Ra Bitcoin ní Nàìjíríà

Paxful ni aṣíwájú ibi ìtajà enìkan-sí-ẹnìkejì fún Bitcoin ní àgbáyé—ó sì ti wà ní Nigeria! Pààrọ̀ owó Naira (NGN) rẹ sí BTC ní kíákíá àti ní ìrọ̀rùn!

Find great deals for Bitcoin on Paxful from thousands of available offers—all with zero extra fees and over 450 different payment methods, allowing for cost-efficient trades on the platform.

Nàìjíríà ti gba Bitcoin mọ́ra ní ọ̀nà tó tóbi àwọn nọ́mbà kò sì kín parọ́. Ní Igbe 2020 nìkan, àwọn aṣàmúlò wa ní Nàìjíríà d'ókoòwò Bitcoin tí iye rẹ̀ tó 15M USD, èyí tí ó sọ Nàìjíríà di asíwájú tó f'ojúhàn láàrin gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tán wà ní Sub-Sahara ní Africa. Get in on the action! Create an account, grab your free Bitcoin wallet, and choose from thousands of available offers on your desktop, iOS or Andrọidi device.

Àwọn ìnájà tí wọ́n lékè fún Naira Naijiria ní Nàìjíríà

Olùtàjà Sanwó pẹ̀lú Tí ó kéré jù

láti san

láti san

Lórí dọ́là

BitcoinPrincess01 +967
Ti ríi wákati 1 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì All NIGERIA BANKS
$7,350.00 NGN $$0.98
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
Marryscott +49
Orí Ayélujára
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì UBA GTB ZENITH KUDA OPAY
$10,000.00 NGN $$0.91
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí ìdúnadúra òwò tí o darí
AdeptRicefish331 +10
Ti ríi ìsẹjú 3 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì ALL NIGERIAN BANKS
$8,000.00 NGN $$0.86
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
Samisco +1511
Ti ríi wákati 1 kọjá
Owó Chipper Chipper Cash Fast pay
$12,000.00 NGN $$0.86
àwọn ìsanwó orí ayélujára kò sí àwọn ẹnìkẹta kò sí ìdúnadúra
Lastec123 +2824
Ti ríi wákati 10 kọjá
Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì Wema Zenith
$10,000.00 NGN $$0.87
BOLA_RAHMAN +935
Orí Ayélujára
Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì TRUSTED Fast Release
$7,350.00 NGN $$0.89
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta
BOLA_RAHMAN +935
Orí Ayélujára
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì TRUSTED Fast Release
$7,350.00 NGN $$0.89
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
BOLA_RAHMAN +935
Orí Ayélujára
Owó Chipper TRUSTED Fast Release
$7,350.00 NGN $$0.89
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta
Dove__ +62
Ti ríi wákati 7 kọjá
Owó Chipper Fast reply and release
$10,000.00 NGN $$0.89
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Troouphy +35
Ti ríi wákati 16 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì UBA
$8,800.00 NGN $$0.90
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
soemboeloep +4
Ti ríi wákati 21 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì UNITED BANK FOR AFRICA
$10,000.00 NGN $$0.91
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
Btc_Plug247 +193
Ti ríi ìsẹjú 6 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì All NIGERIAN BANKS
$8,000.00 NGN $$0.86
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
FelixCoin +11
Ti ríi wákati 3 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì KUDA Microfinace Bank
$10,000.00 NGN $$0.91
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
LucidGrebe897 +39
Ti ríi wákati 17 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Asunmo Mathew mayowa
$10,000.00 NGN $$0.91
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
FastPike902 +31
Ti ríi ìsẹjú 58 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì First City Monument Bank
$7,350.00 NGN $$0.92
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
Xoxowhite +70
Ti ríi wákati 10 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Kuda bank
$7,350.00 NGN $$0.93
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
HurlyfreshCrypto +26
Ti ríi ìsẹjú 55 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì NO THIRD PARTY
$20,500.00 NGN $$0.93
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
WiseIbisbill460 +31
Ti ríi wákati 5 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Oladimeji
$8,800.00 NGN $$0.94
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
Rhylocash +49
Ti ríi wákati 14 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì All Banks
$8,800.00 NGN $$0.94
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
Ajhikeade +1245
Ti ríi wákati 5 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì All bank
$20,000.00 NGN $$0.94
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí

Àwọn ìlànà ìsanwó tí wọ́n lékè ní Nàìjíríà

Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Owó Alágbèéká MTN

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Owó Alágbèéká MTN lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Owó Alágbèéká MTN

Owó Chipper

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Owó Chipper lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Owó Chipper

Perfect Money

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Perfect Money lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Perfect Money

Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì

Káàdì Ẹ̀bùn Amazon

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.

Ṣé mo lè ta Bitcoin lórí Paxful?

Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn èèyàn mìíràn ní Nàìjíríà láti rí Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó tó 60% lórí títa ẹyọ kọ̀ọ̀kan. Bẹ̀rẹ̀ títa pẹ̀lú àkántì báǹkì abẹ́lé rẹ báyìí, wo ìtọ́nisọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful yóò ní 1000's olùrajà Bitcoin láti Nàìjíríà ní ojoojúmọ́.

Ṣẹda àkántì ki o bẹ̀rẹ̀ títà

Owó Àìlágùnjìnàfún

Ṣé o ma ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó fẹ́ ra Bitcoin ní Nàìjíríà? Pẹlú Kíọ̀sì Bitcoin àti ètò Ìbánipolówó rẹ ìwọ yóò gba 2% lórí òwò kọ̀ọ̀kan títí láyé nípa pínpín ìtọ́kasí. Bẹ̀rẹ̀ Báyì.