Ta Bitcoin lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ní Bolivia

Ọ̀kan lára àwon ibi ìtajà Bitcoin enìkan-sí-ẹnìkejì tó ní ìṣọ́ jù ní àgbáyé ti wà ní Bolivia! Yára ṣe pàsípààrọ̀ Boliviano (BOB) rẹ sí BTC nípasẹ̀ lílo àwọn àṣàyàn ìsanwó tán lé ní 300 tán wà ní orí ìkànnì náà. Àwọn àṣàyàn rẹ pẹ̀lú PayU, Mercado Pago, Western Union, Ìfiránṣẹ́ gbati orílẹ̀-èdè kan sí òmííràn (SWIFT), Skrill, PayPal, àwọn káàdì ẹ̀bùn, ìfiránṣẹ́ gbati bánkì, àti ọ̀pọ̀ mííràn.

O lè ra Bitcoin lọ́wọ́ ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn oníṣòwò nínú àti ní ìta àwọn ààlà Bolivia. Láti mú ìrírí ìdókoowò rẹ wúlò kí ó sì wà ní ìṣọ́, Paxful ń dáàbò bo owó rẹ pẹ̀lú ìfàṣẹsí onígbẹ̀èsẹ̀-méjì (2FA), ààbò lórí ìkànni rẹ̀, tó sì bẹ̀rẹ̀ ìjẹríísí àkántì lọ́wọ́ gbogbo olùtajà rẹ̀.

Bẹ̀rẹ̀ ìrìnàjò Bitcoin rẹ nípasẹ̀ ṣíṣẹ̀dá àkántì Paxful rẹ tí ìwọ kò báì tíì ṣeé. Ìwọ yóò gba wálẹ́ẹ́tì Bitcoin ọ̀fẹ́ kété tí ìwọ́ bá ti forúkọsílẹ̀ láti tẹ̀síwájú. Dídarapọ̀ mọ́ àwùjọ kírípítò tó ń bọ̀ ní àgbáyé kò rọrùn tó báyìí rí. Ìdókoowò ayọ̀!

Àwọn ìnájà tí wọ́n lékè fún Bolivian Boliviano ní Bolivia

Olùtàjà Sanwó pẹ̀lú Tí ó kéré jù

láti san

láti san

Lórí dọ́là

JACO100MEDO +141
Ti ríi ìsẹjú 4 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Mercantil Santa Cruz
500.00 BOB $0.83
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
Generalmwalimu +42
Ti ríi ìsẹjú 48 kọjá
PayPal Genuine trade partner
103.00 BOB $0.83
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
prettyqueen118 +42
Orí Ayélujára
PayPal goods and service
344.00 BOB $0.67
prettyqueen118 +42
Orí Ayélujára
Káàdì Visa Dẹ́bítì/Visa Kírẹ́dítì released right away
342.00 BOB $0.67

Àwọn ìlànà ìsanwó tí wọ́n lékè ní Bolivia

Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

PayPal

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú PayPal lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú PayPal

Skrill

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Skrill lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Skrill

Wise (TransferWise)

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Wise (TransferWise) lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Wise (TransferWise)

Káàdì Ẹ̀bùn Amazon

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon

OneVanilla VISA/Káàdì Ẹ̀bùn MasterCard

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú OneVanilla VISA/Káàdì Ẹ̀bùn MasterCard lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú OneVanilla VISA/Káàdì Ẹ̀bùn MasterCard

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.

Ṣé mo lè ta Bitcoin lórí Paxful?

Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn èèyàn mìíràn ní Bolivia láti rí Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó tó 60% lórí títa ẹyọ kọ̀ọ̀kan. Bẹ̀rẹ̀ títa pẹ̀lú àkántì báǹkì abẹ́lé rẹ báyìí, wo ìtọ́nisọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful yóò ní 1000's olùrajà Bitcoin láti Bolivia ní ojoojúmọ́.

Ṣẹda àkántì ki o bẹ̀rẹ̀ títà

Owó Àìlágùnjìnàfún

Ṣé o ma ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó fẹ́ ra Bitcoin ní Bolivia? Pẹlú Kíọ̀sì Bitcoin àti ètò Ìbánipolówó rẹ ìwọ yóò gba 2% lórí òwò kọ̀ọ̀kan títí láyé nípa pínpín ìtọ́kasí. Bẹ̀rẹ̀ Báyì.