Ìfẹnukò Ìlò Ìpawó Paxful

Ọjọ́ tí yóò bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́: Agẹmọ (July) 1, 2021

JỌ̀WỌ́ KA ÀDÉHÙN YÌÍ YÉKÉYÉKÉ. Nípa lílo ètò Ìpawó Paxful, ìwọ́ gba láti jẹ́ dídè pẹ̀lú àfikún "Ìfenukò Ìlò Ìpawó Paxful" wọ̀nyíí ìwọ́ sì gbà wípé ìwọ́ ti kà pẹ̀lú ìfura, ní òye, sì ti gba gbogbo àwọn àdéhùn àti àwọn àlàálẹ̀ tó wà nínu rẹ̀, èyí tó jẹ́ àfikún Ìfenukò Ìlò Paxful ("Àdéhùn" náà). Èyíkèyí àwọn àkànlò èdè tí a lò sùgbọ́n tí a kò túnmọ̀ sí ìsàlẹ̀ ní ìtumọ̀ wọn wà ní inú Àdéhùn. Tí èyíkèyí ìforígbárí bá wáyé láàrin Àdéhùn náà àti Ìfenukò Ìlò Ìpawó Paxful ní àsìko tàbí tó ní ìbátan pẹ̀lú ìlò ètò Ìpawó Paxful rẹ, Ìfenukò Ìlò Ìpawó Paxful ni yóò borí.

Nípa Ìpawó Paxful

Ètò Ìpawó Paxful jẹ́ ètò àpèwárajà tó f'àyè gbà ọ́, aṣàmúlò Paxful tó peregedé, láti fi àwọn Ohun Ìní Onídíjítà rẹ ránṣẹ́ sí ìkànnì olùbádòwòpọ̀ (the "Earn Counterparty"), níbi tí o ti lè jèrè fún dídi àwọn Ohun Ìní Onídíjítà mú ní àwọn wálẹ́ẹ̀tì rẹ̀.

Ètò Àpèwárajà

Ètò Ìpawó Paxful jẹ́ ìlànà àpèwárajà tó níwọ̀n tí ó wà nípasẹ̀ ìkànnì Paxful. Nípa fífi ìfẹ́ rẹ hàn láti kópa nínú Ìpawó Paxful, o fún Paxful ní àṣẹ láti pín àlàyé àkántì Paxful rẹ pẹ̀lú Earn Counterparty àti àlàyé ìdánimọ̀ àdáni fún àwọn ìdí láti ṣètò àyẹ̀wo Earn Counterparty ti yíyẹ rẹ láti kópa nínú ètò Ìpawó Paxful. Àlàyé yìí le pẹ̀lú, ṣùgbọ́n kò ní òpin sí, orúkọ rẹ, ọjọ́ ìbí, àti ìpínlẹ̀ àti orílẹ̀-èdè tí ò ń gbé. Earn Counterparty lè bèrè fún àlàyé àfikún. Lẹ́yìnnáà o gbọdọ̀ tẹ̀lé àwọn ohun tí a pèsè ní ìbẹ̀rẹ̀ láti fi èyíkèyí àlàyé àfikún sílẹ̀. Earn Counterparty lè fipamọ́, ráyè sí, fi ránṣẹ́ tàbí lo àlàyé ti ara rẹ yàtọ̀ sí bí a ṣe lòó. Tí o kò bá fẹ́ láti pín àlàyé ìdánimọ̀ ara rẹ pẹ̀lú Earn Counterparty, má ṣe kópa nínú Ìpawó Paxful.

Lẹ́yìn ìjẹ́rìísí, o lè yan irú (àwọn) àwọn Ohun-ìní Onídíjítà àti àwọn ẹ̀bùn tí ó jọ mọ́ọ tí Earn Counterparty pèsè fún àsansílẹ̀. Lọ́gán tí o bá yàn láti san àsansílẹ̀ àwọn Ohun-ìní Onídíjítà, àwọn Ohun-ìní Onídíjítà yóò wà ní títì ní wálẹ́ẹ̀tì Paxful rẹ yóò sì jẹ́ fífiránsẹ́ sí ìkànnì Earn Counterparty. Àwọn Ohun-ìní Onídíjítà tí o san àsansílẹ̀ wọn náà, àti àwọn èrè tí o p, wa fún ọ láti wò nípasẹ̀ abala Wálẹ́ẹ̀tì Mi / Ìpawó lóri ìkànnì Paxful.

