Jọwọ dúró lákòkò tí à ń wá àwọn ìnájà tí ó dára jùlọ fún ọ.

Sell to

Get paid with

js.rate_per_crypto.usdc

Bíí ó ṣe Le Ta USD Coin lórí Paxful

Paxful jẹ kí ó rọrùn fún àwọn olùbẹ̀rẹ̀ àti àwọn ògbólógbò láti ṣe àṣeyọrí òmìnira òwò. Àti pé nítorí a jẹ ibi ìtajà ẹnìkan-sí-ẹnìkejì, o lè ta USD Coin (USDC) tààrà fún àwọn mílìọnù àwọn aṣàmúlò ni gbogbo àgbáyé láìsí ìwúlò fún àwọn ile-ifowopamọ tàbí àwọn ilé-iṣẹ!

Èyí ni ohun tí o nílò láti ṣe:

Ṣáájú kí o tó bẹrẹ títa USD Coin, o gbọdọ kọkọ ṣẹdá àti ṣàyẹwò akọọlẹ Paxful rẹ tàbí wọlé sí ọkan tí o wà tẹlẹ. Lọ́gán tí o bá ti wọlé, kàn tẹlé àwọn ìgbésẹ wọnyí:

  1. Ṣètò àwọn àdéhùn rẹ - Ṣe ìpinnu iye tí ó pọ jùlọ tí USD Coin tí o fẹ tà àti mú ìlànà ìsanwó tí o fẹ. O tún lè ṣètò kọ́rẹ́ńsì àyànfẹ rẹ àti agbègbè rẹ tí o bá fẹ.
  2. Wá àwọn ìnájà - Lọ́gán tí o ti ṣètò àwọn àdéhùn rẹ, tẹ Wa Awọn ìnájà láti wo àwọn ìnájà tí o yẹ láti yàn ninu èyí tí o wà.
  3. Àtúnyẹ̀wò àwọn ìnájà - Máṣe gbàgbé láti ṣàyẹwò gbogbo àwọn àlàyé pàtàkì ti olùrajà pẹlú ìpele ìjẹ́rìísí wọn, iye àwọn òwò tí o ṣàṣeyọrí, àtí àwọn ìjábọ̀ láti ọdọ àwọn aṣàmúlò mííràn, ṣáájú kí o tó tẹsíwájú.
  4. Start the trade - If you find a reputable buyer, click Sell. to review the terms and conditions set by the buyer. If you agree, enter the amount of %1s you’re willing to trade and click Sell Now. This then brings you to a live trade chat and temporarily transfers your %1s to our secure escrow.
  5. Parí iṣowo náà: Ní kété tí o bá gba owó sísan àti olùrajà ṣàṣeyọrí òpin ti ìṣòwò náà, o lè fi USD Coin silẹ láti ẹsíkírò sí wálẹ́ẹ̀tì wọn. Ìwọ yóò tún ní ànfàní láti ṣe ìgbàsílẹ ẹ̀rí ìsanwó tí gbogbogboo tí ó bá fẹ láti tọjú ìgbàsílẹ ti ìdúnàádúrà náà.
  6. Fi ìjábọ̀ sílẹ̀ - Máṣe gbàgbé láti sọ fún wa ìrírí rẹ pẹlú olùbádòwòpọ̀ rẹ lẹhìn ìdúnàádúrà aláṣeyọrí.

Ṣàyẹwò Ibi àmúsọgbọ́n wa láti ní ìmọ síwájú síí nípa bí a ṣe lè ta https://paxful.com/yo/list-crypto-buy-sell-ad lẹsẹkẹsẹ. O tún lè ṣẹdá ẹbùn tí o bá fẹ ṣètò àwọn àdéhùn tìrẹ tàbí àwọn ìtọ́nísọ́nà òwò. Máṣe ṣiyèméjì láti dé ọdọ ẹgbẹ àtìlẹyìn wa tí o bá ní ìbéèrè èyíkèyí. Ìdókòwò ìdùnnú!