Ṣẹ̀dá àkántì rẹ

Forúkọsílẹ̀ nísinsìnyí ki o bá lè gba wálẹ́ẹ̀tì abánipolówó ọ̀fẹ́.

  • Tips:
  • Jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ìgbaniwọlé rẹ lágbára pẹ̀lú ó kéré jù ọ̀rọ̀ 8 àti àkójọpọ̀ àwọn lẹ́tà nlá àti kékeré, àwọn nọmba, àti àwọn àmì. Tí ó bá ṣe gùn sí ló sẹ dára jù sí. Àwọn ọ̀rọ̀ ìgbaniwọlé gúngùn máa n sòro fún àwọn olè láti ṣí.
  • Lo $ dípò S tàbí 1 dípò L, tàbí pẹ̀lu & tàbí % – ṣùgbọ́n ṣe àkíyèsí wípé $1ngle KÌÍ ṢE ọ̀rọ̀ ìgbaniwọlé gidi. Àwọn olè ọ̀rọ̀ ìgbaniwọlé wà lẹ́nu ẹ̀. Ṣùgbọ́n Mf$J1ravng (kúkúrú fún “Myfriend Sam Jones is really a very nice guy) jẹ́ ọ̀rọ̀ ìgbaniwọlé tó dára.
Nipa titẹ Ṣẹda àkántì o gbà fúnAwọn Ìfẹnukò Ìlò Paxful, Awọn Ìfẹnukò Ìlò Ètò ìbanipolówó wa àti , ìfitónílétí Onípamọ́ wa

Ṣe ìwádìí àwọn ìfilọ̀ ìnájà