The interest earned by Users is determined by, and subject to the rules of, the Earn Counterparty and may be changed or modified by the Earn Counterparty at its sole discretion. By entering into a transaction with the Earn Counterparty you agree to be bound by the Earn Counterparty’s Terms of Service. The Earn Counterparty Terms of Service are valid in all cases except when they contradict or violate the Agreement, these Paxful Earn Terms of Service, are illegal, are unreasonable or otherwise difficult to comply with (as determined in Paxful’s sole and absolute discretion), or if you and the Earn Counterparty consent to alter the Earn Counterparty Terms. IT IS YOUR RESPONSIBILITY TO CAREFULLY READ THE EARN COUNTERPARTY TERMS AND FOLLOW THEM EXACTLY. IF YOU DO NOT FOLLOW THE EARN COUNTERPARTY TERMS, YOUR TRANSACTION MAY BE DENIED. NEVER ENTER INTO A PAXFUL EARN SERVICE TRANSACTION UNLESS YOU HAVE FOLLOWED ALL TERMS AND CONDITIONS LISTED. IF YOU FAIL TO FOLLOW THE TERMS AND CONDITIONS, PAXFUL MAY NOT BE ABLE TO ASSIST YOU IN A DISPUTE PROCESS TO RECOVER YOUR FUNDS.

Àwọn Owósan

Paxful yóò kó àkóyawọ́ nípa àwọn owósan wa nígbà gbogbo. Èyíkèyí àwọn owósan ni yóò wà fún ìlò àwọn iṣẹ́ Paxful rẹ. Fún àlàyé síi àti àwọn ìmúdójúìwọ̀n lóri àwọn owósan ìyípadà, jọ̀wọ́ tọ́ka sí Ibùdó Ìrànwọ́ wa.

Àwọn Àkántì Ìyege àti àwọn Sàkání Òfin tó wà ní Ìhámọ́

Ètò Ìpawó Paxful ní a jẹ́ kó wà fún àwọn aṣàmúlò tí wọ́n yẹ fún ètò náà nìkan. Paxful ní ẹ̀tọ́ láti f'òfindè tàbí ṣàtúnṣe ètò Ìpawó Paxful fún èyíkèyí aṣàmúlò Paxful, Earn Counterparty sì lè kọ èyíkèyí ìdúnadúrà pẹ̀lú èyíkèyí aṣàmúlò Paxful. Ní àfikún sí àwọn Sàkání Òfin tó wà ní Ìhámọ́ bí wọ́n ti ṣe gbée kalẹ̀ ní Abala 2.7 ti Ìfenukò Ìlò wa, ètò Paxful Earn kò sí fún àwọn aṣàmúlò tí wọ́n ń gbé ní Ìpínlè Texas, pẹ̀lú èyíkèyí orílẹ̀-èdè tàbí ìpínlè mííràn tí ìfẹnukọ̀ ìlò Earn Counterparty. f'òfindè.

