Gbé Paxful lọ ibikíbi pẹ̀lú áápù alágbèéká wa.

Fi ránṣẹ́, gbàá, kí o sì d'ókoòwò Bitcoin ní ibikíbi tí ìwọ́ bá lọ pẹ̀lú áápù wálẹ́ẹ́tì alágbèéká Paxful. Gba ìṣàkóso yáànyán BTC rẹ kí ìwọ́ sì ṣe ìṣàmójútó àwọn òwò rẹ ní tòótọ́.

Ṣàyẹ̀wò Kóòdù QR tàbí gbàá láti ilé ipamọ́ áàpù:

content-illustration content-illustration
content-illustration

Àwọn ẹ̀yà

  • Fi ránṣẹ́ kí o sì gba Bitcoin nínú wálẹ́ẹ́tì kọ́rẹ́nsì kírípítò tìẹ gangan
  • Ṣe àmójútó àwọn òwò rẹ tán ṣí sílẹ̀ lóri Paxful kí ìwọ́ lè mọ ipò tí àwọn ìdúnadúrà rẹ wà lọ́wọ́lọ́wọ́ bí ìwọ́ ṣé n ra àti ta Bitcoin
  • Ṣe àdáni asàpèjúwe wálẹ́ẹ̀tì Paxful rẹ kí àwọn ènìyàn tí ìwọ́ ń bá dúnadúrà lè mọ̀ wípé ìwọ ni
  • Ṣàpamọ́ tóláàbò Bitcoin rẹ tí ìwọ́ ṣe wàhálà pa pamọ́ ní ọ̀nà ààbò kí ìwọ́ sì wo àṣẹ́kù owó rẹ ní tòótọ́
  • Pín àdírẹ́ẹ̀sì wálẹ́ẹ́tì Bitcoin rẹ tàbí kóódù QR pẹ̀lú àwọn olókoòwò mííràn àti àwọn ọ̀rẹ́.
  • Jẹ́ ìmúdójúìwọ̀n iye owó ìpààrọ̀ Bitcoin-sí-kọ̀rẹ́nsì fíàtì ní ìrọ̀rùn rẹ
  • Gba àwon ìfitóníléti lórí ẹ̀rọ alágbèéká nípa àwọn ìṣòwò àtí àwọn ìnájà rẹ
  • Kò lè wọlé sí Google Play? Tẹ ibi làti kọ ohun tó lè ṣe