Ìbáṣepọ ìbáramu

Ohun tí ó tóbi jùlọ láti fisọ́kàn ní ibáṣepọ ìbáramu, a fẹ ríi dájú pé ìwọ yóò ní ìdùnnú nínú ipa tí o ń ṣe ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò fún àti ní ìpadàbọ, o dára jùlọ láti pinnu fún ara rẹ bóyá tàbí kìí ṣe èyí ni ààyè tó tọ fún ọ.

1

Fi ìwé ìwáṣẹ̀ sílẹ̀

2

Jẹ́ kí a ní ìtàkurọ̀sọ

A yóò pè ọ. Èyí ni ànfàní fún ọ láti fihàn wa ohun tí o mọ àti ìfẹ

3

Ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò àkọ́kọ́

Sọ fún wa bí àwọn ọgbọn àti àwọn òye rẹ ṣe lè ṣe alábàápín sí iṣẹ gbogbo gbòò ilé-iṣẹ wa.

4

Iṣẹ́ ìyànsílẹ̀ ìdánwò

Àsìkò tí tó láti lè fi hàn wá ohun tí o lè ṣe

5

Ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò ẹlẹẹ̀kejì

Ìwọ yóò pàdé àwọn akẹgbẹ àti àwọn adarí láti parí ètò náà.

6

Ìnájà ati àdéhùn

Káàbọ̀ sí ẹbí Paxful!

7