIP fún àwọn olùtajà tí ó ra pupọ
 • Àkópọ ti àwọn ìdúnàádúrà àti àwọn owó-apáwọlé
 • Ètò ìbanipolówó láti mú àwọn olùtajà tuntun wọlé àti ṣe imúgbòòrò òwò rẹ

Ṣowò lórí Paxful kí o bẹrẹ ìṣòwò ti fintech tìrẹ

Iye owó Bitcoin lọwọlọwọ: 
Ọkùnrin kan ti ó ń tọka sí ìnájà òwò Bitcoin tí ó fẹràn lójú ìbòjú kan.

1. Ṣẹ̀dá tàbí ìnájà kan

O lé lọ kiri tàbí ṣẹdá àwọn ìnájà fún ríra àti títa Bitcoin. Ṣètò àwọn òṣùwọn tìrẹ, wá olùbádòwòpọ̀, kí o ṣe ìdúnàádúrà àkọkọ rẹ lóní.

A man selecting a profile image for his Paxful account.

2. Ṣàgbékalẹ̀ aṣàpèjúwe rẹ

Wá àwọn olùrajà nípa ìparí ìjẹ́rìísí, fifí àwòrán aṣàpèjúwe kún, àti ìkójọpọ àwọn ìjábọ̀ tó ní ìlera. Níní ìtàn-àkọọlẹ tí ìlèra tó pẹ́ mú kí ìgbayìsí rẹ pọ sí àti ṣe ìrànlọwọ fún ọ láti fọkàntán àwọn oníbárà tó ṣeé ṣe.

A man and a woman smiling and cheering a successful trade they completed on Paxful.

3. Ṣòwò kí o jèrè tó pọ̀

Ra lówó tó kéré, ta lówó tó ga. Èyí ni ìpìlẹ tí àwòṣe ìṣòwò ńlá àti pé a gbà. Kọ ẹkọ síwájú síi nípa àwọn àrékérekè tí ìdókòwò lórí Paxful, láti ilé-iṣẹ ìrànlọwọ wa.

An image showing the Paxful app on a mobile device with links to download it on both iOS and Android.

Mọ bó ṣé ńlọ, nígbàkugbà, níbikíbi

Máṣe yọ ara rẹ lẹnu nípa pípàdánù àwọn òwò tí ó ṣeé ṣe, tàbí àwọn ìfiránṣẹ láti ọdọ àwọn alabara. Paxful jẹ ìrọrùn-láti-lò àti ṣiṣẹ lórí gbogbo àwọn ẹrọ rẹ. Àwọn ètò isẹ-ṣíṣe iOS àti Android wa, yóò ríi dájú pé o wà pẹlú wa nígbàgbogbo àti pé o ṣetán fún ìgbésẹ̀.

Àwọn olùtajà Bitcoin tí o forukọsilẹ ti o ju 12,000 lọ ló gbẹ́kẹ̀lée

 • Kareninsf user avatar image

  Kareninsf

  Paxful vendor - USA

  Paxful is a wonderful place to buy and sell Bitcoin! I started trading as a small hobby, but I'm now addicted to selling Bitcoin. I love how helpful and welcoming the Paxful community is. I also like that Paxful's dynamic support team is always available in a heartbeat if needed.

 • MaineBitcoin user avatar image

  MaineBitcoin

  Paxful vendor - Maine, USA

  Being a paxful vendor has been great. Support is always responsive and helpful, and best of all I've been able to help many new Bitcoin users get some of their first Bitcoin. It's always rewarding to be the first on-ramp to the currency of the future.

A man introducing and explaining Paxful affiliate program to his friend. A man introducing and explaining Paxful affiliate program to his friend.

Pawó sii pẹlú Ètò ìbanipolówó Paxful

A ṣẹdá Ètò ìbanipolówó Paxful láti ṣe ìrànlọwọ fún ọ láti mú àlékún àwọn èrè rẹ pọ sí nípasẹ pípe àwọn ọrẹ rẹ, ẹbí rẹ, àti nẹtiwọọki tí o gbòòrò sí ìkànnì wa.

Àwọn èrè lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ lórí Gbogbo òwò:

 • 50% ti Ìpele 1 owósan ìbanipolówó rẹ
 • 10% ti Ìpele 2 owósan ìbanipolówó rẹ tí àwọn Abánipolówó wọn ti san
Wo síwájú síi

* O lóye àti gbà pé Paxful kò pèsè òfin, owó-orí, tàbí ìmọràn ìdókowò, àti sí iye tí o ríi pé o ṣe pàtàkì, ìwọ yóò ní ìmọràn pẹlú àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ òṣìṣẹ ní àṣẹ ti ara rẹ ṣáájú lílo ìkànnì ẹnìkan-sí-ẹnìkejì Paxful àti di olùtajà kan. Jọwọ rántí pé iṣẹ tí o kọjá kìí ṣe ìtọkasí iṣẹ́ iwájú. Paxful kò ṣe ìdánilójú èyíkèyí tàbí àwọn ìlérí mííràn nípa iṣẹ́ ìṣúná owó èyíkèyí tàbí àwọn àbájáde tí o lè gbà làti di olutaja Paxful àti pé o lóye àti gbà pé gbogbo àwọn ìpinnu láti lo ìkànnì ẹnìkan-sí-ẹnìkejì Paxful jẹ tìrẹ lódindi àti lápapọ. O lóye o sì gbà pé a kò gba èyíkèyí ojúṣe ohunkóhun fún, àti pé kò si àwọn àyídáyidà ní yóò ṣe onídúró fún ọ ní àsopọ pẹlú, àwọn ìpinnu rẹ. O lóye o sì gbà pé lábẹ àwọn àyídáyidà kankan ni lílo ìkànnì ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti Paxful àti di olùtajà ni ó yẹ láti ṣẹdá ìbátan kan tí ó ní ìpèsè tàbí fífúnni ìmọràn ti ìdókowò.