KÒ SÍ ÀTÌLẸYÌN ỌJÀ, ÌDIWỌ̀N LAYABÍLÍTÌ & ÀRÒSÍNÚ TI EEWU

ÀWỌN ÈTÒ ÌLÒ ÌPAWÓ PAXFUL NI A PÈSÈ LÓRÍ “ BÍ Ó TI ṢE RÍ” ÀTI “BÍ Ó ṢE WÀ“ LÁÌSÍ ÈYÍKÉYÌ ÀWỌN ÌṢÈDÚRÓ, ÀWỌN AṢOJÚ TÀBÍ ÀWỌN ÀTÌLẸYÌN ỌJÀ, BÓYÁ ÌYÁRA, ÌDÁBÁ TÀBÍ ỌRANYÀN. SI IYE TI Ó PỌ̀JÙ TI ÒFIN TÓ WÀ FÚN UN GBÀ LÁÀYÈ, PAXFUL NI PÀTÓ KỌ ÈYÍKÉYÌ ÌDÁBÁ ÀWỌN ÀTÌLẸYÌN ỌJÀ TI O NÍ ÀKỌLÉ, TÍ Ó ṢEÉ TA, DÍDÁRA FÚN ÌDÍ KAN ÀTI/TÀBÍ ÀÌLÒDÌSÁDÉHÙN.PAXFUL KÒ ṢE ÈYÍKÉYÌ ÀWỌN AṢOJÚ TÀBÍ ÀWỌN ÀTÌLẸYÌN ỌJÀ TÍ Ó NÍ IRAYE SÍ WẸ́BÚSÁÌTÌ, ÈYÍKÉYÌ Ẹ̀YÀ TI ÀWỌN IṢẸ́, TÀBÍ ÈYÍKÉYÌ TI ÀWỌN OHUN ÈLÒ TI O WÀ NÍBÍ,YÓÒ TẸSÍWÁJÚ LÁÌSÍ ÌDÁDÚRÓ, LÁSÌKÒ, TÀBÍ LÁÌNÍ ÀṢÌṢE. PAXFUL KÌÍ ṢE ONÍDÙÚRÓ FÚN ÈYÍKÈYÍ ÌDÁLỌ́WỌ́DÚRÓ TÀBÍ ÌPÀDÁNÙ TÍ AṢÀMÚLÒ LÈ KOJÚ.ÌWỌ NIBIYI GBÀ ÀTI GBÀ PÉ ÌWỌ KÓ DÚRÓ LÓRÍ ÈYÍKÈYÍ ÀLÀYÉ MÍRÀN TÀBÍ AGBỌYE, BÓYÁ KÍKỌ TÀBÍ SÍSỌ, NÍ ÌBÁMÚ SÍ LÍLÒ ÀTI IRAYE TI ÀWỌN IṢẸ́ ÀTI WẸ́BÚSÁÌTÌ.LÁÌSÍ ÒPIN ÌTÈ̩SÍWÁJÚ NÁÀ. ÌWỌ NIBIYI GBÀ ATI GBÀ PÉ ORÍṢIRÍṢI ÀWỌN EEWU ÀJOGÚNBÁ TI LÍLO KỌ́RẸ́ŃSÌ-ONÍDÍJÍTÀ PẸ̀LÚ ṢÙGBỌ́N TI KÌÍ ṢE ÒPIN SÍ ÌKÙNÀ Ẹ̀YÀ ARA KOMPUTA, WÀHÁLÀ SOFITIWIA, ÌKÙNÀ ASOPO ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ, FAIRỌSI SOFITIWIA, ITOJUBỌ ENIKETA TÍ O ṢE OKÙNFÀ ÌPÀDÁNÙ TÀBÍ AIRAYE SÍ ÀKÁNTÌ TÌRẸ TÀBÍ WÁLẸ́Ẹ̀TÌ ÀTI DÁTÀ AṢÀMÚLÒ MÍRÀN, ÌKÙNÀ Ẹ̀RỌ OLUPIN TÀBÍ IPADANU DÁTÀ. ÌWỌ GBÀ ÀTI GBÀ PÉ PAXFUL KÌÍ YÓÒ ṢE ÌDÚRÓ FÚN ÈYÍKÈYÍ ÀWỌN ÌKÙNÀ IBASORO, ÀWỌN ÌDÁLỌ́WỌ́DÚRÓ, ÀṢÌṢE IDANUJU TÀBÍ ÌDÁDÚRÓ TÍ ÌWỌ LÈ FOJÚWINÁ NÍ LÍLO ÀWỌN IṢẸ́, SÍBẸ̀SÍBẸ̀ TI ṢẸLẸ̀.

