Ìfẹnukò Ìlò Stablecoin Paxful

Ọjọ́ tí yóò bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́: Ẹrẹ́nà (March) 4, 2021

JỌ̀WỌ́ KA ÀDÉHÙN YÌÍ YÉKÉYÉKÉ. Nípa lílo ètò Stablecoin Paxful, ìwọ́ gba láti jẹ́ dídè pẹ̀lú àfikún "Ìfenukò Ìlò Stablecoin Paxful" wọ̀nyíí ìwọ́ sì gbà wípé ìwọ́ ti kà pẹ̀lú ìfura, ní òye, sì ti gba gbogbo àwọn àdéhùn àti àwọn àlàálẹ̀ tó wà nínu rẹ̀, èyí tó jẹ́ àfikún Ìfenukò Ìlò Paxful ("Àdéhùn" náà). Èyíkèyí àwọn àkànlò èdè tí a lò sùgbọ́n tí a kò túnmọ̀ sí ìsàlẹ̀ ní ìtumọ̀ wọn wà ní inú Àdéhùn. Tí èyíkèyí ìforígbárí bá wáyé láàrin Àdéhùn náà àti Ìfenukò Ìlò Stablecoin Paxful ní àsìko tàbí tó ní ìbátan pẹ̀lú ìlò ètò Stablecoin Paxful rẹ, Ìfenukò Ìlò Stablecoin Paxful ni yóò borí.

Nípa Stablecoin Paxful

Ètò Stablecoin Paxful jẹ́ ètò àpèwárajà tó f'àyè gbà ọ́, gẹ́gẹ́ bíi aṣàmúlò Paxful tó yẹ, láti wọ ìdúnadúrà ẹnìkan-sí-ẹnìkejì pẹ̀lú ilé-isé ẹnìkẹta tí a ti ṣáájú yàn ("Ẹlẹ́gbẹ́ Stablecoin"), tí Paxful mú, fún pàsípààrọ̀ Bitcoin rẹ fún àwọn stablecoin tí iye wọn ṣe déédé USD, tí yóò jẹ́ ìdìmú gbati ọwọ́ Ẹlẹ́gbẹ́ Stablecoin fún ànfààní rẹ. Nípasẹ̀ àwòṣe yìí, Stablecoin Paxful gba ìwọ láàyè láti kúrò ní ipò Bitcoin rẹ bọ́ sí stablecoin tío yàn.

Ètò Àpèwárajà

Ètò ìlò Stablecoin Paxful jẹ́ ọ̀nà àpèwárajà ìdíwọn tó wà lórí ìkànnì Paxful. Tí ìwọ bá ti fìfẹ́hàn sí ṣíṣe ìdúnadúrà Stablecoin Paxful, Paxful yóò darí rẹ lọ sí Ẹlẹ́gbẹ́ Stablecoin fún ṣíṣe ìdúnadúrà náà. Ìwọ́ gbọdọ̀ wá pèsè àwọn ìlànà láti lè fi àwọn àdéhùn náà sílẹ̀ fún Ẹlẹ́gbẹ́ Stablecoin. Tí Ẹlẹ́gbẹ́ Stablecoin bá gba àwọn àdéhùn ìnájà rẹ, ìdúnadúrà náà yóò jẹ́ ṣíṣe láàrin ìwọ àti Ẹlẹ́gbẹ́ Stablecoin. Fún àwọn ìdúnadúrà tó dójú ìwọ̀n tí ìwọ́ ṣe lórí ibi ìtajà rẹ̀, Paxful kò ní ìlọ́wọ́sí, àkóso, agbára, òye, tàbí àṣẹ níbi àwọn ìdúnadúrà Stablecoin Paxful tí ìwọ́ wọ̀ tàbí gbìyànju láàrin ìwọ àti Ẹlẹ́gbẹ́ Stablecoin. Paxful kò ní gba àwọn stablecoin sí ọ̀dọ̀ tàbí gbà ọ́ ní ìmọ̀ràn tàbí sọ fún èyíkèyí aṣàmúlò Paxful láti ra irú àwọn stablecoin bẹ́ẹ̀.

