Ta Bitcoin lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ní Pakistan

Káàbọ̀ sí Paxful, ibi tó wà fún ìwọ láti pààrọ̀ owó Rupee ti Pakistan rẹ (PKR) sí BTC ní ọ̀nà ààbò tó ṣeéṣe jù. Ibi ìtajà Bitcoin ẹnìkan-sí-ẹnìkejì wa tó ń síwájú ti wà ní Pakistan, tí ó sì ṣetán àti ran ìwọ lọ́wọ́–bóyá fún àwọn ìrajà ojoojúmọ́, àwọn ìfiránṣẹ́ owó, tàbí ìtọ́jú ọrọ̀.

Ṣe àwárí ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn ìnájà tí wọ́n wà lórí ìkànnì wa kí ìwọ́ sì wá àwọn òwò tí wọ́n dára jù fún BTC—gbogbo rẹ̀ pẹ̀lú àwọn owósan olùrajà ọ̀fẹ́ àti àwọn ìlànà ìsanwó 300+. Àti pẹ̀lú àwọn ìlànà ààbò tí wọ́n gbópọn tí wọ́n wà nílẹ̀, ìwọ́ mọ̀ wípé owó rẹ wà ní ààbò.

Ṣ'èdá àkántì lónìí, gba wálẹ́ẹ̀tì Bitcoin ọ̀fẹ́ rẹ, ra BTC lọ́wọ́ ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn olùtajà wa tí wọ́n ṣé fọkàntán, kí o sì bẹ̀rẹ̀ ìrìnàjò kírípítò rẹ.

Àwọn ìnájà tí wọ́n lékè fún Pakistan Rupee ní Pakistan

Olùtàjà Sanwó pẹ̀lú Tí ó kéré jù

láti san

láti san

Lórí dọ́là

Abdullahshabbir +1028
Ti ríi wákati 2 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì All bank Accepted
10,000.00 PKR $0.91
àwọn ìsanwó orí ayélujára kò sí àwọn ẹnìkẹta
Beenish888 +157
Ti ríi wákati 2 kọjá
Easypaisa
2,000.00 PKR $0.62
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó
Irfan_Saleem +79
Ti ríi wákati 6 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Any Bank
1,700.00 PKR $0.91
MuhammadNadir08 +451
Ti ríi ìsẹjú 1 kọjá
Easypaisa Third party is allowed
1,700.00 PKR $0.51
kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ìsanwó orí ayélujára àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
MuhammadNadir08 +451
Ti ríi ìsẹjú 1 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Third party is allowed
2,000.00 PKR $0.52
kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ìsanwó orí ayélujára àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
FaraAyyaz4 +388
Ti ríi wákati 2 kọjá
Easypaisa For all real buyers
1,700.00 PKR $0.56
owó-àgbàsọ́wọ́ nìkan
younus2020 +195
Ti ríi wákati 5 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì bank all
1,700.00 PKR $0.59
ó ń gba àwọn kóòdù orí ẹ̀rọ ayélujára kò sí ìdúnadúra
FaraAyyaz4 +388
Ti ríi wákati 2 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Pakistani bank
1,700.00 PKR $0.59
owó-àgbàsọ́wọ́ nìkan
Mosaahmed +148
Ti ríi wákati 1 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Hbl
1,700.00 PKR $0.59
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn ìsanwó orí ayélujára
ZoyaPari +284
Ti ríi wákati 3 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì THIRDPARTY ACCEPTED
1,700.00 PKR $0.59
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn ìsanwó orí ayélujára
Adnanrana +162
Ti ríi ìsẹjú 46 kọjá
Easypaisa High trusted service
2,000.00 PKR $0.59
owó-àgbàsọ́wọ́ nìkan àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Adnanrana +162
Ti ríi ìsẹjú 46 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Any bank
1,700.00 PKR $0.62
kò sí àwọn ẹnìkẹta àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
Beenish888 +157
Ti ríi wákati 2 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì habib bank limited
2,000.00 PKR $0.65
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó
MUKTIAR540 +6
Ti ríi wákati 7 kọjá
Easypaisa Bannk
1,700.00 PKR $0.90
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó owó-àgbàsọ́wọ́ nìkan kò sí àwọn ẹnìkẹta
BFAREEDTRADER15 +28
Ti ríi wákati 4 kọjá
Easypaisa
2,000.00 PKR $0.69
owó-àgbàsọ́wọ́ nìkan àwọn ìsanwó orí ayélujára
Aurangzeb0237 +320
Ti ríi wákati 3 kọjá
Payoneer Pakistan
2,000.00 PKR $0.69
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó
irfanAli1758 +276
Ti ríi wákati 7 kọjá
Easypaisa Thirdparty payment acpted
1,700.00 PKR $0.69
àwọn ìsanwó orí ayélujára
Moonchohn24 +245
Ti ríi wákati 17 kọjá
Easypaisa Bitcoin
1,700.00 PKR $0.70
kò nílò ìjẹ́rìísí owó-àgbàsọ́wọ́ nìkan
Alizacoins +303
Ti ríi wákati 1 kọjá
Easypaisa Easypaisa
2,000.00 PKR $0.71
kò sí àwọn ẹnìkẹta
AASHIR_TRADER +282
Ti ríi wákati 2 kọjá
Payoneer Easypaisa jazz cash bank
1,700.00 PKR $0.71

Àwọn ìlànà ìsanwó tí wọ́n lékè ní Pakistan

Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Easypaisa

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Easypaisa lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Easypaisa

Skrill

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Skrill lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Skrill

Payoneer

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Payoneer lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Payoneer

PayPal

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú PayPal lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú PayPal

Káàdì Ẹ̀bùn Amazon

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.

Ṣé mo lè ta Bitcoin lórí Paxful?

Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn èèyàn mìíràn ní Pakistan láti rí Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó tó 60% lórí títa ẹyọ kọ̀ọ̀kan. Bẹ̀rẹ̀ títa pẹ̀lú àkántì báǹkì abẹ́lé rẹ báyìí, wo ìtọ́nisọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful yóò ní 1000's olùrajà Bitcoin láti Pakistan ní ojoojúmọ́.

Ṣẹda àkántì ki o bẹ̀rẹ̀ títà

Owó Àìlágùnjìnàfún

Ṣé o ma ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó fẹ́ ra Bitcoin ní Pakistan? Pẹlú Kíọ̀sì Bitcoin àti ètò Ìbánipolówó rẹ ìwọ yóò gba 2% lórí òwò kọ̀ọ̀kan títí láyé nípa pínpín ìtọ́kasí. Bẹ̀rẹ̀ Báyì.