Ta Bitcoin lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ní Bahrain

Paxful ti wà ní Bahrain, ti ṣetán láti ran ìwọ lọ́wọ́ ní kíákíá àti ní ọ̀nà ààbò láti pààrọ̀ owó Dinar ti Bahrain (BHD) rẹ sí BTC.

Gẹ́gẹ́ bíi ọmọ ẹgbẹ́ Group-IB tó ṣeé fọkàntán àti alábàáṣiṣẹ́pọ̀ Chainalysis, a ní èròńgbà láti fún ìwọ ní àyíká ìdókoowò tó ní ààbò jù. Pẹ̀lú ẹ̀rọ ẹ́síkírò tó ní ìṣọ́ àti ìfàṣẹsí onígbẹ̀èsẹ̀-méjì, ìwọ́ lè dókoòwò ní ìrọ̀rùn, nígbàtí ìwọ́ mọ̀ wípé owó rẹ wà ní ààbò.

Kíni o n dúró dé? Pẹ̀lú ìjẹríísí òòjọ́, ìwọ́ lè bẹ̀rẹ̀ ìdókoowò pẹ̀lú ìwọ̀n tó ga nísìín! Bẹ̀rẹ̀ ìdókoowò nípasẹ̀ ṣíṣẹ̀dá àkántì, gbígba wálẹ́ẹ́tì Bitcoin ọ̀fẹ́ rẹ, àti wíwá ìnájà tó dára jù láti ọ̀dọ̀ ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn olùtajà wa tán ṣeé fọkàntán. A wà lórí ẹ̀rọ kọ̀mpútà, tàbí lóri Andrọidi rẹ tàbí ẹ̀rọ iOS!

Àwọn ìnájà tí wọ́n lékè fún Bahraini Dinar ní Bahrain

Olùtàjà Sanwó pẹ̀lú Tí ó kéré jù

láti san

láti san

Lórí dọ́là

Tililei +183
Orí Ayélujára
PayPal friends and families only
4.00 BHD $0.85
kò nílò ìjẹ́rìísí kò sí ìdúnadúra àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Yebay +632
Ti ríi wákati 1 kọjá
PayPal friends and family only
4.00 BHD $0.84
kò nílò ìjẹ́rìísí kò sí ìdúnadúra
princeroni64 +479
Orí Ayélujára
PayPal Instant Release
10.00 BHD $0.83
kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ìsanwó orí ayélujára
Skaikruvi +123
Orí Ayélujára
PayPal Released in Seconds
25.00 BHD $0.83
àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
ReadyWolffish29 +78
Ti ríi ìsẹjú 11 kọjá
PayPal Instant release
4.00 BHD $0.83
kò sí ìdúnadúra àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Hardfly_44 +365
Orí Ayélujára
PayPal INSTANT REPLY AND RELEASE
18.00 BHD $0.80
kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ìsanwó orí ayélujára
prettyqueen888888 +143
Ti ríi ìsẹjú 8 kọjá
PayPal release right away
11.00 BHD $0.62
KindlyMarlin815 +316
Ti ríi wákati 17 kọjá
PayPal friends and family
20.00 BHD $0.81
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí ìdúnadúra
Dimplus +236
Ti ríi ìsẹjú 7 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Owó RIA honest fast and sure
100.00 BHD $0.90
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó owó-àgbàsọ́wọ́ nìkan àwọn ìsanwó orí ayélujára
KsaBtc786_MRGroup +720
Ti ríi ìsẹjú 4 kọjá
Neteller SkrillNeteller Insta Rls
4.00 BHD $0.87
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó ojú iye tí ó tó 100 kò sí àwọn ẹnìkẹta
Altcoin88 +459
Orí Ayélujára
EzRemit FAST AND SECURE
15.00 BHD $0.86
àwọn ìsanwó orí ayélujára
Altcoin88 +459
Orí Ayélujára
Ìfowóránṣẹ́ Owó RIA SECURE FAST RELEASE
10.00 BHD $0.85
àwọn ìsanwó orí ayélujára
Hardfly_44 +365
Orí Ayélujára
Remitly INSTANT REPLY AND RELEASE
18.00 BHD $0.83
kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ìsanwó orí ayélujára
Hardfly_44 +365
Orí Ayélujára
Paysend.com INSTANT REPLY AND RELEASE
18.00 BHD $0.83
kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ìsanwó orí ayélujára
Fred2495 +347
Orí Ayélujára
Transfast Fast release
40.00 BHD $0.83
kò nílò ìjẹ́rìísí
KsaBtc786_MRGroup +720
Ti ríi ìsẹjú 4 kọjá
Western Union MoneyGramRiaRemitlyOFX
10.00 BHD $0.83
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó ojú iye tí ó tó 100 kò sí àwọn ẹnìkẹta
Hardfly_44 +365
Orí Ayélujára
Wise (TransferWise) INSTANT REPLY AND RELEASE
18.00 BHD $0.81
kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ìsanwó orí ayélujára
Fred2495 +347
Orí Ayélujára
Western Union QUICK EASY TO MY MPESA
10.00 BHD $0.81
ShahbazHussain786 +549
Ti ríi ìsẹjú 15 kọjá
Western Union deposit any exchange
4.00 BHD $0.79
kò sí àwọn ẹnìkẹta
Hardfly_44 +365
Orí Ayélujára
MoneyGram INSTANT REPLY AND RELEASE
18.00 BHD $0.77
kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ìsanwó orí ayélujára

Àwọn ìlànà ìsanwó tí wọ́n lékè ní Bahrain

Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

PayPal

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú PayPal lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú PayPal

ÈYÍKÉYÌ Káàdì kírẹ́dítì/Dẹ́bítì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú ÈYÍKÉYÌ Káàdì kírẹ́dítì/Dẹ́bítì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú ÈYÍKÉYÌ Káàdì kírẹ́dítì/Dẹ́bítì

Perfect Money

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Perfect Money lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Perfect Money

MoneyPak

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú MoneyPak lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú MoneyPak

Payeer

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Payeer lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Payeer

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.

Ṣé mo lè ta Bitcoin lórí Paxful?

Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn èèyàn mìíràn ní Bahrain láti rí Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó tó 60% lórí títa ẹyọ kọ̀ọ̀kan. Bẹ̀rẹ̀ títa pẹ̀lú àkántì báǹkì abẹ́lé rẹ báyìí, wo ìtọ́nisọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful yóò ní 1000's olùrajà Bitcoin láti Bahrain ní ojoojúmọ́.

Ṣẹda àkántì ki o bẹ̀rẹ̀ títà

Owó Àìlágùnjìnàfún

Ṣé o ma ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó fẹ́ ra Bitcoin ní Bahrain? Pẹlú Kíọ̀sì Bitcoin àti ètò Ìbánipolówó rẹ ìwọ yóò gba 2% lórí òwò kọ̀ọ̀kan títí láyé nípa pínpín ìtọ́kasí. Bẹ̀rẹ̀ Báyì.