Paxful in Russia

We're committed to growing global financial inclusion by making cryptocurrency trading easy, fair and safe. Due to international restrictions on certain geographies, government bodies, businesses or persons by which Paxful must abide, we're not always able to offer Paxful's popular platform in every region. At the moment, Paxful does not serve users in Russia. There are no individual exceptions being made, nor is a timeline available for the reversal of this decision.

Kó owó s'óri Bitcoin ní ìrọ̀rùn àti ààbò. Paxful nibi to dára jù láti ra, ta àti fi ránṣẹ́ pẹ̀lu ó lé ní ọ̀nà 300 láti sanwó fún Bitcoin pẹ̀lú ìfiránṣẹ́ nípaṣẹ̀ ilé ìfowópamọ́, káàdì ẹ̀bùn, Paypal, Western Union, Moneygram, àwọn káàdì ìsanwó/ìpawó rẹ àti bẹ́ẹ̀ lọ!

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.