Pàdé ẹgbẹ Paxful!

Àwọn òṣìṣẹ ti Paxful jẹ ọkàn ti ilé-iṣẹ wa. Pẹlú oríṣiríṣi àṣà àti ẹ̀yà, nígbàgbogbo a ńkọ ẹ̀kọ́ láti ọdọ ara wa. Apákan tí ó dára jùlọ? Gbogbo ènìyàn lè ní ìrírí àwọn èdè àti àṣà oríṣiríṣi. A lè ní ẹgbẹ ọjà ìfiṣòótọ ṣùgbọn ìkànnì wa jẹ àbájáde ti iṣẹ ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àti ìjábọ̀ láti gbogbo ẹgbẹ àti ẹka.

Max

Ìgbìmọ̀ Àjọṣepọ̀ (Orílẹ̀-èdè Olómìnira Amẹ́ríkà)

Kíni nǹkan náà tí o kò lè ṣàìṣe lọ́jọ́ kan ní Paxful?

Ṣíṣe àwàdà pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ ẹgbẹ́ mi

Kíni ó mú ọ ní ìwúrí níbí ní Paxful?

Agbára. Ilé-iṣẹ yíí ní agbára ńlá, àti pé Mo mọ pé Mo lè kó ipa ńlá nínú rírí pé a ṣe àṣeyọrí yẹn.

Kíni nńkan kan nípa ìṣúná Paxful / P2P tí o fẹ ki gbogbo ènìyàn mọ?

Àwọn ènìyàn bèèrè ìdí ti ìṣúná P2P ṣe pàtàkì. Báǹkì Àgbáyé gbà pé o fẹrẹ tó bílíọ̀nù méjì ènìyàn ni kò ní ààyè sí àwọn iṣẹ ìṣùnà ti ìbílẹ̀. Paxful fún àwọn ènìyàn wọnnì ní àyè láti ní ipa nínú ètò ìṣúná.

Lana

Olórí Òṣìṣẹ́ Ìbámu (Orílẹ̀-èdè Olómìnira Amẹ́ríkà)

Kíni ó mú ọ ní ìwúrí níbí ní Paxful?

Ìlàkààkà àti akitiyan láti mú Bitcoin dé ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn

Kíni ipa tí ó ní ìtumọ jùlọ nípa Iṣẹ́ rẹ?

Mo wà ní ìkápá rírí dájú pé a mú àwọn ènìyàn búburú. Mo ti fún ẹgbẹ mi ní àwọn irinṣẹ àti àwọn ìlànà láti ṣe bẹ. A ní ìfaradà òdo fún jìbìtì àti iṣẹ́ arúfin lórí ààyè wa.

Trisha

Olùyàwòrán Onídíjítà (Philippines)

Kíni ànfàní tí ó dára jùlọ níbí ní Paxful?

Mo ní ìfẹ́ ànfàní ti ìdárayá àti spa! Ilé-iṣẹ ṣe àbójútó gaan nípa ìlera ti àwọn òṣìṣẹ rẹ àti pe ànfàní pẹ́ẹ̀kì yíí ṣe ìrànlọwọ fún ọ láti ní díẹ nínú ìsínmi lákókò wàhálà jùlọ ti àwọn ọjọ.

Kíni nńkan kan nípa ìṣúná Paxful / P2P tí o fẹ ki gbogbo ènìyàn mọ?

Mo fẹ kí àwọn ènìyàn mọ síwájú síí nípa ilé-iṣẹ ní àpapọ. Ilé-iṣẹ ìṣúná owó P2P ní ọpọlọpọ àwọn nǹkan láti pèsè, pàápàá sí àwọn tí kò ní báǹkì.

Kíni ìṣẹlẹ àyànfẹ ilé-iṣẹ Paxful rẹ tí o ti lọ títí dí ìsinsìnyí?

Kíni ìṣẹlẹ àyànfẹ ilé-iṣẹ Paxful rẹ tí o ti lọ títí dí ìsinsìnyí?

Ysabelle

Ìtajà fídíò (Philippines)

Kíni ó mú ọ ní ìwúrí níbí ní Paxful?

Ohun tí ó ń mú mi tẹ̀síwájú ní àwọn àyè àìlópin láti dàgbà níhìn. Pàápàá nígbàtí mo wà ní ọdọ, wọn gbàgbọ nínú mi àti iṣẹ mi. Wọn fún mi ní àyè láti fihàn ohun tí Mo lè ṣe.

Kíni ìṣẹlẹ àyànfẹ ilé-iṣẹ Paxful rẹ tí o ti lọ títí dí ìsinsìnyí?

Ni gbogbo ìgbà tí a bá jáde fún àwọn mímu, o máa ń jẹ́ ìgbádùn púpọ̀ àti ọnà ńlá fún mi láti ìrẹ́pọ̀ pẹlú àwọn ẹlẹgbẹ mi ní ìta iṣẹ!

Kíni ipa tí ó ní ìtumọ jùlọ nípa Iṣẹ́ rẹ?

Iṣẹ́ mi gbà mi láàyè láti ṣe ìyípadà ìfẹrànmi sí iṣẹ́ tí yóò nípa sí àwọn tí ó ń wo àwọn fídíò tí a ṣe.

Michelle

Olùyanjú Dídára ìjábọ̀ (Philippines)

Kíni ànfàní tí ó dára jùlọ níbí ní Paxful?

Seeing the whole team improve, working at our best with genuine smiles on our faces. Being a part of that process for improvement keeps my drive going here at Paxful. And of course when the value of Bitcoin rises!