Ẹlẹ́gbẹ́ Stablecoin lè ní àwọn àdehùn àti àlàálẹ̀ tiwọn fún àwọn ìdúnadúrà ètò Stablecoin Paxful, àti pé ètò Stablecoin Paxful lè yàtọ̀ ní òṣùwọ̀n pàsípààrọ̀, ìyára pàṣípààrọ̀, àti àwọn àdehùn àti àlàálẹ̀ mííràn tí Ẹlẹ́gbẹ́ Stablecoin lè gbé kalẹ̀ ("àwọn Àdéhùn Ẹlẹ́gbẹ́ Stablecoin"). Nípa wíwọ ìdúnadúrà pẹ̀lú Ẹlẹ́gbẹ́ Stablecoin ìwọ́ gbà láti jẹ́ dídè pẹ̀lú àwọn Àdéhùn Ẹlẹ́gbẹ́ Stablecoin. Àwọn Àdéhùn Ẹlẹ́gbẹ́ Stablecoin tọ̀nà ní gbogbo àwọn ọ̀ràn àyàfi nígbà tí wọ́n bá tako tàbí ní ìforígbárí pẹ̀lú Àdéhùn náà, àwọn Ìfenukò Ìlò Stablecoin Paxful yìí, kò b'ófìnmu, kò mú ọgbọ́n lọ́wọ́ tàbí bíbẹ́ẹ̀kọ́ ó nira láti ní ìbámu pẹlú (gẹ́gẹ́bí a ti pinnu ní àdáṣe Paxful àti làkáyè pípé), tàbí tí ìwọ àti Ẹlẹ́gbẹ́ Stablecoin fọwọ́si láti pààrọ̀ àwọn Àdehùn Ẹlẹ́gbẹ́ Stablecoin. OJÚṢE RẸ NI LÁTI FARABALẸ̀ KA ÀWỌN ÀDEHÙN ẸLẸ́GBẸ́ STABLECOIN ÀTI TẸ̀LÉ WỌN BÍ WỌ́N ṢE WÀ.TÍ ÌWỌ KÒ BÁ TẸ̀LÉ ÀWỌN ÀDEHÙN ẸLẸ́GBẸ́ STABLECOIN, ÌDÚNADÚRÀ RẸ LE MÁ JẸ́ ÌTẸ́WỌ́GBÀ. MÁ ṢE WỌ ÌDÚNADÚRÀ ÌLÒ STABLECOIN PAXFUL ÀYÀFI TÍ ÌWỌ BÁ TI TẸ̀LÉ GBOGBO ÀWỌN ÀDEHÙN ÀTI ÀLÀÁLẸ̀ TÍ A ṢE ÀTÒKỌ WỌN. TÍ ÌWỌ BÁ KÙNÀ LÁTI TẸ̀LÉ ÀWỌN ÀDEHÙN ÀTI ÀLÀÁLẸ̀ NÁÀ, PAXFUL LE MÁ LE RAN ÌWỌ LỌ́WỌ́ NÍNÚ ÌṢAÁYAN ÀRÍYÀNJIYÀN LÁTI GBA OWÓ RẸ PADÀ.

Àwọn Owósan

Paxful yóò kó àkóyawọ́ nípa àwọn owósan wa nígbà gbogbo. Èyíkèyí àwọn owósan ni yóò wà fún ìlò àwọn iṣẹ́ Paxful rẹ. Fún àlàyé síi àti àwọn ìmúdójúìwọ̀n lóri àwọn owósan ìyípadà, jọ̀wọ́ tọ́ka sí Ibùdó Ìrànwọ́ wa.

Àwọn Àkántì Ìyege àti àwọn Sàkání Òfin tó wà ní Ìhámọ́

Ètò ìlò Stablecoin Paxful ní a jẹ́ kó wà fún àwọn aṣàmúlò tí wọ́n yẹ fún ètò náà nìkan. Láti yẹ fún lílò ètò Stablecoin Paxful náà, ìwọ́ gbọdọ̀ jẹ́rìí sí àkántì rẹ kí o sì ní Bitcoin tí iye rẹ̀ tó USD $1.00 nínú wálẹ́ẹ̀tì Paxful rẹ, àti èyíkèyí àfikún iye Bitcoin tó nílò láti san èyíkèyí àwọn owósan tó so máa. Paxful ní ẹ̀tọ́ láti dènà tàbí ṣe àyípadà ètò Stablecoin Paxful fún èyíkèyí aṣàmúlò Paxful Paxful, Ẹlẹ́gbẹ́ Stablecoin sì le kọ èyíkèyí ìdúnadúrà pẹ̀lú èyíkèyí aṣàmúlò Paxful. Ní àfikún sí àwọn Sàkání Òfin tó wà ní Ìhámọ́ bí wọ́n ti ṣe gbée kalẹ̀ ní Abala 2.7 ti Ìfenukò Ìlò wa, ètò Stablecoin Paxful kò sí fún àwọn aṣàmúlò tí wọ́n ń gbé ní Ìpínlè Texas.

