Ta Bitcoin lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ní Gúúsù Áfíríkà

Paxful, ibi ìtajà Bitcoin ẹnìkan-sí-ẹnìkejì tó ń ṣíwájú ní àgbáyé, ti wà ní South Africa ṣetán láti bá ìwọ pààrọ̀ owó Rand (ZAR) rẹ sí BTC ní ọ̀nà tó ní ààbò jù tó ṣeéṣe. South Africa jẹ́ àwùjọ Paxful tó ń yára gbòòrò. Ní oṣù tó lọ nìkan, ìwọn òwò ti gbéra lọ sí BTC tí iye rẹ̀ tó ó lé ní 2.5M. Wọlé síbi ìṣe náà nípasẹ̀ ṣíṣẹ̀dá àkántì àti gbígba wálẹ́ẹ̀tì Bitcoin ọ̀fẹ́ rẹ lónìí!

Àwá mú ààbò ní ọ̀kúnkúndùn ní Paxful, èyí tó mú kí a ṣètò ètò ààbò tó gbópọn láti dáàbò bo wálẹ́ẹ́tì rẹ lọ́wọ́ èyíkèyí àwọn ìpalára. A pèsè ìfàṣẹsí onígbẹ̀èsẹ̀-méjì gẹ́gẹ́ bíi àfikún ìpele ààbò àti ẹgbẹ́ ètò ìlò oníbàárà 24/7 tí ó ṣetán láti ran ìwọ lọ́wọ́ báyìí. Ìwọ́ lè ra Bitcoin ní àlàáfíà bí a ṣe ńṣe ìrànwọ́ àti tọ́jú owó rẹ àti ìṣọ́ rẹ̀.

Ṣé ìwọ́ sábà máa ńwà lórí-ìrìn? Kò sí wàhálà! Ṣe àkóso àwọn owó rẹ ní ibikíbi tí ìwọ́ bá wà lórí Andrọidi rẹ tàbí ẹ̀rọ iOS nípasẹ̀ gbígba áápù alágbèéká wa!

Àwọn ìnájà tí wọ́n lékè fún South African Rand ní Gúúsù Áfíríkà

Olùtàjà Sanwó pẹ̀lú Tí ó kéré jù

láti san

láti san

Lórí dọ́là

Rudco +348
Ti ríi ìsẹjú 2 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì FNBABSACAPITECTYME
149.00 ZAR $0.93
kò sí àwọn ẹnìkẹta Paxful 6
JovialCombfish745 +1
Orí Ayélujára
PayPal Instant realese
149.00 ZAR $0.91
àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
ShiidehM +74
Ti ríi ìsẹjú 27 kọjá
PayPal Instant reply and release
200.00 ZAR $0.80
àwọn ìsanwó orí ayélujára àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
kr254 +707
Orí Ayélujára
PayPal Fast and Reliable
300.00 ZAR $0.79
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn ìsanwó orí ayélujára àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
KAmericanah +181
Ti ríi wákati 1 kọjá
PayPal Instant Release
385.00 ZAR $0.79
àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Seundegs +785
Orí Ayélujára
WÁLẸ́Ẹ̀TÌ-AYÉLUJÁRA FNB FNB STB Nedbank Absa
400.00 ZAR $0.77
kò nílò ìjẹ́rìísí kò sí àwọn ẹnìkẹta Paxful 6
PoshQueen_V +962
Ti ríi ìsẹjú 40 kọjá
Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì STD bank n other facility
5,000.00 ZAR $0.77
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí ìdúnadúra
MaturePanther849 +151
Orí Ayélujára
Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì Standard banFNB EWALLET
200.00 ZAR $0.77
Calitoronoz +1047
Orí Ayélujára
PayPal Instant release
200.00 ZAR $0.77
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó kò nílò ìjẹ́rìísí
PoshQueen_V +962
Ti ríi ìsẹjú 40 kọjá
WÁLẸ́Ẹ̀TÌ-AYÉLUJÁRA FNB fnbstandardcapnedabsa
300.00 ZAR $0.77
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó
SammyB12345 +43
Ti ríi ìsẹjú 5 kọjá
WÁLẸ́Ẹ̀TÌ-AYÉLUJÁRA FNB
200.00 ZAR $0.65
prettyqueen888 +405
Ti ríi wákati 1 kọjá
PayPal release right away
431.00 ZAR $0.63
àwọn káàdì àfojúrí nìkan kò nílò ìjẹ́rìísí kò sí àwọn ẹnìkẹta
Chidic90 +159
Ti ríi ìsẹjú 3 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì First National Bank
200.00 ZAR $0.59
WHALESTAR +5
Orí Ayélujára
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Standard Bank
500.00 ZAR $0.95
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn ìsanwó orí ayélujára kò sí àwọn ẹnìkẹta
nkhensykhen +64
Orí Ayélujára
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì FNB
149.00 ZAR $0.92
kò sí àwọn ẹnìkẹta kò sí ìdúnadúra
Theo025 +84
Orí Ayélujára
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì FNB and Standard Bank
200.00 ZAR $0.92
kò sí àwọn ẹnìkẹta kò sí ìdúnadúra Paxful 6
KamogeloRallele +32
Ti ríi ìsẹjú 3 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì FNB
149.00 ZAR $0.91
kò sí àwọn ẹnìkẹta kò sí ìdúnadúra
Evans89 +312
Ti ríi wákati 4 kọjá
PayPal Release on withdrawal
300.00 ZAR $0.80
SuperBarbet333 +22
Ti ríi ìsẹjú 55 kọjá
Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì StandardBank Capitec
300.00 ZAR $0.84
kò sí àwọn ẹnìkẹta kò sí ìdúnadúra
LOYAL_BTC_NETWORK +153
Orí Ayélujára
PayPal Quick release
200.00 ZAR $0.81
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí

Àwọn ìlànà ìsanwó tí wọ́n lékè ní Gúúsù Áfíríkà

WÁLẸ́Ẹ̀TÌ-AYÉLUJÁRA FNB

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú WÁLẸ́Ẹ̀TÌ-AYÉLUJÁRA FNB lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú WÁLẸ́Ẹ̀TÌ-AYÉLUJÁRA FNB

Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì

PayPal

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú PayPal lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú PayPal

Perfect Money

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Perfect Money lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Perfect Money

Káàdì Ẹ̀bùn Amazon

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.

Ṣé mo lè ta Bitcoin lórí Paxful?

Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn èèyàn mìíràn ní Gúúsù Áfíríkà láti rí Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó tó 60% lórí títa ẹyọ kọ̀ọ̀kan. Bẹ̀rẹ̀ títa pẹ̀lú àkántì báǹkì abẹ́lé rẹ báyìí, wo ìtọ́nisọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful yóò ní 1000's olùrajà Bitcoin láti Gúúsù Áfíríkà ní ojoojúmọ́.

Ṣẹda àkántì ki o bẹ̀rẹ̀ títà

Owó Àìlágùnjìnàfún

Ṣé o ma ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó fẹ́ ra Bitcoin ní Gúúsù Áfíríkà? Pẹlú Kíọ̀sì Bitcoin àti ètò Ìbánipolówó rẹ ìwọ yóò gba 2% lórí òwò kọ̀ọ̀kan títí láyé nípa pínpín ìtọ́kasí. Bẹ̀rẹ̀ Báyì.