Ṣé a lè jẹ́ ọ̀rẹ́?

Darapọ̀ mọ́ àwùjọ Paxful

Jẹ́ kí á darapọ̀ lóri òpó ayélujára ìgbàlódé a yóò sì máa fi ohun tó ń ṣẹlẹ̀ ní Paxful àti ayé kírípítò tó ìwọ létí. Ibí ni ìwọ yóò ti rí àwọn àkántì òpó ìgbàlódé wa—àwa yóò ṣe ìmúdójúìwọ̀n abala yìí èyíkèyí àwọn tuntun tí a bá tún fi kún un.

àwọn àkántì òpó ayélujára ìgbàlódé paxful

Jẹ́ k'á darapọ̀!

Darapọ̀ pẹ̀lú àkántì kan ní abẹ́, tàbí gbogbo wọn!

àwọn àkántì òpó ayélujára ìgbàlódé paxful

Jẹ́ kí a ní ìtàkurọ̀sọ lórí Telegram

Àwá ti ṣ'èdá àwọn ìkànnì Telegram fún orílẹ̀-èdè kọ̀ọ̀kan tí a tí ń ṣiṣẹ́. Darapọ̀ mọ́ wa lórí Telegram láti ní ìtàkurọ̀sọ pẹ̀lú wa nípa àwọn ìmọ̀ràn rẹ fún Paxful pẹ̀lú àwọn olólùfẹ́ kírípítò tó kù ní àwùjọ rẹ.

Àwọn ìpàdé orí ayélujára Paxful

Ṣé o fẹ́ wà ní ìmúdójúìwọ̀n pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà tuntun lórí Paxful àti àwọn ohun tó ń lọ ní ayé kírípítò? Àwọn ìpàdé orí ayélujára wa jẹ́ ìṣúra ìmọ̀ fún ìwọ láti jẹ ànfààní.

àwọn àkántì òpó ayélujára ìgbàlódé paxful