Ra Bitcoin ní Singapore

Gbígbé ìgbésẹ̀ àkọ́kọ́ sínú ayé kírípítò ti wá di ìrọ̀rùn pẹ̀lú Paxful, aṣíwájú ibi ìtajà Bitcoin tó ń lo agbára àwọn ènìyàn ní àgbáyé lónìí. Ní báyìí, ìwọ́ lè yí SGD padà sí BTC lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ pẹ̀lú títẹ ẹ̀rọ laptop rẹ tàbí fóònù díẹ̀.

Ní kété tí o bá ṣẹ̀dá àkántì, o ní ẹ̀tọ́ sí Wálẹ́ẹ̀tì Bitcoin ọ̀fẹ́, níbi tí o ti lè ṣàkóso àwọn owó kírípítò rẹ láìṣe wàhálà ní 24/7. O tún lè gbàá sórí ẹ̀rọ iOS tabi ẹ̀rọ Android rẹ, nítorínáà o lè mú owó rẹ pẹ̀lú rẹ lọ ibikíbi tí o fẹ́. Pẹ̀lú ètò ààbò wa tó ga jù àti àwọn ìlànà ìjẹ́rìísí àkántì dandan lóri ìkànnì náà, o lè rí àrídájú pé àwọn owó rẹ ní ààbò nígbàgbogbo. Lórí èyí, ẹgbẹ́ àtìlẹ́yìn oníbàárà wa ti ṣetán láti ràn ọ́ lọ́wọ́ pẹ̀lú èyíkèyí àwọn ìbéèrè tí o lè ní.

Fún ìdí èyí, ṣé o ṣetán láti lọ ìrìn-àjò ìnáwó àìlẹ́gbẹ́ sì ní èrè? Forúkọsílẹ̀ lóri Paxful lónìí, ra Bitcoin ní Singapore, kí o sì mú ara rẹ súnmọ́ òmìnira ìnáwó. A yóò rí ọ nítòsí!

