Ta Bitcoin lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ní Brazil

Paxful, ibi ìtajà Bitcoin tó ń ṣíwájú ní àgbáyé tó ń lo agbára àwọn ènìyàn, wà fún ìlò rẹ—ṣetán láti bá ìwọ pààrọ̀ owó Real ti Brasil (BRL) rẹ sí BTC. Àwùjọ Paxful ti Brasil jẹ́ ọ̀kan lára èyí tó ń yára gbòòrò ní Latin America, tó d'ókoòwò BTC tí iye rẹ̀ tó 500,000 USD ní oṣù tó lọ nìkan. Jẹ́ ọ̀kan lára rẹ̀ lónìí nípasẹ̀ ṣíṣẹ̀dá àkántì, gbígba wálẹ́ẹ́tì Bitcoin ọ̀fẹ́ rẹ, àti mímú lára àwọn ọ̀nà ìsanwó fún BTC rẹ tán lé ní 300.

Lo ẹ̀rọ ààbò tó lékenkà wa láti fi ọwọ́ rẹ ba BTC àkọ́kọ́ rẹ ní ọ̀nà ààbò. Pẹ̀lú ìfàṣẹsí onígbẹ̀èsẹ̀-méjì (2FA) àti ẹgbẹ́ àtìlẹ́yìn oníbàárà tó wà fún 24/7, àwá ti ṣẹ̀dá àyíká ìdókoowò tó dára jù fún ọ.

Mú lára ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn ìnájà láti ọ̀dọ̀ àwọn olùtajà wa tán ṣé fọkàntán kí ìwọ́ sì ṣ'àkóso àwọn owó rẹ lórí ẹ̀rọ kọ̀mpútà desktop tàbí lórí-ìrìn nípasẹ̀ gbígba àwọn áápù alágbèéká Andrọidi tàbí iOS!

Àwọn ìnájà tí wọ́n lékè fún Brazilian Real ní Brazil

Olùtàjà Sanwó pẹ̀lú Tí ó kéré jù

láti san

láti san

Lórí dọ́là

WanbBTC +1437
Ti ríi ìsẹjú 40 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Todos bancos ou via PIX
350.00 BRL $0.97
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó ó nílò ìgbàniwọlé kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
OpenMoney +46
Ti ríi wákati 17 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Nubank24horas
20.00 BRL $0.97
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
tomazda +407
Ti ríi wákati 10 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì PIX TED QUALQUER BANCO
200.00 BRL $0.80
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò nílò ìjẹ́rìísí òwò tí o darí
ValleTrading +31
Ti ríi wákati 10 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì PIX TED VARIOS BANCOS
200.00 BRL $0.83
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò nílò ìjẹ́rìísí òwò tí o darí
JovialCombfish745 +82
Ti ríi wákati 3 kọjá
PayPal Instant realese
35.00 BRL $0.83
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí ìdúnadúra àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Sergiobortoline +259
Ti ríi wákati 8 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Pix 24HS BTC agora
100.00 BRL $0.83
kò sí àwọn ẹnìkẹta
Rashimillo +115
Ti ríi wákati 17 kọjá
PayPal Instant release
445.00 BRL $0.85
kò sí ìdúnadúra àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
waraujo +363
Ti ríi wákati 10 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì PIX TED MUITOS BANCOS
300.00 BRL $0.85
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò nílò ìjẹ́rìísí òwò tí o darí
Nathigil +29
Ti ríi wákati 13 kọjá
Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì NUBANKBRADESCOSANTANDER
100.00 BRL $0.87
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó kò nílò ìjẹ́rìísí
carnovore1130 +0
Ti ríi wákati 3 kọjá
PayPal instant release
17.00 BRL $0.88
kò sí ìdúnadúra àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Vspian +676
Ti ríi wákati 6 kọjá
Mercado Pago ZROBBNEXTORIBRACEF
155.00 BRL $0.93
Vspian +676
Ti ríi wákati 6 kọjá
Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì ZROBBNEXTORIBRACEF
455.00 BRL $0.95
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó
Vspian +676
Ti ríi wákati 6 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì PIXBBINTERORIBRACEF
555.00 BRL $0.96
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
Ruboao22 +75
Ti ríi ìsẹjú 10 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì pagamentos de terceiros
100.00 BRL $0.74
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó owó-àgbàsọ́wọ́ nìkan òwò tí o darí
DeboraMtl +1354
Ti ríi ìsẹjú 2 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì PIXBBCEFBRADSANTINTE
300.00 BRL $0.95
kò nílò ìjẹ́rìísí kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
Ruboao22 +75
Ti ríi ìsẹjú 10 kọjá
Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì qualquer banco
100.00 BRL $0.87
owó-àgbàsọ́wọ́ nìkan Ìsanwó ojútáyé pẹ̀lú ẹ̀rí ìsanwó
LoracBTC +3
Ti ríi ìsẹjú 2 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì PIX TED OU BRADESCO
50.00 BRL $0.94
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
JoyfulJackal171 +172
Orí Ayélujára
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì I ACCEPT THIRD by PIX
20.00 BRL $0.60
kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ìsanwó orí ayélujára
Tisdale +146
Orí Ayélujára
Skrill Fast and reliable trader
250.67 BRL $0.77
àwọn ìsanwó orí ayélujára
Reborn66 +375
Orí Ayélujára
Skrill Fast and reliable
400.00 BRL $0.77
àwọn ìsanwó orí ayélujára

Àwọn ìlànà ìsanwó tí wọ́n lékè ní Brazil

Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Skrill

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Skrill lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Skrill

PayPal

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú PayPal lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú PayPal

Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì

Mercado Pago

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Mercado Pago lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Mercado Pago

Owó-àtẹ́wógbà lojúkojú

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Owó-àtẹ́wógbà lojúkojú lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Owó-àtẹ́wógbà lojúkojú

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.

Ṣé mo lè ta Bitcoin lórí Paxful?

Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn èèyàn mìíràn ní Brazil láti rí Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó tó 60% lórí títa ẹyọ kọ̀ọ̀kan. Bẹ̀rẹ̀ títa pẹ̀lú àkántì báǹkì abẹ́lé rẹ báyìí, wo ìtọ́nisọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful yóò ní 1000's olùrajà Bitcoin láti Brazil ní ojoojúmọ́.

Ṣẹda àkántì ki o bẹ̀rẹ̀ títà

Owó Àìlágùnjìnàfún

Ṣé o ma ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó fẹ́ ra Bitcoin ní Brazil? Pẹlú Kíọ̀sì Bitcoin àti ètò Ìbánipolówó rẹ ìwọ yóò gba 2% lórí òwò kọ̀ọ̀kan títí láyé nípa pínpín ìtọ́kasí. Bẹ̀rẹ̀ Báyì.