ètò ẹlẹ́gbẹ́ paxful

Ètò ẹlẹ́gbẹ́ Paxful

Ṣe Àgbédìde Àwùjọ Rẹ kí ìwọ́ sì J'èrè Bitcoin

Àdáwọ́lé Paxful ní òmìnira ìnáwó fún gbogbo ènìyàn, Ètò Ẹlẹ́gbẹ́ wa sì jẹ́ ǹkan ìrìnnà rẹ láti múu wá sí ìmúṣẹ. Darapọ̀ mọ́ wa, ṣe àfihàn kírípítò sí àwọn ènìyàn tán súnmọ́ ìwọ́, kí ìwọ́ sì j'èrè BTC tí iye rẹ̀ tó 2000 USD tàbí ju bẹ́ẹ̀ lọ nípasẹ̀ nẹ́tíwọọkì rẹ.

Jí Oníṣòwò Inú Rẹ

Mímú àwọn èèyàn wá Paxful rọrùn ó sì dùn. Wo àwọn èrè yìí ìwọ́ lè pawó nígbà tí ìwọ́ bá ń ṣe ìrànwọ́ mímú kírípítò lọ sí àwùjọ rẹ:

ètò ẹlẹ́gbẹ́ paxful
ẸLẸ́GBẸ́
Mú aṣàmúlò tuntun 7 wá
ètò ẹlẹ́gbẹ́ paxful
ÀŃBÁSÁDỌ̀
Mú aṣàmúlò tuntun 20 wá
ètò ẹlẹ́gbẹ́ paxful
ALÁBÀÁṢIṢẸ́PỌ̀
Mú aṣàmúlò tuntun 100 wá
J'èrè 5 USD ní BTC Lóri Àpèwárajà Kan
Àwọn Owópa Àpèwárajà
Àtìlẹ́yìn Ààyò
Báàjì lóri Aṣàpèjúwe Rẹ
Àwọn Ẹ̀bùn Déédé
Àwọn Ìgbéga Ìnájà tí a Fi Hàn
Ṣe Àlékún Ìtẹ̀lé Àwùjọ Rẹ
Ọjà Ìyàsọ́tọ̀ Paxful
Alákòóso Àkántì tó ní Ìfarasíí
Kọ́kọ́ Gbìyànjú àwọn Ẹ̀yà & àwọn Ọjá Tuntun
J'èrè 150 USD ní BTC ní Gbogbo Ọṣù

Báwo ni Mo ṣe lè Di Ẹlẹ́gbẹ́?

Ṣe ìbẹ̀wẹ̀, a yóò ṣàyẹ̀wò rẹẹ̀, tí gbogbo rẹ̀ bá sì dára, ìwọ́ tí wọlé!

ètò ẹlẹ́gbẹ́ paxful

Darapọ̀ mọ́ Ẹbí

Àwọn Ẹlẹ́gbẹ́ wa wá láti gbogbo àgbáyé àti gbogbo ìrìnàjò ayé.

Darapọ̀ Mọ́ Wa lóri Twitter àti Instagram!