Jọwọ dúró lákòkò tí à ń wá àwọn ìnájà tí ó dára jùlọ fún ọ.

Sell to

Get paid with

Price per Bitcoin

Bí ó ṣe Le ta Bitcoin lórí Paxful

O rọrùn báyì láti ta Bitcoin bí olùtajà Paxful. O ní òmìnira láti ṣètò àwọn òṣùwọn tìrẹ, àti pẹlú ìgbádùn ti àwọn àṣàyàn sísanwó tí ó ju 300 lọ láti sanwó fún Bitcoin tí o ta. Bí Paxful ṣe jẹ ibi ìtajà ẹnìkan-sí-ẹnìkejì, o lè ta Bitcoin rẹ tààrà fún àwọn aṣàmúlò ti ó ju mílíọnù 3 lọ ní káríayé. Ìkànnì wa jẹ kí o rọrùn púpọ jùlọ fún àwọn olùbẹ̀rẹ̀ àti àwọn ògbólógbò bákanná láti jèrè.

Láti ta Bitcoin lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ṣẹdá àkántì Paxful kantàbí wọlé sí ọkan tí o wà tẹlẹ . Lọgán tí o wọlé, kàn tẹlé àwọn ìgbésẹ wọnyí:

  1. Ṣètò àwọn ìbéèrè rẹ - Yan ìlànà ìsanwó ti o fẹ jùlọ àti iye Bitcoin tí ó pọ jùlọ tí o fẹ tà. O tún lè tọka agbègbè rẹ àti kọ́rẹ́ńsì ti o fẹ jùlọ. Wá Àwọn ìnájà. Ìwọ yóò wo àtòkọ ti àwọn ìnájà tí ó yẹ láti yàn.
  2. Àtúnyẹ̀wò àwọn ìnájà - Ṣáájú kí o tó yan ìnájà kan, ríí dájú láti ṣayẹwo gbogbo àlàyé pàtàkì nípa olùrajà, pẹlú ṣùgbọn kíí ṣe òpin sí orúkọ wọn, ìgbayìsí, ìpele ìjẹ́rìísí, àti òṣùwọn fún Bitcoin. Lọ́gán tí o bá ti ríí ìnájà tí ó yẹ, tẹ Ta .Kì yóò ṣíí òwò síbẹsíbẹ, ṣùgbọn yóò ṣe ìtọ́sọ́nà fún ọ nípasẹ àwọn àdéhùn ìfilọ̀ ìnájà àti Kání ti olùrajà pèsè.
  3. Start the trade – If you are satisfied with the buyer’s terms, enter the amount you’re willing to trade for and click Sell Now. This will open a live trade chat and move your Bitcoin to our secured escrow. Read the instructions provided carefully, and follow them. Once your buyer completes their end of the trade and you receive the payment, you can release the Bitcoin. You can download a public receipt after the trade.
  4. Fi ìjábọ̀ sílẹ̀ - Lẹhìn tí o ti ní àṣeyọrí títa Bitcoin rẹ , máṣe gbàgbé láti fún olùbádòwòpọ̀ rẹ ni ìjábọ̀. Èyí ṣe pàtàkì fún ìkànnì wa bí ó ṣe ńṣe ìrànlọwọ láti ṣàgbékalẹ̀ ìgbayìsí aṣàmúlò.

Fún àlàyé síwájú síí, wo ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ fídíò àtúngbéyẹ̀wò ẹ̀kọ́ wa lórí bí o ti lè ta Bitcoin ní kíákíá. O tún lè ṣẹdá ìnájà kan láti ta Bitcoin nípa títẹlé ìtọ́sọ́nà wa sí ṣíṣẹdá ìnájà lórí Paxful.

Ibi ìtajà ẹnìkan-sí-ẹnìkejì Paxful rọrùn láti lò, ní ààbò nípasẹ ẹsíkírò, àti wíwọlé sí gbogbo àgbáyé. Bẹ̀rẹ̀ òwò lónì!