Sell to
Get paid with
Price per Bitcoin
Bí ó ṣe Le ta Bitcoin lórí Paxful
O rọrùn báyì láti ta Bitcoin bí olùtajà Paxful. O ní òmìnira láti ṣètò àwọn òṣùwọn tìrẹ, àti pẹlú ìgbádùn ti àwọn àṣàyàn sísanwó tí ó ju 300 lọ láti sanwó fún Bitcoin tí o ta. Bí Paxful ṣe jẹ ibi ìtajà ẹnìkan-sí-ẹnìkejì, o lè ta Bitcoin rẹ tààrà fún àwọn aṣàmúlò ti ó ju mílíọnù 3 lọ ní káríayé. Ìkànnì wa jẹ kí o rọrùn púpọ jùlọ fún àwọn olùbẹ̀rẹ̀ àti àwọn ògbólógbò bákanná láti jèrè.
Láti ta Bitcoin lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ṣẹdá àkántì Paxful kantàbí wọlé sí ọkan tí o wà tẹlẹ . Lọgán tí o wọlé, kàn tẹlé àwọn ìgbésẹ wọnyí:
- Ṣètò àwọn ìbéèrè rẹ - Yan ìlànà ìsanwó ti o fẹ jùlọ àti iye Bitcoin tí ó pọ jùlọ tí o fẹ tà. O tún lè tọka agbègbè rẹ àti kọ́rẹ́ńsì ti o fẹ jùlọ. Wá Àwọn ìnájà. Ìwọ yóò wo àtòkọ ti àwọn ìnájà tí ó yẹ láti yàn.
- Àtúnyẹ̀wò àwọn ìnájà - Ṣáájú kí o tó yan ìnájà kan, ríí dájú láti ṣayẹwo gbogbo àlàyé pàtàkì nípa olùrajà, pẹlú ṣùgbọn kíí ṣe òpin sí orúkọ wọn, ìgbayìsí, ìpele ìjẹ́rìísí, àti òṣùwọn fún Bitcoin. Lọ́gán tí o bá ti ríí ìnájà tí ó yẹ, tẹ Ta .Kì yóò ṣíí òwò síbẹsíbẹ, ṣùgbọn yóò ṣe ìtọ́sọ́nà fún ọ nípasẹ àwọn àdéhùn ìfilọ̀ ìnájà àti Kání ti olùrajà pèsè.
- Bẹ̀rẹ̀ òwò náà - Tí o bá ní ìtẹlọrùn pẹlú àwọn àdéhùn ìfẹnukò olùrajà , tẹ iye ti o fẹ fi ṣòwò àti tẹTà Báyì. Èyí yóò ṣíí ìtàkurọ̀sọ ojutaye àti gbé Bitcoin rẹ sí ààbò ẹsíkírò wa. Ka àwọn ìtọ́nísọ́nà tí a pèsè dáradára, kí o tẹle wọn. Ní kété tí olùrajà parí ìparí òwò wọn àti pé o gba owó sísan, o le fi Bitcoin náà sílẹ. O lè ṣe ìgbàsílẹ ẹ̀rí ìsanwó ti gbogbogboo lẹhìn òwò.
- Fi ìjábọ̀ sílẹ̀ - Lẹhìn tí o ti ní àṣeyọrí títa Bitcoin rẹ , máṣe gbàgbé láti fún olùbádòwòpọ̀ rẹ ni ìjábọ̀. Èyí ṣe pàtàkì fún ìkànnì wa bí ó ṣe ńṣe ìrànlọwọ láti ṣàgbékalẹ̀ ìgbayìsí aṣàmúlò.
Fún àlàyé síwájú síí, wo ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ fídíò àtúngbéyẹ̀wò ẹ̀kọ́ wa lórí bí o ti lè ta Bitcoin ní kíákíá. O tún lè ṣẹdá ìnájà kan láti ta Bitcoin nípa títẹlé ìtọ́sọ́nà wa sí ṣíṣẹdá ìnájà lórí Paxful.
Ibi ìtajà ẹnìkan-sí-ẹnìkejì Paxful rọrùn láti lò, ní ààbò nípasẹ ẹsíkírò, àti wíwọlé sí gbogbo àgbáyé. Bẹ̀rẹ̀ òwò lónì!