KÒ SÍ ÀTÌLẸYÌN ỌJÀ, ÌDIWỌ̀N LAYABÍLÍTÌ & ÀRÒSÍNÚ TI EEWU

ÀWỌN ÌLÒ STABLECOIN PAXFUL NI A PÈSÈ LÓRÍ “ BÍ Ó TI ṢE RÍ” ÀTI “BÍ Ó ṢE WÀ“ LÁÌSÍ ÈYÍKÉYÌ ÀWỌN ÌṢÈDÚRÓ, ÀWỌN AṢOJÚ TÀBÍ ÀWỌN ÀTÌLẸYÌN ỌJÀ, BÓYÁ ÌYÁRA, ÌDÁBÁ TÀBÍ ỌRANYÀN. SI IYE TI Ó PỌ̀JÙ TI ÒFIN TÓ WÀ FÚN UN GBÀ LÁÀYÈ, PAXFUL NI PÀTÓ KỌ ÈYÍKÉYÌ ÌDÁBÁ ÀWỌN ÀTÌLẸYÌN ỌJÀ TI O NÍ ÀKỌLÉ, TÍ Ó ṢEÉ TA, DÍDÁRA FÚN ÌDÍ KAN ÀTI/TÀBÍ ÀÌLÒDÌSÁDÉHÙN.PAXFUL KÒ ṢE ÈYÍKÉYÌ ÀWỌN AṢOJÚ TÀBÍ ÀWỌN ÀTÌLẸYÌN ỌJÀ TÍ Ó NÍ IRAYE SÍ WẸ́BÚSÁÌTÌ, ÈYÍKÉYÌ Ẹ̀YÀ TI ÀWỌN IṢẸ́, TÀBÍ ÈYÍKÉYÌ TI ÀWỌN OHUN ÈLÒ TI O WÀ NÍBÍ,YÓÒ TẸSÍWÁJÚ LÁÌSÍ ÌDÁDÚRÓ, LÁSÌKÒ, TÀBÍ LÁÌNÍ ÀṢÌṢE. PAXFUL KÌÍ ṢE ONÍDÙÚRÓ FÚN ÈYÍKÈYÍ ÌDÁLỌ́WỌ́DÚRÓ TÀBÍ ÌPÀDÁNÙ TÍ AṢÀMÚLÒ LÈ KOJÚ.ÌWỌ NIBIYI GBÀ ÀTI GBÀ PÉ ÌWỌ KÓ DÚRÓ LÓRÍ ÈYÍKÈYÍ ÀLÀYÉ MÍRÀN TÀBÍ AGBỌYE, BÓYÁ KÍKỌ TÀBÍ SÍSỌ, NÍ ÌBÁMÚ SÍ LÍLÒ ÀTI IRAYE TI ÀWỌN IṢẸ́ ÀTI WẸ́BÚSÁÌTÌ.LÁÌSÍ ÒPIN ÌTÈ̩SÍWÁJÚ NÁÀ. ÌWỌ NIBIYI GBÀ ATI GBÀ PÉ ORÍṢIRÍṢI ÀWỌN EEWU ÀJOGÚNBÁ TI LÍLO KỌ́RẸ́ŃSÌ-ONÍDÍJÍTÀ PẸ̀LÚ ṢÙGBỌ́N TI KÌÍ ṢE ÒPIN SÍ ÌKÙNÀ Ẹ̀YÀ ARA KOMPUTA, WÀHÁLÀ SOFITIWIA, ÌKÙNÀ ASOPO ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ, FAIRỌSI SOFITIWIA, ITOJUBỌ ENIKETA TÍ O ṢE OKÙNFÀ ÌPÀDÁNÙ TÀBÍ AIRAYE SÍ ÀKÁNTÌ TÌRẸ TÀBÍ WÁLẸ́Ẹ̀TÌ ÀTI DÁTÀ AṢÀMÚLÒ MÍRÀN, ÌKÙNÀ Ẹ̀RỌ OLUPIN TÀBÍ IPADANU DÁTÀ. ÌWỌ GBÀ ÀTI GBÀ PÉ PAXFUL KÌÍ YÓÒ ṢE ÌDÚRÓ FÚN ÈYÍKÈYÍ ÀWỌN ÌKÙNÀ IBASORO, ÀWỌN ÌDÁLỌ́WỌ́DÚRÓ, ÀṢÌṢE IDANUJU TÀBÍ ÌDÁDÚRÓ TÍ ÌWỌ LÈ FOJÚWINÁ NÍ LÍLO ÀWỌN IṢẸ́, SÍBẸ̀SÍBẸ̀ TI ṢẸLẸ̀.

