Ta Bitcoin lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ní Ghana

Tí o bá ń wá ààyè tó ní ààbò láti pààrọ̀ owó Cedi ti Ghana (GHS) rẹ sí BTC, ibi tó tọ̀nà ni ìwọ́ wá. Gẹ́gẹ́ bíi ọ̀kan lára àwọn ibi ìtajà Bitcoin ẹnìkan-sí-ẹnìkejì tán ṣíwájú ní àgbáyé, Paxful jẹ́ kí ìwọ́ ra BTC lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ kí ìwọ́ sì lòó bí ó ṣe wù ẹ́—bóyá ìdókoowò tàbí fífi owó ránṣẹ́ lóri ayélujára tàbí sísanwó ní ìgbàkígbà, ibikíbi. Ìwọ kò nílò láti kojú àlékún ìdíyelé tán wá pẹ̀lú àwọn ìsanwó gbati àwọn ilé ìfowópamọ́ ìbílẹ̀.

O lè ra BTC ní ọ̀nà tìrẹ pẹ̀lú ọgọọgọ́rún àwọn àṣàyàn ìsanwó tán wà lórí ìkànnì wa. Àti pẹ̀lú ètò ààbò tó gbópọn tó wà nílẹ̀, ìwọ́ lè fi ọkàn ara rẹ balẹ̀ nígbàtí ìwọ́ mọ̀ wípé ìwọ́ ń gba àwọn òwò tán ní èrè lọ́dọ̀ àwọn olùtajà tán ṣeé fọkàntán jù. Wá ǹkan tó bá ìwọ lára mu jù kí ìwọ́ sì wọ inú rẹ̀.

Apá tó dára jù ní wípé ó rọrùn yanilẹ́nu láti bẹ̀rẹ̀ —ṣẹ̀dá àkántì, gba wálẹ́ẹ́tì Bitcoin ọ̀fẹ́ rẹ, kí ìwọ́ sì dókoòwò lọ!

Àwọn ìnájà tí wọ́n lékè fún Ghanaian Cedi ní Ghana

Olùtàjà Sanwó pẹ̀lú Tí ó kéré jù

láti san

láti san

Lórí dọ́là

Jaxpot04 +1329
Ti ríi ìsẹjú 1 kọjá
Owó Alágbèéká MTN Withdrawal only E levy
100.00 GHS $1.00
kò sí àwọn ẹnìkẹta
Babceee +133
Ti ríi wákati 2 kọjá
Ìsanwó ojúkojú Vodafone Trusted
81.00 GHS $0.83
kò sí àwọn ẹnìkẹta kò sí ìdúnadúra
SnapWryneck490 +29
Ti ríi ìsẹjú 34 kọjá
PayPal Instant release
81.00 GHS $0.85
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí ìdúnadúra àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Saga123 +10
Orí Ayélujára
Owó Alágbèéká MTN Fast release
81.00 GHS $0.85
kò sí ìdúnadúra
Ghazzy +2439
Orí Ayélujára
Ìsanwó ojúkojú Vodafone Instant release
100.00 GHS $0.83
kò sí ìdúnadúra
Ghazzy +2439
Orí Ayélujára
Owó Alágbèéká MTN Instant release
100.00 GHS $0.83
kò sí ìdúnadúra
Ghazzy +2439
Orí Ayélujára
Momo Fast release
100.00 GHS $0.83
kò sí ìdúnadúra
Nasara69 +1851
Ti ríi ìsẹjú 1 kọjá
Owó Alágbèéká MTN Simple trader
1,000.00 GHS $0.83
kò sí ìdúnadúra
Nasara69 +1851
Ti ríi ìsẹjú 1 kọjá
Ìsanwó ojúkojú Vodafone SPEED OF LIGHT PAYMENT
1,000.00 GHS $0.83
kò sí ìdúnadúra
POINT_CRYPTO +89
Ti ríi wákati 11 kọjá
Owó Alágbèéká MTN TRUSTED
81.00 GHS $0.83
Babceee +133
Ti ríi wákati 2 kọjá
Owó Alágbèéká MTN All networks
81.00 GHS $0.83
kò sí àwọn ẹnìkẹta
CoinNet1 +1654
Ti ríi ìsẹjú 9 kọjá
Momo Paxful trusted trader
81.00 GHS $0.85
kò sí àwọn ẹnìkẹta
Taashiosking506 +125
Ti ríi wákati 2 kọjá
Owó Alágbèéká MTN
81.00 GHS $0.83
Taashiosking506 +125
Ti ríi wákati 2 kọjá
Ìsanwó ojúkojú Vodafone
81.00 GHS $0.83
Mooisammy +367
Ti ríi wákati 10 kọjá
PayPal Instant release
1,000.00 GHS $0.83
kò sí àwọn ẹnìkẹta àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Generalmwalimu +43
Ti ríi ìsẹjú 39 kọjá
PayPal Honest trading
90.00 GHS $0.83
kò nílò ìjẹ́rìísí kò sí ìdúnadúra àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Ramzzy +1312
Ti ríi ìsẹjú 15 kọjá
Owó Alágbèéká MTN Fair trader
81.00 GHS $0.83
àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Ckay30 +26
Ti ríi wákati 1 kọjá
Owó Airtel Fast
81.00 GHS $0.82
kò nílò ìjẹ́rìísí
Fuseinishagbaa +94
Ti ríi ìsẹjú 11 kọjá
Momo
81.00 GHS $0.81
Scrilla96 +346
Ti ríi wákati 9 kọjá
Momo Serious Business only
81.00 GHS $0.80

Àwọn ìlànà ìsanwó tí wọ́n lékè ní Ghana

Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Owó Alágbèéká MTN

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Owó Alágbèéká MTN lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Owó Alágbèéká MTN

Owó Airtel

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Owó Airtel lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Owó Airtel

PayPal

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú PayPal lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú PayPal

Ìsanwó ojúkojú Vodafone

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìsanwó ojúkojú Vodafone lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìsanwó ojúkojú Vodafone

Momo

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Momo lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Momo

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.

Ṣé mo lè ta Bitcoin lórí Paxful?

Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn èèyàn mìíràn ní Ghana láti rí Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó tó 60% lórí títa ẹyọ kọ̀ọ̀kan. Bẹ̀rẹ̀ títa pẹ̀lú àkántì báǹkì abẹ́lé rẹ báyìí, wo ìtọ́nisọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful yóò ní 1000's olùrajà Bitcoin láti Ghana ní ojoojúmọ́.

Ṣẹda àkántì ki o bẹ̀rẹ̀ títà

Owó Àìlágùnjìnàfún

Ṣé o ma ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó fẹ́ ra Bitcoin ní Ghana? Pẹlú Kíọ̀sì Bitcoin àti ètò Ìbánipolówó rẹ ìwọ yóò gba 2% lórí òwò kọ̀ọ̀kan títí láyé nípa pínpín ìtọ́kasí. Bẹ̀rẹ̀ Báyì.