Àwọn ìnájà tí wọ́n lékè fún Dọ́là Singapore ní Singapore

Olùtàjà Sanwó pẹ̀lú Tí ó kéré jù

láti san

láti san

Lórí dọ́là

aribtc +291
Ti ríi ìsẹjú 1 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì ALL SG BANKS INSTANT
74.00 SGD $0.92
kò sí àwọn ẹnìkẹta
BaiWanShenJia +2080
Ti ríi ìsẹjú 23 kọjá
Káàdì Ẹ̀bùn iTunes Accept the code BRL
15.00 SGD $0.69
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn káàdì àfojúrí nìkan Paxful 6
cshd5lypav +3722
Orí Ayélujára
Káàdì Ẹ̀bùn Wálẹ́ẹ̀tì Steam FAST Release In 1 Min
14.00 SGD $0.66
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó
Chin5418 +4915
Orí Ayélujára
Káàdì Ẹ̀bùn iTunes Fast safe and honest
50.00 SGD $0.67
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn káàdì àfojúrí nìkan
Shanial1996 +449
Ti ríi wákati 1 kọjá
PayPal
50.00 SGD $0.67
Cudoli +1538
Orí Ayélujára
Káàdì Ẹ̀bùn iTunes Honest fast and professi
50.00 SGD $0.67
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn káàdì àfojúrí nìkan Paxful 6
AgileSturgeon371 +2527
Orí Ayélujára
Káàdì Ẹ̀bùn iTunes Honest fast and reliable
50.00 SGD $0.68
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó kò nílò ìjẹ́rìísí
AcuteMudfish625 +704
Ti ríi ìsẹjú 2 kọjá
Káàdì Ẹ̀bùn iTunes Quick honest
50.00 SGD $0.69
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn káàdì àfojúrí nìkan Paxful 6
ItunesGoogleSteamAmazon +18796
Orí Ayélujára
Káàdì Ẹ̀bùn iTunes Fast transaction
50.00 SGD $0.70
àwọn káàdì àfojúrí nìkan
richard886521 +1473
Ti ríi ìsẹjú 3 kọjá
Káàdì Ẹ̀bùn Wálẹ́ẹ̀tì Steam Honest and fast
15.00 SGD $0.65
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn káàdì àfojúrí nìkan kò nílò ìjẹ́rìísí
SnapSparrow18 +1522
Orí Ayélujára
Káàdì Ẹ̀bùn iTunes Honest and fast trading
50.00 SGD $0.70
àwọn káàdì àfojúrí nìkan àwọn ìsanwó orí ayélujára
Chinesered +4555
Orí Ayélujára
Káàdì Ẹ̀bùn iTunes SGD
50.00 SGD $0.70
àwọn káàdì àfojúrí nìkan
KindMonjita834 +2482
Ti ríi ìsẹjú 1 kọjá
Káàdì Ẹ̀bùn iTunes Paxful6
15.00 SGD $0.71
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn káàdì àfojúrí nìkan Paxful 6
Yingzi1993 +10577
Ti ríi wákati 4 kọjá
Káàdì Ẹ̀bùn iTunes honest and fast
50.00 SGD $0.71
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó ó ń gba àwọn kóòdù orí ẹ̀rọ ayélujára
new_start +765
Ti ríi ìsẹjú 1 kọjá
Káàdì Ẹ̀bùn iTunes SGD itunes A rapid and re
50.00 SGD $0.71
àwọn káàdì àfojúrí nìkan
Peak1Steam +29942
Orí Ayélujára
Káàdì Ẹ̀bùn iTunes Honest and Fast
15.00 SGD $0.71
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn káàdì àfojúrí nìkan kò nílò ìjẹ́rìísí
iGGTeam +5914
Orí Ayélujára
Káàdì Ẹ̀bùn iTunes SGD
30.00 SGD $0.65
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn káàdì àfojúrí nìkan kò sí àwọn ẹnìkẹta
VVVBB112_FAST_SAFE +8057
Orí Ayélujára
Káàdì Ẹ̀bùn Wálẹ́ẹ̀tì Steam Trusted And Within 1min
20.00 SGD $0.63
ó ń gba àwọn kóòdù orí ẹ̀rọ ayélujára kò nílò ìjẹ́rìísí Paxful 6
flaviopedota +4056
Ti ríi ìsẹjú 4 kọjá
Káàdì Ẹ̀bùn iTunes fast
25.00 SGD $0.71
àwọn káàdì àfojúrí nìkan Paxful 6
MiKeTOO +2639
Ti ríi ìsẹjú 5 kọjá
Káàdì Ẹ̀bùn iTunes Fast and honest
50.00 SGD $0.50
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn káàdì àfojúrí nìkan

Àwọn ìlànà ìsanwó tí wọ́n lékè ní Singapore

Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

PayPal

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú PayPal lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú PayPal

Ìsanwó WeChat

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìsanwó WeChat lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìsanwó WeChat

Káàdì Ẹ̀bùn iTunes

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn iTunes lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn iTunes

Káàdì Ẹ̀bùn Wálẹ́ẹ̀tì Steam

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Wálẹ́ẹ̀tì Steam lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Wálẹ́ẹ̀tì Steam

Káàdì Ẹ̀bùn eBay

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn eBay lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn eBay

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.

Ṣé mo lè ta Bitcoin lórí Paxful?

Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn èèyàn mìíràn ní Singapore láti rí Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó tó 60% lórí títa ẹyọ kọ̀ọ̀kan. Bẹ̀rẹ̀ títa pẹ̀lú àkántì báǹkì abẹ́lé rẹ báyìí, wo ìtọ́nisọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful yóò ní 1000's olùrajà Bitcoin láti Singapore ní ojoojúmọ́.

Ṣẹda àkántì ki o bẹ̀rẹ̀ títà

Owó Àìlágùnjìnàfún

Ṣé o ma ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó fẹ́ ra Bitcoin ní Singapore? Pẹlú Kíọ̀sì Bitcoin àti ètò Ìbánipolówó rẹ ìwọ yóò gba 2% lórí òwò kọ̀ọ̀kan títí láyé nípa pínpín ìtọ́kasí. Bẹ̀rẹ̀ Báyì.