NÍ ÌṢẸ̀LẸ̀ KÍ ÌṢẸ̀LẸ̀ NÍ PAXFUL, ÀWỌN ABÁNIPOLÓWÓ RẸ̀ ÀTI ÀWỌN OLÙPÈSÈ IṢẸ́ , TÀBÍ ÈYÍKÈYÍ TI ÀWỌN Ọ̀GÁ WỌN, ÀWỌN ADARÍ, ÀWỌN OLÙRÀNLỌ́WỌ́, ÀWỌN ÒṢÌṢẸ́, ÀWỌN ONIMORAN, ÀWỌN AGBANI-NÍMỌ̀RÀN, TÀBÍ ÀWỌN AṢOJÚ, YÓÒ JẸ́ ONÍDÙÚRÓ (A) FÚN ÈYÍKÉYÌ IYE TI Ó TÓBI JU IYE OWÓSAN ÀPAPỌ̀ TÍ ÌWỌ SAN FÚN IṢẸ́ TÍ Ó JẸ́ OKÙNFÀ FUN ÌṢE NI ÀWỌN OṢÙ KEJÌLÁ (12) SÍWÁJÚ SÍ ÌPÀDÁNÙ LÁTÀRÍ (B) FÚN ÈYÍKÈYÍ ÌPÀDÁNÙ ÀWỌN ÈRÈ, IJAWALE NÍYE TÀBÍ ÀNFÀNÍ ÌṢÒWÒ, ÈYÍKÉYÌ ÌPÀDÁNÙ, ÌBÀJẸ́, ÀJẸBÁNU, TÀBÍ IRUFIN TI DÁTÀ TÀBÍ ÈYÍKÉYÌ OHUN ÌNÍ TÍ KÒ TO PỌ́N MÌÍRÀN TÀBÍ ÈYÍKÉYÌ PÀTÀKÌ, ÌṢẸ̀LẸ̀, AIṢE-TÀÀRÀ, KÒTÓPỌ́N, TÀBÍ ÀWỌN ÌBÀJẸ́ ALEYIN, BÓYÁ DÁ LÓRÍ ÀDÉHÙN, ÌPALÁRA, ÀÌKỌBIARASÍ, ÌDÚRÓ TÓ GBÓPỌN, TÀBÍ BIBEEKO, TÍ. Ó JẸYỌ LÁTÀRÍ TÀBÍ NÍ ASOPO PẸ̀LÚ ALÁṢẸ TÀBÍ. AIGBASE LÍLO WẸ́BÚSÁÌTÌ TÀBÍ ÀWỌN IṢẸ́, TÀBÍ ÀDÉHÙN YÍÍ, PÀÁPÀÁ TÍ AṢOJÚ ALÁṢẸ TI PAXFUL KAN BÁ TI GBA ÌMỌ̀RÀN TI TÀBÍ TI MỌ̀ TÀBÍ YẸ KÓ TI MỌ̀ TI ÌṢE E ṢÉ TI ÌBÀJẸ́, ÀTI PẸ̀LÚPẸ̀LÙ IKUNA TI ÈYÍKÉYÌ TI GBÀ TÀBÍ ÀTÚNṢE ÒMÍRÀN FÚN KÒṢEMÁNÌ ÌDÍ, ÀYÀFI SÍ IYE ÌPINNU ÌPARÍ ÌDÁJỌ́ PÉ ÀWỌN ÌBÀJẸ́ JẸ́ ÀBÁJÁDE ÀÌKỌBIARASÍ ŃLÁ TI PAXFUL, JÌBÌTÌ, IWA-ÌBÀJẸ́ ÀMỌ̀MỌ́Ọ̀ṢE TÀBÍ IRUFIN MÍMỌ̀Ọ́MỌ̀. DÍẸ̀ NÍNÚ ÀWỌN ÀYÍKÁ ÌDÁJỌ́ KÒ FÀYÈ GBA ÌYỌKÚRÒ TÀBÍ ÌDÓPIN ÌṢẸ̀LẸ̀ ÀÌMỌ́ TÀBÍ ÀWỌN ÌBÀJẸ́ ALẸ́YÌN, KÍ ÌDÓPIN TI ÒKÈ LE MÁ KAN ÌWỌ.

O gbà pé Paxful ń ṣiṣẹ́ bíi atọ́kùn olùpèsè fun ètò Paxful Earn yìí. O gbà síwájú pé Paxful kò ní ìṣàkóso lóri, tàbí pé Paxful kò ní dáhùn fún àwọn ètò ìpilẹ̀ṣẹ̀ èrè tí a pèsè nípasẹ̀ Earn Counterparty. Paxful kì yóò dáhùn fún èyíkèyí àwọn àdánù tí ó wáyé látàrí àwọn àìlágbára àdéhùn ọlọ́gbọ́n, àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwọlé ní ọ̀nà àìtọ́, tàbí ìdáṣẹ́dúró, àìtẹ̀síwájú, tàbí ìfopinsí òwò, gbèsè, ìdáṣẹ́dúró tí kò bójú mu tàbí ìdádúró ìdókoòwò Earn Counterparty tàbí àwọn ewu mííràn tí ó ṣeéṣe. O bá gbà láti ru gbogbo àwọn ewu tí ó yẹ tí ó ní ṣe pẹ̀lú ìkànnì Earn Counterparty àti gbogbo àwọn àdánù tí o lè kojú látàrí àwọn ewu tí a mẹ́nubà lókè. Tí o bá kojú ìpàdánù èyíkèyí látàrí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí a sọ lókè, o gbà pé apákan tí ó bá àwọn òwò tí a tìpa mu tí o pàdánù nínú àkántì rẹ ni yóò pàdánù ní iye ìbàjẹ́ tàbí àdánù tí o fà.

