Ta Bitcoin lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ní Mexico

Yi owó Peso ti Mexico rẹ (MXN) sí BTC lónìí lóri Paxful, ibi ìtajà Bitcoin ẹnìkan-sí-ẹnìkejì tó ń síwájú ní àgbáyé. Ríra BTC lórí Paxful jẹ́ ohun méjì: kò wọ́n lówó ó sì ní ààbò.

Pẹlú àwọn ìlànà ìsanwó tó ju 300 lọ ní àrọ́wọ́tó rẹ, ìwọ́ lè ra Bitcoin ní Mexico pẹ̀lú ó súnmọ́ ohunkóhun. Lórí ìyẹn, kò sí àwọn owósan fún ríra BTC. Ṣé ìwọ́ ti ríi? Ó rọjú!

A tún ní ẹ̀rọ ààbò tó gbópọn. Pẹ̀lú àjọṣepọ̀ wa pẹ̀lú àwọn ilé-iṣẹ́ ìyànnàná àkópọ̀ ìtẹ̀léra Kírípítò ńlá, ẹ̀rọ wa máa n ríi dájú wípé ibi ìtajà wa ní ààbò ó sì n lé àwọn èèyàn burúkú tán le pàdé rẹ dánú. Bẹ̀rẹ̀ lónìí! Ṣẹ̀dá àkántì, gba wálẹ́ẹ́tì Bitcoin ọ̀fẹ́ rẹ, kí ìwọ́ sì ṣ'òwò lọ!

Àwọn ìnájà tí wọ́n lékè fún Mexican Peso ní Mexico

Olùtàjà Sanwó pẹ̀lú Tí ó kéré jù

láti san

láti san

Lórí dọ́là

Generalmwalimu +14
Ti ríi wákati 1 kọjá
PayPal
313.00 MXN $0.83
Rodrigorz +411
Ti ríi wákati 5 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì ASP integra
5,000.00 MXN $0.87
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn ìsanwó orí ayélujára òwò tí o darí
Rashimillo +115
Ti ríi wákati 17 kọjá
PayPal Instant release
1,600.00 MXN $0.77
kò sí àwọn ẹnìkẹta kò sí ìdúnadúra
Aldec +356
Ti ríi wákati 6 kọjá
OXXO Libero al instante
900.00 MXN $0.79
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó
Aldec +356
Ti ríi wákati 6 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì BBVA Bancomer HSBC OXXO
1,000.00 MXN $0.80
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn ìsanwó orí ayélujára òwò tí o darí
Aldec +356
Ti ríi wákati 6 kọjá
Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì BANCOMER OXXO SPEI TRANSF
1,000.00 MXN $0.81
kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ìsanwó orí ayélujára
MichCripto +54
Ti ríi wákati 7 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì TODOS LOS BANCOS
400.00 MXN $0.85
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
MichCripto +54
Ti ríi wákati 7 kọjá
OXXO Fast Trade
400.00 MXN $0.85
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó
Nextwolf +916
Ti ríi ọjọ́ 1 kọjá
OXXO OXXO
1,000.00 MXN $0.86
owó-àgbàsọ́wọ́ nìkan kò sí àwọn ẹnìkẹta kò sí ìdúnadúra
Kryptoamigo +490
Ti ríi wákati 6 kọjá
Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì BANCOMER OXXO PRACTICAJA
1,000.00 MXN $0.86
kò nílò ìjẹ́rìísí
Nextwolf +916
Ti ríi ọjọ́ 1 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì BBVA Bancommer
1,000.00 MXN $0.88
kò sí àwọn ẹnìkẹta bánkì kannáà nìkan òwò tí o darí
Manny_Ke +134
Ti ríi ìsẹjú 39 kọjá
PayPal INMEDIATO LIBERACIÓN
1,400.00 MXN $0.81
àwọn ìsanwó orí ayélujára kò sí ìdúnadúra àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
PetitePika148 +445
Orí Ayélujára
PayPal Fast trade
7,000.00 MXN $0.52
àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
SheenPiapiac335 +32
Ti ríi ìsẹjú 40 kọjá
PayPal PayPal trader
209.00 MXN $0.55
kò sí ìdúnadúra
Ericeriggar +1721
Ti ríi ìsẹjú 6 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì BBVA Bancomer STP OXXO
1,000.00 MXN $0.59
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó òwò tí o darí
LawfulDorado768 +157
Orí Ayélujára
PayPal Fast
400.00 MXN $0.67
àwọn ọ̀rẹ́ àti ẹbí
prettyqueen520 +11
Ti ríi ìsẹjú 9 kọjá
PayPal release right away
2,057.00 MXN $0.67
CoinerMX +425
Ti ríi wákati 2 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Any Mexican Bank
1,000.00 MXN $0.80
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó àwọn ìsanwó orí ayélujára òwò tí o darí
CoinerMX +425
Ti ríi wákati 2 kọjá
OXXO Third party accepted
1,000.00 MXN $0.80
owó-àgbàsọ́wọ́ nìkan
CoinerMX +425
Ti ríi wákati 2 kọjá
Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì Third party accepted
1,000.00 MXN $0.80
owó-àgbàsọ́wọ́ nìkan

Àwọn ìlànà ìsanwó tí wọ́n lékè ní Mexico

Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

OXXO

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú OXXO lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú OXXO

PayPal

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú PayPal lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú PayPal

Káàdì Ẹ̀bùn Neosurf

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Neosurf lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Neosurf

Káàdì Ẹ̀bùn Amazon

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon

Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.

Ṣé mo lè ta Bitcoin lórí Paxful?

Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn èèyàn mìíràn ní Mexico láti rí Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó tó 60% lórí títa ẹyọ kọ̀ọ̀kan. Bẹ̀rẹ̀ títa pẹ̀lú àkántì báǹkì abẹ́lé rẹ báyìí, wo ìtọ́nisọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful yóò ní 1000's olùrajà Bitcoin láti Mexico ní ojoojúmọ́.

Ṣẹda àkántì ki o bẹ̀rẹ̀ títà

Owó Àìlágùnjìnàfún

Ṣé o ma ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó fẹ́ ra Bitcoin ní Mexico? Pẹlú Kíọ̀sì Bitcoin àti ètò Ìbánipolówó rẹ ìwọ yóò gba 2% lórí òwò kọ̀ọ̀kan títí láyé nípa pínpín ìtọ́kasí. Bẹ̀rẹ̀ Báyì.