Buy Bitcoin in Ethiopia

Dáàbò bo àwọn ohun ìní rẹ lọ́wọ́ ìgbówólórí nípasẹ̀ dídáàbò bo ọrọ̀ rẹ ní Bitcoin. Ní Paxful, ìwọ́ lè ṣe pàsípààrọ̀ owó Birr ti Ethiopia (ETB) rẹ fún BTC ní ìrọ̀rùn, bóyá lóri ẹ̀rọ kọ̀mpútà desktop tàbí gbati áápù wálẹ́ẹ́tì Paxful lóri iOS tàbí Andrọidi.

Ra Bitcoin lọ́wọ́ ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn olùtajà nínú àti ní ìta orílẹ̀-èdè kí ìwọ́ sì jẹ ìgbádùn àwọn òṣùwọ̀n BTC ìpínrọ̀ tàbí kéré sí ìdíyelé ìtajà lọ́wọ́lọ́wọ́. Ríra Bitcoin ní Ethiopia kò rọjú nìkan lóri Paxful, ó tún ní ìṣọ́. Àwá ti ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn ilé-iṣẹ́ ìṣọ́-ayélujára láti dáàbò bo wálẹ́ẹ́tì Bitcoin rẹ kí ìwọ́ sì ṣe ibi ìtajà ní mímọ́. Ìwọ́ lè f'ọkànbalẹ̀ wípé owó rẹ wà ní ààbò ìwọ́ sì ń ra Bitcoin lọ́wọ́ àwọn orísun tán ṣé fọkàntán.

Ṣẹ̀dá àkántì rẹ lónìí kí ìwọ́ sì dáàbò bo ọrọ̀ rẹ kúrò lọ́wọ́ jíjábọ́.

Àwọn ìnájà tí wọ́n lékè fún Ethiopian Birr ní Ethiopia

Olùtàjà Sanwó pẹ̀lú Tí ó kéré jù

láti san

láti san

Lórí dọ́là

ModestLoach262 +67
Ti ríi wákati 1 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì All banks
$1,000.00 ETB $$0.95
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
WizardBluebill741 +201
Ti ríi ìsẹjú 3 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì any bank
$570.00 ETB $$0.86
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
CozyArowana987 +210
Ti ríi wákati 8 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì dfgsda
$577.00 ETB $$0.86
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
MustTurbot648 +42
Ti ríi wákati 1 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì all
$600.00 ETB $$0.81
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
wanghui852 +641
Orí Ayélujára
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Ethiopia
$5,000.00 ETB $$0.81
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
Habib9999 +0
Ti ríi ìsẹjú 1 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì Cbe
$570.00 ETB $$0.73
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
SpruceDotterel440 +202
Ti ríi ìsẹjú 4 kọjá
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì all
$570.00 ETB $$0.73
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí
WireBoss666 +202
Orí Ayélujára
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì any bank
$5,000.00 ETB $$0.95
ó nílò ẹ̀rí ìsanwó kò sí àwọn ẹnìkẹta òwò tí o darí

Àwọn ìlànà ìsanwó tí wọ́n lékè ní Ethiopia

Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

PayPal

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú PayPal lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú PayPal

Skrill

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Skrill lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Skrill

ÈYÍKÉYÌ Káàdì kírẹ́dítì/Dẹ́bítì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú ÈYÍKÉYÌ Káàdì kírẹ́dítì/Dẹ́bítì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú ÈYÍKÉYÌ Káàdì kírẹ́dítì/Dẹ́bítì

Àwọn ohun nkan Eré

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Àwọn ohun nkan Eré lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Àwọn ohun nkan Eré

Káàdì Ẹ̀bùn Amẹ́ríkà Express

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amẹ́ríkà Express lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amẹ́ríkà Express

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.

Ṣé mo lè ta Bitcoin lórí Paxful?

Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn èèyàn mìíràn ní Ethiopia láti rí Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó tó 60% lórí títa ẹyọ kọ̀ọ̀kan. Bẹ̀rẹ̀ títa pẹ̀lú àkántì báǹkì abẹ́lé rẹ báyìí, wo ìtọ́nisọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful yóò ní 1000's olùrajà Bitcoin láti Ethiopia ní ojoojúmọ́.

Ṣẹda àkántì ki o bẹ̀rẹ̀ títà

Owó Àìlágùnjìnàfún

Ṣé o ma ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó fẹ́ ra Bitcoin ní Ethiopia? Pẹlú Kíọ̀sì Bitcoin àti ètò Ìbánipolówó rẹ ìwọ yóò gba 2% lórí òwò kọ̀ọ̀kan títí láyé nípa pínpín ìtọ́kasí. Bẹ̀rẹ̀ Báyì.