Ra Bitcoin lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ní Zimbabwe

Paxful, ibi ìtajà Bitcoin tó ń ṣíwájú ní àgbáyé tó ń lo agbára àwọn ènìyàn, ti wà ní Zimbabwe. Nísìín ìwọ́ lè fi BTC dáàbò bo ọrọ̀ rẹ lọ́wọ́ ìgbówólórí tàbí yanjú èyíkèyí àwọn ìdúnadúrà abẹ́ẹlẹ́.

Àwọn ìṣòro ọrọ̀-ajé tí orílẹ̀-èdè ń kojú yé wa, nítorí náà ni a ṣe múu rọrùn fún ará Zimbabwe láti ra Bitcoin lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ àti ní ìdíyelé tó kéré jù. Ní ìrírí owósan ọ̀fẹ́ nígbàtí ìwọ́ bá ń ra BTC lọ́dọ̀ àwọn olùtajà nínú àti ní ìta orílẹ̀-èdè náà. Ṣé ìwọ kò ní àkántì bánkì? Máṣe làágùn bí ìwọ́ ṣe lè mú lára àwọn ọ̀nà ìsanwó tí wọ́n lé ní 300 láti sanwó fún kọ́rẹ́nsì kírípítò rẹ pẹ̀lú àwọn káàdì ẹ̀bùn, Skrill, àti Western Union.

Tọ́jú iye owó rẹ lónìí! Forúkọsílẹ̀ lórí Paxful, gba wálẹ́ẹ́tì Bitcoin ọ̀fẹ́ rẹ, kí ìwọ́ sì d'ókoòwò lọ!

Àwọn ìnájà tí wọ́n lékè fún Dọ́là Zimbabwean ní Zimbabwe

Olùtàjà Sanwó pẹ̀lú Tí ó kéré jù

láti san

láti san

Lórí dọ́là

mikechikosi +49
Ti ríi ìsẹjú 19 kọjá
EcoCash Fast release
3,220.00 ZWL $1.11
Reborn66 +151
Orí Ayélujára
Mukuru Fast and reliable
7,500.00 ZWL $0.72
àwọn ìsanwó orí ayélujára Paxful 6
HOSTCOIN001 +126
Ti ríi wákati 9 kọjá
Mukuru HONEST AND RELIABLE
3,220.00 ZWL $0.81
àwọn ìsanwó orí ayélujára
ZazzyLeafbird225 +0
Ti ríi wákati 13 kọjá
EcoCash Ecocash
3,220.00 ZWL $1.11
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn ìsanwó orí ayélujára bánkì kannáà nìkan
Paywyze +51
Ti ríi wákati 14 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Any Zimbabwe Bank zipit
3,220.00 ZWL $1.11
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó ó nílò àwòrán ìdánimọ̀ kò sí àwọn ẹnìkẹta
Wemadeyou +5
Ti ríi wákati 11 kọjá
EcoCash
3,220.00 ZWL $1.11
Wemadeyou +5
Ti ríi wákati 11 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì ZB bank
3,220.00 ZWL $1.11
Ngiza +86
Ti ríi wákati 5 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Zimbabwean banks only
3,220.00 ZWL $1.11
mikechikosi +49
Ti ríi ìsẹjú 19 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Any Zimbabwean bank
3,220.00 ZWL $1.11
Paxful 6
prettyqueen888 +405
Ti ríi ìsẹjú 9 kọjá
PayPal
10,856.00 ZWL $0.63
àwọn káàdì àfojúrí nìkan kò sí àwọn ẹnìkẹta
J_Crypto +113
Orí Ayélujára
Mukuru mukuru to mpesa
3,220.00 ZWL $0.64
àwọn ìsanwó orí ayélujára
INSTANT5 +48
Orí Ayélujára
Mukuru INSTANT RELEASE
32,200.00 ZWL $0.67
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ìsanwó orí ayélujára
hustlermik +246
Ti ríi ìsẹjú 1 kọjá
Mukuru PROMPT RELEASE
3,520.00 ZWL $0.69
àwọn ìsanwó orí ayélujára
mathewk92 +452
Ti ríi wákati 1 kọjá
Mukuru MUKURU TO MPESA
5,000.00 ZWL $0.72
àwọn ìsanwó orí ayélujára
kym32 +222
Orí Ayélujára
Mukuru Instant Release
10,000.00 ZWL $0.72
Coinhorse +443
Orí Ayélujára
Mukuru Honest and reliable
3,220.00 ZWL $0.72
àwọn ìsanwó orí ayélujára
munondowashe +136
Ti ríi wákati 1 kọjá
EcoCash
3,220.00 ZWL $1.11
Paxful 6
pm_Coinfly +267
Orí Ayélujára
Mukuru MUKURU TO MPESA
3,500.00 ZWL $0.72
àwọn ìsanwó orí ayélujára
Kay_vo +132
Ti ríi wákati 5 kọjá
Mukuru instant release to mpesa
30,000.00 ZWL $0.75
kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ìsanwó orí ayélujára
Reborn66 +151
Orí Ayélujára
EcoCash Fast and reliable
17,000.00 ZWL $0.77
àwọn ìsanwó orí ayélujára Paxful 6

Àwọn ìlànà ìsanwó tí wọ́n lékè ní Zimbabwe

EcoCash

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú EcoCash lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú EcoCash

Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

PayPal

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú PayPal lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú PayPal

Káàdì Ẹ̀bùn Amazon

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon

Mukuru

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Mukuru lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Mukuru

AirTM

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú AirTM lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú AirTM

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.

Ṣé mo lè ta Bitcoin lórí Paxful?

Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn èèyàn mìíràn ní Zimbabwe láti rí Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó tó 60% lórí títa ẹyọ kọ̀ọ̀kan. Bẹ̀rẹ̀ títa pẹ̀lú àkántì báǹkì abẹ́lé rẹ báyìí, wo ìtọ́nisọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful yóò ní 1000's olùrajà Bitcoin láti Zimbabwe ní ojoojúmọ́.

Ṣẹda àkántì ki o bẹ̀rẹ̀ títà

Owó Àìlágùnjìnàfún

Ṣé o ma ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó fẹ́ ra Bitcoin ní Zimbabwe? Pẹlú Kíọ̀sì Bitcoin àti ètò Ìbánipolówó rẹ ìwọ yóò gba 2% lórí òwò kọ̀ọ̀kan títí láyé nípa pínpín ìtọ́kasí. Bẹ̀rẹ̀ Báyì.