Pawó kírípítò pẹ̀lú Paxful

Rà àti tà àwon kọ́rẹ́ńsì Onídíjítà ní ọnà tí ó rọrùn. Gba àkántì Paxful rẹ, bẹrẹ gbígba àwọn sísanwó, kí o sì ní owó.

Ju 350 àwọn ọ̀nà lọ láti ra ati ta Bitcoin

Yan ìlànà ìsanwó ti o fẹràn àti ṣòwò tààrà pẹlú àwọn ènìyàn mííràn gẹgẹ bí ìwọ!

Wo gbogbo àwọn ìnájà

Paxful ni ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́

Paxful jẹ gbajúmọ púpọ ní ààyè kọ́rẹ́ńsì-kírípítò àti pé o ti ní agbègbè tó gbòòrò ní ọpọlọpọ àwọn ìwé ìròyìn olókìkí. Ọkan nínú àwọn èròngbà wa ní láti kọ àwọn ilé-ìwé 100 ní Áfíríkà. Ṣàyẹwò fídíò tí ó wà ní ìsàlẹ láti ní ìmọ síwájú síi nípa ìpilẹṣẹ #builtwithbitcoin wa.

Di olùtajà Bitcoin lórí Paxful

Di olùtajà lórí Paxful kí o ró àwọn mílíọnù ní agbára òmìnira owó ní àgbáyé . Pèsè àwọn ìlànà ìsanwó lọpọlọpọ ti àwọn olùrajà fẹ, ìmúkúrò àwọn alágbàtà, àti pé a yóò ràn ọ lọwọ pẹlú gbogbo àwọn ohun èlò àti ìtọsọnà tí o nílò láti ṣàṣeyọrí.

12,000+

Àwọn ìnájà tí ó ṣéé gbẹ́kẹ̀lé

12,000+

Àwọn olùtajà ti oṣéé gbẹ́kẹ̀lé

6,000,000+

Àwọn oníbàárà aláyọ̀

Di olùtajà kan

Àwọn ẹ̀rí

Àìmọye mílíònù ní ó ti lo Paxful ní àṣeyọrí àti pé wọn ti ní ọpọlọpọ àwọn ohun tí o wuyì láti sọ nípa wa. Èyí ní ohun tí àwọn aṣàmúlò wa rò nípa Paxful, nínú àwọn ọ̀rọ̀ tí ara wọn.

Pẹ̀lú Paxful o lè

Gbe òmìnira ti owó rẹ ga sí pèpéle ti ó ga jùlọ pẹlú Paxful.

Ra Bitcoin lórí ayélujára

Ra Bitcoin lórí Paxful ní àkókò gidi. Ṣe òwò pẹlú àwọn aṣàmúlò mííràn lórí ayélujára nípa lílo ìtàkurọ̀sọ ojútáyé wa.

Ta Bitcoin

Ta Bitcoin rẹ ní òṣùwọn ti o yàn, kí o gba owó sísan ní ọkan nínú ọpọlọpọ àwọn ìlànà ìsanwó.

Ṣòwò pẹ̀lú ààbò ẹsíkírò

Bitcoin rẹ wà ní ààbò ẹsíkírò wa títí tí ìṣòwò yóò parí ni àṣeyọrí.

Ṣàgbékalẹ̀ ìgbayìsí rẹ

Ètò ìjábọ̀ aṣàmúlò wa ń jẹ kí o ṣe Ìdánimọ̀ àwọn ẹlẹgbẹ ìgbẹ́kẹ̀lé àti ìrírí láti ṣòwò pẹlú.

Gba wálẹ́ẹ̀tì ọ̀fẹ́ kan

Gba wálẹ́ẹ̀tì Bitcoin ọfẹ ti ìgbésí ayé ti BitGo ń ṣe àmójútó rẹ , olùṣàkóso aṣìwájú tí àwọn wálẹ́ẹ̀tì Bitcoin aláàbò.

Ní ọnà ìpawówọlé mííràn

Lo ànfàní ti Ètò ìbanipolówó wa láti ṣẹdá owó tí ò dá tó dúróṣinṣin.

Bẹ̀rẹ̀ ìdókòwò lórí Paxful

Forúkọsílẹ̀ lóní láti gba wálẹ́ẹ̀tì onídíjítà ọ̀fẹ́ rẹ. O lè bẹrẹ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ láti ra tàbí ta Bitcoin, láìsí wàhálà.

Ṣẹ̀dá àkántì