Sell to
Get paid with
Price per Ethereum
Bí ó ṣe Le Ta Ethereum lórí Paxful
Paxful jẹ kí ó rọrùn fún àwọn olùbẹ̀rẹ̀ àti àwọn ògbólógbò láti ṣe àṣeyọrí òmìnira òwò. Àti pé nítorí a jẹ ibi ìtajà ẹnìkan-sí-ẹnìkejì, o lè ta Ethereum (ETH) tààrà fún àwọn mílìọnù àwọn aṣàmúlò ni gbogbo àgbáyé láìsí ìwúlò fún àwọn ile-ifowopamọ tàbí àwọn ilé-iṣẹ!
Èyí ni ohun tí o nílò láti ṣe:
Ṣáájú kí o tó bẹrẹ títa Ethereum, o gbọdọ kọkọ ṣẹdá àti ṣàyẹwò akọọlẹ Paxful rẹ tàbí wọlé sí ọkan tí o wà tẹlẹ. Lọ́gán tí o bá ti wọlé, kàn tẹlé àwọn ìgbésẹ wọnyí:
- Ṣètò àwọn àdéhùn rẹ - Ṣe ìpinnu iye tí ó pọ jùlọ tí ETH tí o fẹ tà àti mú ìlànà ìsanwó tí o fẹ. O tún lè ṣètò kọ́rẹ́ńsì àyànfẹ rẹ àti agbègbè rẹ tí o bá fẹ.
- Wá àwọn ìnájà - Lọ́gán tí o ti ṣètò àwọn àdéhùn rẹ, tẹ Wa Awọn ìnájà láti wo àwọn ìnájà tí o yẹ láti yàn ninu èyí tí o wà.
- Àtúnyẹ̀wò àwọn ìnájà - Máṣe gbàgbé láti ṣàyẹwò gbogbo àwọn àlàyé pàtàkì ti olùrajà pẹlú ìpele ìjẹ́rìísí wọn, iye àwọn òwò tí o ṣàṣeyọrí, àtí àwọn ìjábọ̀ láti ọdọ àwọn aṣàmúlò mííràn, ṣáájú kí o tó tẹsíwájú.
- Bẹ̀rẹ̀ òwò náà - Tí o bá rí olùrajà olokiki, tẹ Ta láti ṣe àtúnyẹwò àwọn àdehùn àti kání ti olùrajà náà ṣètò. Tí o bá gbà, tẹ iye ETH tí o ṣetán láti ṣòwò kí o tẹ Tà Báyì . Èyí lẹhinna mú ọ wá sí ìtàkúrọ̀sọ òwò ojútáyé àti ìfiránṣẹ́ àwọn ETH rẹ fún ìgbà díẹ sí ààbò ẹsíkírò wa.
- Parí iṣowo náà: Ní kété tí o bá gba owó sísan àti olùrajà ṣàṣeyọrí òpin ti ìṣòwò náà, o lè fi ETH silẹ láti ẹsíkírò sí wálẹ́ẹ̀tì wọn. Ìwọ yóò tún ní ànfàní láti ṣe ìgbàsílẹ ẹ̀rí ìsanwó tí gbogbogboo tí ó bá fẹ láti tọjú ìgbàsílẹ ti ìdúnàádúrà náà.
- Fi ìjábọ̀ sílẹ̀ - Máṣe gbàgbé láti sọ fún wa ìrírí rẹ pẹlú olùbádòwòpọ̀ rẹ lẹhìn ìdúnàádúrà aláṣeyọrí.
Ṣàyẹwò Ibi àmúsọgbọ́n wa láti ní ìmọ síwájú síí nípa bí a ṣe lè ta ETH lẹsẹkẹsẹ. O tún lè ṣẹdá ẹbùn tí o bá fẹ ṣètò àwọn àdéhùn tìrẹ tàbí àwọn ìtọ́nísọ́nà òwò. Máṣe ṣiyèméjì láti dé ọdọ ẹgbẹ àtìlẹyìn wa tí o bá ní ìbéèrè èyíkèyí. Ìdókòwò ìdùnnú!