Kíni nńkan kan nípa ìṣúná Paxful / P2P tí o fẹ ki gbogbo ènìyàn mọ?

Mo fẹ kí gbogbo ènìyàn ní òye tó dára lórí bíí Bitcoin ṣe ń ṣiṣẹ ní àpapọ àti bíì ìlànà ìdókòwò ṣe ń ṣiṣẹ ní Paxful kí wọn lè ní òye dáradára bóyá wọn ṣe ète ìtànjẹ tàbí rárá.

Kíni nǹkan tí o fẹ láti ríí pé Paxful ṣàṣeyọrí tàbí ṣe bí ilé-iṣẹ ní àwọn ọdún díẹ tí ń bọ?

Di ilé-iṣẹ fintech àkọ́kọ́ àti ìkànnì ìdókòwò P2P!

Madis

Olùgbéejáde PHP (Estonia)

Kíni nǹkan náà tí o kò lè ṣàìṣe lọ́jọ́ kan ní Paxful?

Ìpanu lórí àwọn èso mímu àti èso jíjẹ ní ibi ìdáná, pàápàá àwọn kajú.

Kíni ó mú ọ ní ìwúrí níbí ní Paxful?

Àwọn ènìyàn tí Mo ṣiṣẹ pẹlú àti àwọn ibi-afẹdé ilé-iṣẹ tí ó ṣe ìrànlọwọ fún ènìyàn láti wọlé sí àwọn iṣẹ ìṣúná ti wọn bíbẹ́ẹ̀kọ́ kìì yóò ní ànfànì.

Kíni nńkan kan nípa ìṣúná Paxful / P2P tí o fẹ ki gbogbo ènìyàn mọ?

Wípé àwọn ọnà gidi wà, àwọn ọnà èrè láti lowó lórí Paxful àti pé kìí ṣe gbogbo ènìyàn ní o jẹ atànnijẹ

Pavel

Onímọ̀ -ẹrọ Kubernetes (Estonia)

Kíni nǹkan náà tí o kò lè ṣàìṣe lọ́jọ́ kan ní Paxful?

Ohun mímu kọfí pẹlú àwọn ẹlẹgbẹ mi. O jẹ àkókò tí ó dára láti gba ìjábọ̀ ti ọlọ́rẹ̀dọ́rẹ̀ láti ọdọ ẹnikẹni kí o kọ ẹkọ ohun tí ń ṣẹlẹ láàrín àwọn ẹka mííràn. Àwọn ìtàkurọ̀sọ ọlọ́rẹ̀dọ́rẹ̀ lè fí àwọn wákàtí pamọ ní àwọn ìpàdé.

Kíni ànfàní tí ó dára jùlọ níbí ní Paxful?

Ìdárayá, ṣe oúńjẹ ọsán, àwọn ọjọ ìsinmi. Ohun tí o ṣe kókó tí a máa ń gbàgbé nígbàgbogbo, síbẹsíbẹ, ni pé Paxful jẹ ilé-iṣẹ olóòótọ jùlọ tí Mo ti ṣiṣẹ fún ní ìgbésí ayé mi. Wọn ṣe ohun gbogbo ti wọn lè ṣe láti jẹ kí ọjọ rẹ ní ìtùnú síwájú síi àti láti jẹ kí o lérò pàtàkì.

Kíni ìṣẹlẹ àyànfẹ ilé-iṣẹ Paxful rẹ tí o ti lọ títí dí ìsinsìnyí?

Ìṣẹlẹ ìkọjá tí o lárinrin jùlọ ní Àwọn Ọjọ Òòru wa, nígbàtí gbogbo ilé-iṣẹ, pẹlú gbogbo ènìyàn láti àwọn ọ́fíìsì mííràn, kójọpọ fún ìrìn-àjò ẹgbẹ-alábàṣiṣẹpọ ní Split, Croatia. Ó jẹ ohun ìyanu láti pàdé àwọn alábàṣiṣẹpọ, mímọ gbogbo ènìyàn, àti kọ ẹmí ẹgbẹ gidi.

Aska

Ìbámu (Hong Kong)

Kíni ó mú ọ ní ìwúrí níbí ní Paxful?

Àwọn àbájáde àti àwọn ọmọ ẹgbẹ mi.

Kíni nńkan kan nípa ìṣúná Paxful / P2P tí o fẹ ki gbogbo ènìyàn mọ?

Wípé a ń gbìyànjú ipá wa láti dáàbòbò àwọn olùtajà àti àwọn olùrajà! Ohun ìkẹhìn tí a fẹ ni láti mú BTC rẹ dúró

Kíni ìṣẹlẹ àyànfẹ ilé-iṣẹ Paxful rẹ tí o ti lọ títí dí ìsinsìnyí?

Lílọ sí àwọn ọ́fíìsì oríṣiríṣi fún àwọn àbẹwò àti ìkẹkọ

Tugba

Olùṣàkóso Abánipolówó (Estonia)

Kíni nǹkan náà tí o kò lè ṣàìṣe lọ́jọ́ kan ní Paxful?

Ẹgbẹ́ mi!

Kíni ó mú ọ ní ìwúrí níbí ní Paxful?

Ànfàní ìdàgbà aláràgbàyídá wa fún ọjọgbọn àti àwọn ọgbọn ìṣàkóso.

Kíni nńkan kan nípa ìṣúná Paxful / P2P tí o fẹ ki gbogbo ènìyàn mọ?

Gbogbo àwọn ìṣẹlẹ Paxful jẹ ìgbádùn! Ṣùgbọn pàápàá fẹràn Àwọn Ọjọ Ooru 2019, níbi tí a lo ọsẹ kan ní Kroatia.