O gbà o sí f'ọwọ́ síi pé tí èyíkèyí apákan ètò Paxful Earn tí Paxful pèsè tàbí Earn Counterparty kò bá ṣeé rí àyè sí tàbí ní ìdíwọ́ nítorí àwọn àyídàyidà wọ̀nyí, Paxful kì yóò dáhùn fún èyíkèyí àdánù rẹ tàbí ri èyíkèyí àwọn ẹnìkẹta (pẹ̀lú ṣùgbọ́n kò d'ópin sí èyíkèyí àdánù èrè tààrà, àìṣe-tààrà, tàbí tí ó ṣeéṣe) bíi àbájáde láti ìbẹ̀:

  1. Ìdáṣẹ́dúró Earn Counterparty, àìtẹ̀síwájú, títìpa tàbí fífagilé òwò rẹ̀;
  2. Ìdáṣẹ́dúró ètò fún àtúnṣe bí Earn Counterparty tàbí Paxful ṣe ti kéde;
  3. Ìkùnà ẹ̀rọ níbi ìfiránṣẹ́ dátà;
  4. Force majeure tàbí àwọn ìjàmbá mííràn tí àwọn sábàbí àìrò, kò ṣeé yẹra fún, àti tí kò ṣeé yàn ṣokùnfà, bíi typhoon, earthquake, tsunami, omíya'lé, àjàkálẹ̀ àrùn, àìsí iná, ogun, làásìgbò, àwọn ìgbésẹ̀ ìjọba, àwọn àkọlù agbésùmọ̀mí, etc., tó yọrí sí ìdáṣẹ́dúró Paxful tàbí àwọn ìkànnì Earn Counterparty;
  5. Ìkùnà iṣẹ́, ìdíwọ́ tàbí ìdádúró tí ó wáyé láti ìwọlé ní ọ̀nà àìtọ́, kòkòrò àrùn kọ̀npútà, àtúnṣe ẹ̀rọ tàbí ìkùnà, ìdàgbàsókè wẹ́búsaìtì, àwọn ọ̀ràn ìfowópamọ́, tàbí títì fún ìgbà díẹ̀ tí ó wáyé látàrí àwọn ìlànà ìjọba;
  6. Ìkùnà iṣẹ́, ìdíwọ́, ìdádúró, àìfèsì ẹ̀rọ, tàbí ìdádúró èsì ẹ̀rọ tí bíbàjẹ́ ẹ̀rọ kọ̀npútà ìkànnì Earn Counterparty tàbí Paxful, àlébù tàbí ìdàkejì tí kò ríbi ṣiṣẹ́ b'óṣeyẹ;
  7. Àwọn ìṣòro ẹ̀rọ tí kò ṣeé sọ tẹ́lẹ̀ tàbí yanjú nípasẹ̀ àwọn agbára ìmọ̀-ẹ̀rọ tó wà nílẹ̀ tẹ́lẹ̀ ní ilé-iṣẹ́ náà;
  8. Ìṣòro tàbí ìdádúró èyíkèyí àwọn ẹnìkẹta; tàbí
  9. Àwọn Àyípadà ní èyíkèyí àwọn òfin tó jẹ mọ́ ọ, àwọn ìlànà, tàbí àwọn àṣẹ ìjọba.

O tún gbà o sì f'ọwọ́ síi wípé ìṣẹ̀lẹ̀ sábàbí tí a sọ ní òkè lè jásí àwọn ìdúnadúrà tí kò bójú mu, ìdíwọ́ fún ọjà, àti àwọn sábàbí tí ó ṣeéṣe tí kò bójú mu, Paxful sì ní ẹ̀tọ́ láti kọ láti ṣe ìdúnadúrà rẹ ní ìwòyè tirẹ̀.