NÍ ÌṢẸ̀LẸ̀ KÍ ÌṢẸ̀LẸ̀ NÍ PAXFUL, ÀWỌN ABÁNIPOLÓWÓ RẸ̀ ÀTI ÀWỌN OLÙPÈSÈ IṢẸ́ , TÀBÍ ÈYÍKÈYÍ TI ÀWỌN Ọ̀GÁ WỌN, ÀWỌN ADARÍ, ÀWỌN OLÙRÀNLỌ́WỌ́, ÀWỌN ÒṢÌṢẸ́, ÀWỌN ONIMORAN, ÀWỌN AGBANI-NÍMỌ̀RÀN, TÀBÍ ÀWỌN AṢOJÚ, YÓÒ JẸ́ ONÍDÙÚRÓ (A) FÚN ÈYÍKÉYÌ IYE TI Ó TÓBI JU IYE OWÓSAN ÀPAPỌ̀ TÍ ÌWỌ SAN FÚN IṢẸ́ TÍ Ó JẸ́ OKÙNFÀ FUN ÌṢE NI ÀWỌN OṢÙ KEJÌLÁ (12) SÍWÁJÚ SÍ ÌPÀDÁNÙ LÁTÀRÍ (B) FÚN ÈYÍKÈYÍ ÌPÀDÁNÙ ÀWỌN ÈRÈ, IJAWALE NÍYE TÀBÍ ÀNFÀNÍ ÌṢÒWÒ, ÈYÍKÉYÌ ÌPÀDÁNÙ, ÌBÀJẸ́, ÀJẸBÁNU, TÀBÍ IRUFIN TI DÁTÀ TÀBÍ ÈYÍKÉYÌ OHUN ÌNÍ TÍ KÒ TO PỌ́N MÌÍRÀN TÀBÍ ÈYÍKÉYÌ PÀTÀKÌ, ÌṢẸ̀LẸ̀, AIṢE-TÀÀRÀ, KÒTÓPỌ́N, TÀBÍ ÀWỌN ÌBÀJẸ́ ALEYIN, BÓYÁ DÁ LÓRÍ ÀDÉHÙN, ÌPALÁRA, ÀÌKỌBIARASÍ, ÌDÚRÓ TÓ GBÓPỌN, TÀBÍ BIBEEKO, TÍ. Ó JẸYỌ LÁTÀRÍ TÀBÍ NÍ ASOPO PẸ̀LÚ ALÁṢẸ TÀBÍ. AIGBASE LÍLO WẸ́BÚSÁÌTÌ TÀBÍ ÀWỌN IṢẸ́, TÀBÍ ÀDÉHÙN YÍÍ, PÀÁPÀÁ TÍ AṢOJÚ ALÁṢẸ TI PAXFUL KAN BÁ TI GBA ÌMỌ̀RÀN TI TÀBÍ TI MỌ̀ TÀBÍ YẸ KÓ TI MỌ̀ TI ÌṢE E ṢÉ TI ÌBÀJẸ́, ÀTI PẸ̀LÚPẸ̀LÙ IKUNA TI ÈYÍKÉYÌ TI GBÀ TÀBÍ ÀTÚNṢE ÒMÍRÀN FÚN KÒṢEMÁNÌ ÌDÍ, ÀYÀFI SÍ IYE ÌPINNU ÌPARÍ ÌDÁJỌ́ PÉ ÀWỌN ÌBÀJẸ́ JẸ́ ÀBÁJÁDE ÀÌKỌBIARASÍ ŃLÁ TI PAXFUL, JÌBÌTÌ, IWA-ÌBÀJẸ́ ÀMỌ̀MỌ́Ọ̀ṢE TÀBÍ IRUFIN MÍMỌ̀Ọ́MỌ̀. DÍẸ̀ NÍNÚ ÀWỌN ÀYÍKÁ ÌDÁJỌ́ KÒ FÀYÈ GBA ÌYỌKÚRÒ TÀBÍ ÌDÓPIN ÌṢẸ̀LẸ̀ ÀÌMỌ́ TÀBÍ ÀWỌN ÌBÀJẸ́ ALẸ́YÌN, KÍ ÌDÓPIN TI ÒKÈ LE MÁ KAN ÌWỌ.