Ta Bitcoin lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ní Belgium

Ríra Bitcoin ní Belgium ti rọrùn ọpẹ́ lọ́wọ́ Paxful, ibi ìtajà Bitcoin tó ń ṣíwájú ní àgbáyé tó ń lo agbára àwọn ènìyàn. Àwọn olùtajà wa ni a sọ́ra ṣ'àtúnyẹ̀wọ̀ wọn gbati ẹ̀rọ ìjẹríísí KYC tó rọrùn, kí ìwọ́ sì d'ókoòwò Bitcoin lábẹ ibi ìtajà P2P tí ìjọba US ń f'òfinsí. Èyí túnmọ̀ sí wípé ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn olùtajà tán ṣeé fọkàntán ti ṣetán láti ta BTC fún ìwọ pẹ̀lú àwọn ọ̀nà ìsanwó tán lé ní 300 àti àwọn owósan olùrajà ọ̀fẹ́.

Lórí ìyẹn, ẹ̀rọ ìlọ́lùpọ̀ wa ní àtìlẹ́yìn àwọn ìlànà ààbò tán gbópọn, èyí tó pẹ̀lúu Ìfàṣẹsí onígbẹ̀èsẹ̀-méjì (2FA) àti ẹgbẹ́ àtìlẹ́yìn oníbàárà tó wà ní 24/7. Papọ̀, wọ́n ṣẹ̀dá àyíká ìdókoowò tó ní ààbò dọ́ba.

Lọ́gán tí ìwọ́ bá ti ṣẹ̀dá àkántì, ìwọ yóò gba wálẹ́ẹ́tì Bitcoin ọ̀fẹ́—tó túnmọ̀ sí wípé bíbẹ̀rẹ̀ rọrùn ó sì lọ tààrà. Gbìyànjú rẹ̀ nísìín!

Àwọn ìnájà tí wọ́n lékè fún Euro ní Belgium

Olùtàjà Sanwó pẹ̀lú Tí ó kéré jù

láti san

láti san

Lórí dọ́là

UniqueTapir834 +439
Ti ríi ìsẹjú 22 kọjá
PayPal Instant payment
50.00 EUR $0.85
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Ryankips +420
Orí Ayélujára
PayPal INSTANT RELEASE
60.00 EUR $0.83
kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ìsanwó orí ayélujára àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
RYAN36 +38
Ti ríi wákati 1 kọjá
PayPal Friends and family
10.00 EUR $0.83
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
TonnieV +37
Ti ríi wákati 3 kọjá
PayPal Instant release
15.00 EUR $0.83
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí ìdúnadúra àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
JayOmedo +126
Ti ríi wákati 8 kọjá
PayPal instant
11.00 EUR $0.83
àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
BATIEMHONEST +23
Ti ríi wákati 1 kọjá
PayPal Instant release
40.00 EUR $0.83
àwọn ìsanwó orí ayélujára kò sí ìdúnadúra àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Charonyi +12
Ti ríi ìsẹjú 33 kọjá
PayPal
50.00 EUR $0.83
Grandstart +21
Ti ríi wákati 3 kọjá
PayPal Goods and services
50.00 EUR $0.83
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí ìdúnadúra àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Londonking +21
Ti ríi wákati 1 kọjá
Revolut Any UK and European
100.00 EUR $0.83
kò nílò ìjẹ́rìísí
McBETT +613
Ti ríi wákati 1 kọjá
PayPal Instant release
15.00 EUR $0.83
àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
EdenPsalmiste20 +532
Ti ríi ìsẹjú 38 kọjá
PayPal INSTANT RELEASE
45.00 EUR $0.83
kò nílò ìjẹ́rìísí
egancoin +2383
Ti ríi ìsẹjú 1 kọjá
PayPal INSTANT PAYMENT
30.00 EUR $0.83
paypal tí ó ti wà ní ìjẹ́rìísí nìkan
Riobajaymaks +225
Ti ríi wákati 4 kọjá
PayPal Instant release
9.00 EUR $0.83
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
GachugiRyan +991
Ti ríi wákati 2 kọjá
PayPal Quick and Easy trades
9.00 EUR $0.83
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó
Tabby_Crypto +96
Orí Ayélujára
PayPal Instant release
50.00 EUR $0.83
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
GoodlifeBTC +119
Orí Ayélujára
PayPal Instant release
20.00 EUR $0.83
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
GentleCod +18
Ti ríi ìsẹjú 3 kọjá
PayPal Instant
100.00 EUR $0.83
kò sí ìdúnadúra
CEXDirect +202
Ti ríi ìsẹjú 1 kọjá
ÈYÍKÉYÌ Káàdì kírẹ́dítì/Dẹ́bítì AUTOMATED PROCESS 200 EUR
200 EUR $0.83
àwọn ìsanwó orí ayélujára Ìsanwó ojútáyé
AlmightyKaii +1207
Ti ríi ìsẹjú 5 kọjá
SEPA SEPA ALL EUROPEAN BANKS
50.00 EUR $0.82
ó nílò àwòrán ìdánimọ̀ àwọn ìsanwó orí ayélujára kò sí àwọn ẹnìkẹta
AlmightyKaii +1207
Ti ríi ìsẹjú 5 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Bancontact or Mister Cash
50.00 EUR $0.82
ó nílò àwòrán ìdánimọ̀ àwọn ìsanwó orí ayélujára kò sí àwọn ẹnìkẹta

Àwọn ìlànà ìsanwó tí wọ́n lékè ní Belgium

Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

PayPal

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú PayPal lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú PayPal

ÈYÍKÉYÌ Káàdì kírẹ́dítì/Dẹ́bítì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú ÈYÍKÉYÌ Káàdì kírẹ́dítì/Dẹ́bítì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú ÈYÍKÉYÌ Káàdì kírẹ́dítì/Dẹ́bítì

Paysafecard

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Paysafecard lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Paysafecard

Revolut

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Revolut lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Revolut

SEPA

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú SEPA lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú SEPA

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.

Ṣé mo lè ta Bitcoin lórí Paxful?

Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn èèyàn mìíràn ní Belgium láti rí Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó tó 60% lórí títa ẹyọ kọ̀ọ̀kan. Bẹ̀rẹ̀ títa pẹ̀lú àkántì báǹkì abẹ́lé rẹ báyìí, wo ìtọ́nisọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful yóò ní 1000's olùrajà Bitcoin láti Belgium ní ojoojúmọ́.

Ṣẹda àkántì ki o bẹ̀rẹ̀ títà

Owó Àìlágùnjìnàfún

Ṣé o ma ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó fẹ́ ra Bitcoin ní Belgium? Pẹlú Kíọ̀sì Bitcoin àti ètò Ìbánipolówó rẹ ìwọ yóò gba 2% lórí òwò kọ̀ọ̀kan títí láyé nípa pínpín ìtọ́kasí. Bẹ̀rẹ̀ Báyì.