Ra Bitcoin ní USA lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀!

Paxful, àkọ́kọ́ ní àgbáyé ibi ìtajà Bitcoin tó ń lo agbára àwọn ènìyàn, ti ṣetán láti ran ìwọ lọ́wọ́ pààrọ̀ USD rẹ sí BTC.

Gba BTC rẹ ní àwọn ìdíyelé tí wọ́n kéré jù lórí Paxful, níbití kò ti sí àwọn owósan kankan fún àwọn olùrajà. Mú ìnájà tó dára jù fún ọ láàrin ẹgbẹẹgbẹ̀rún tí wọ́n wà lọ́dọ̀ àwọn olùtajà wa tí wọ́n ní àkọsílẹ̀ rere kí ìwọ́ sì ní ìrírí ìdókoowò tó rọrùn d'ọ́ba pẹ̀lú àwọn ọ̀nà àtisanwó fún BTC rẹ tí wọ́n lé ní 300.

Lórí ìwọlé ìrọ̀rùn rẹ sí BTC, àwá ti ṣiṣẹ́ kára láti ṣ'èdá àwùjọ ìdókoòwò tó ní ààbò fún gbogbo àwọn aṣàmúlò wa. Àwọn olùtajà wa ní a ti ṣe àyẹ̀wò fún fínnífínní láti jẹ́ kí wọ́n pèsè àwọn ìnájà gidi fún ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ fi ọwọ́ rẹ ba BTC. Ṣe ìgbésẹ̀! Ṣ'èdá àkántì, gba wálẹ́ẹ́tì Bitcoin ọ̀fẹ́ rẹ, kí ìwọ́ le ra Bitcoin lónìí!

Àwọn ìnájà tí wọ́n lékè fún Dọ́là Amẹríkà ní United States (USA)

Olùtàjà Sanwó pẹ̀lú Tí ó kéré jù

láti san

láti san

Lórí dọ́là

EngineerMaina +16
Ti ríi ìsẹjú 16 kọjá
Zelle Pay Fast and reliable vendor
11.00 USD $1.12
kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ìsanwó orí ayélujára
SirMburu +357
Ti ríi wákati 3 kọjá
PayPal Youll love this
50.00 USD $0.89
paypal tí ó ti wà ní ìjẹ́rìísí nìkan
Debri +63
Ti ríi ìsẹjú 2 kọjá
PayPal fast release of coins
10.00 USD $0.89
àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Bhea1977 +136
Ti ríi wákati 1 kọjá
PayPal GET BTC HASSLEFREE
50.00 USD $0.89
ó nílò àwòrán ìdánimọ̀ kò sí àwọn ẹnìkẹta
Gatiba +151
Ti ríi ìsẹjú 12 kọjá
PayPal Fast Release
30.00 USD $0.89
àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Quincy234 +246
Ti ríi ìsẹjú 23 kọjá
PayPal Bitcoin for all
200.00 USD $0.89
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Rivers98 +528
Orí Ayélujára
PayPal Paypal opladen iDEAL
120.00 USD $0.89
AbuKoech +1445
Ti ríi ìsẹjú 21 kọjá
PayPal Instant release
20.00 USD $0.89
àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Kioge +262
Orí Ayélujára
Western Union Cash pick up available
10.00 USD $0.89
kò nílò ìjẹ́rìísí kò sí ìdúnadúra
Kioge +262
Orí Ayélujára
PayPal Friends And Family
10.00 USD $0.89
kò sí ìdúnadúra àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
PrettySwift726 +157
Ti ríi ìsẹjú 2 kọjá
PayPal Fast and reliable
20.00 USD $0.89
àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
GIDEON_MUTAI +839
Ti ríi wákati 7 kọjá
PayPal READY TO RELEASE NOW
20.00 USD $0.89
àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí Paxful 6
thoirem +106
Orí Ayélujára
PayPal instant release
10.00 USD $0.89
àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Mandenoo254 +51
Ti ríi wákati 18 kọjá
PayPal Family and friends
10.00 USD $0.89
kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ìsanwó orí ayélujára kò sí ìdúnadúra
Kugo +226
Orí Ayélujára
PayPal HONEST
20.00 USD $0.89
àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Wyleslangat +57
Orí Ayélujára
PayPal Instant release
25.00 USD $0.89
pogba254 +130
Ti ríi wákati 8 kọjá
PayPal
10.00 USD $0.89
Real_legend +160
Orí Ayélujára
PayPal Instant release
20.00 USD $0.89
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ìsanwó orí ayélujára
MominulHasan20 +357
Ti ríi wákati 1 kọjá
Western Union Hi
100.00 USD $0.89
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn ìsanwó orí ayélujára kò sí àwọn ẹnìkẹta
FastBITCON +219
Orí Ayélujára
PayPal Fast Release Rate Special
50.00 USD $0.89
kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí

Àwọn ìlànà ìsanwó tí wọ́n lékè ní United States (USA)

Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Zelle Pay

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Zelle Pay lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Zelle Pay

Western Union

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Western Union lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Western Union

PayPal

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú PayPal lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú PayPal

Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì

Káàdì Ẹ̀bùn Amazon

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.

Ṣé mo lè ta Bitcoin lórí Paxful?

Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn èèyàn mìíràn ní United States (USA) láti rí Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó tó 60% lórí títa ẹyọ kọ̀ọ̀kan. Bẹ̀rẹ̀ títa pẹ̀lú àkántì báǹkì abẹ́lé rẹ báyìí, wo ìtọ́nisọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful yóò ní 1000's olùrajà Bitcoin láti United States (USA) ní ojoojúmọ́.

Ṣẹda àkántì ki o bẹ̀rẹ̀ títà

Owó Àìlágùnjìnàfún

Ṣé o ma ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó fẹ́ ra Bitcoin ní United States (USA)? Pẹlú Kíọ̀sì Bitcoin àti ètò Ìbánipolówó rẹ ìwọ yóò gba 2% lórí òwò kọ̀ọ̀kan títí láyé nípa pínpín ìtọ́kasí. Bẹ̀rẹ̀ Báyì.