Níbí ní Paxful, a gbìyànjú láti ṣe àwọn ìyípadà tó dára sí ìgbésí ayé ènìyàn lójoojúmọ. A gbàgbọ òmìnira ti owó jẹ ẹtọ ènìyàn àti ìpinnu láti jẹ kí ó jẹ òtítọ. Darapọ mọ ìdí wa kí o ṣe ìyàtọ!
Ṣe o fẹ mọ nǹkan tí Paxful jẹ? Wo fídíò ìgbayì yíí kí o ríi
Ṣíṣiṣẹ́ ní Paxful jẹ ohunkóhun ṣùgbọn ìyàtọ̀. Pẹlú àwọn ọfíísì mẹrin tí ó wà káàkiri àgbáyé, àwọn ẹgbẹ wa nígbàgbogbo ní kalẹ̀. A ń ṣiṣẹ takuntakun, ṣeré gidi, àti lẹhìńnà ṣiṣẹ síwájú síi láti ríi dájú pé a wà níwájú ìfagagbága nígbàgbogbo. O lè nígbàgbogbo rí àwọn òṣìṣẹ Paxful tí ń jó si orin, ní ibi ìdárayá, jíjẹ àwọn ìpanu, tàbí ibi ìsinmi nínú òòrùn. Ó lè máà dùn ún gbọ ṣùgbọn a pe ara wa ní ẹbí nítorí a nífẹ ara wa àti nífẹ ohun tí à ń ṣe.
Ibi-afẹdé wa ni òmìnira ètò-ọrọ nípasẹ ìṣúnáẹnìkan-sí-ẹnìkejì. Pẹlú ìkànnì tí o ní ààbò, ojúlówó tí ó jẹ ti àwọn Oníbárà tí a ti jẹ́rìsí, a ní ìfọkànsí láti jẹ ìwé ìrìnnà owó káríayé àti onítumọ gbogbo àgbáyé fún owó. Fífi ẹkọ sí iwájú, ẹgbẹ wa ń wá láti ṣe ìrànlọwọ fún àwọn ènìyàn láti gbogbo àgbáńlá ayé láti sopọ kí o kọ àwọn ìbátan pẹlú ara wọn, gbígbà wọn láàyè láti kọ ẹkọ àti dàgbà papọ. Ní òpin ọjọ, ọ jẹ nípa ṣíṣe àwọn ìyàtọ ojúlówó ní àwọn àyè níbi gbogbo. Ìyípadà gidi ti àwọn ènìyán gidi mú wá.
À ń pèsè óúnjẹ ọsán ati óúnjẹ alẹ ní gbogbo ọjọ, ẹgbẹ ọmọ-ìdárayá tí o fẹ, ọpọlọpọ àmọdájú àti àwọn àfikún óúnjẹ, àwọn ara wíwọ́ àti àwọn àbẹwò sí ibìtọ́jú egungun ẹyín, àti àwọn ìṣẹlẹ ẹgbẹ tì ó jọmọ ìlera. Àwọn ìjùmọsọrọ ìṣoògùn lórí ayélujára pẹlú àwọn dọ́kítà ògbóntarìgì.
Láti ìrìn-àjò àwọn ilé-ẹkọ gíga ní àyika àgbáyé sí ìpèsè àwọn orísun àìlópin fún ìkẹkọ àti ìdàgbàsókè ọjọgbọn, a gbàgbọ pé ọnà kan tí ó wà fún ìtẹ̀síwájú ní ìdàgbàsókè àtí ẹkọ tí ó ń tẹsíwájú.
Yíyípadà àgbáyé kò rọrùn. Nítorínáà láti ṣe ìwọntúnwọnsì gbogbo iṣẹ líle, à ń pèsè àwọn iṣẹ ṣíṣe, àwọn ìṣẹlẹ, àti pàápàá àwọn ìsanwó ìsinmi ti gbogbo ilé-iṣẹ nìkan fún ìgbádùn, ìrírí, àti àwọn ìsopọ tí o lè ṣàgbékalẹ̀ pẹlú àwọn ẹlẹgbẹ rẹ láti apá kejì àgbáyé.
Ọkàn ti Paxful. Àwọn ẹgbẹ kárí ọjà ń ṣíṣẹ̀ kánmọ́kánmọ́, nípa ṣíṣe àwọn ọjà titun nígbàgbogbo, mímú àwọn tí ó wà tẹlẹ dé ìmúdójúìwọn , àti ní ìrètí ọjọ iwájú ti ìṣúnáẹnìkan-sí-ẹnìkejì.
Àwọn ẹgbẹ kárí ọjà ń ṣíṣẹ̀ kánmọ́kánmọ́, nígbàgbogbo rónú àwọn ọnà tuntun láti mú ìrírí ti aṣàmúlò wa dára. Àwọn apilẹ̀, Àwọn alákóso Ọjà àti Àwọn aṣàtúpalẹ̀ ń ṣiṣẹ idán wọn, yíyí àwọn ìmọràn padà sí àwọn ọjà àti àwọn ẹyà lílò.
Ẹ̀ka tí o tóbi jùlọ ti Paxful ti tànká láàrín àwọn orílẹ̀-èdè si orílẹ̀-èdè oríṣiríṣi láti ríí dájú àtìlẹyìn 24/7 àti ìpinnu àríyànjiyàn. Àwọn ẹgbẹ wọnyí ń ṣiṣẹ lórí ààbò ìkànnì wa àti àwọn aṣàmúlò, ní ìdánilójú pé àwọn ìlànà ìbéèrè pé àti ṣíṣe àkópọ̀ ìtẹ̀léra kírípítò tó ti ní ìlọsíwájú.
Ìwọnyí ní àwọn ènìyàn tí ńtan ìhìnrere ti ìṣúnáẹnìkan-sí-ẹnìkejì káàkiri àgbáyé. Lílo méjèèjì àwọn ìkànnì ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tiwantiwa àti ti orí ayélujára, wọn ṣe ìfọkànsí láti dé ọdọ àwọn olùgbọ́ àgbáyé nípasẹ ètò-ẹkọ, àkóónú, àti ìbáṣepọ àwùjọ.
Àwọn ẹka wọnyí jẹ epo si ẹrọ wa. Wọn ríí dájú pé àwọn ìwé wa ti wà ní ìmúdójúìwọn àti pé gbogbo àwọn ìṣe wa wà lábẹ òfin.
Àwọn ènìyàn tí ó ríí dájú pé Paxful jẹ ibi iṣẹ ti o dára jùlọ láíláí! Wọn ń ṣiṣẹ gbogbo àwọn ìgbìyànjú àwọn ènìyàn wa, àti ṣiṣẹ́ gbogbo àwọn ọrọ ti o ní ìbátan sí ìdàgbàsókè agbárí, pẹlú ṣíṣe ìṣàkóso ọ́fíìsì àti ọpọlọpọ àwọn iṣẹ àkànṣe ìṣàkóso.
Ìbáṣepọ ìbáramu àti ìwé ìwáṣẹ̀
Gbaradì fún ìpè kan
Ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò àkọ́kọ́