Ta Bitcoin lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ní Cape Verde

Paxful ni ibi tí ó dára jù láti ra Bitcoin lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ pẹ̀lú èyíkèyí ìlànà ìsanwó. Nísín o le dókòwò Bitcoin rẹ sí èyíkèyí ìlànà ìsanwó ní ọ̀nà tó yá, rọrùn tí ó ṣì ní ààbò tí Paxful pèsè.

Kó owó s'óri Bitcoin ní ìrọ̀rùn àti ààbò. Paxful nibi to dára jù láti ra, ta àti fi ránṣẹ́ pẹ̀lu ó lé ní ọ̀nà 300 láti sanwó fún Bitcoin pẹ̀lú ìfiránṣẹ́ nípaṣẹ̀ ilé ìfowópamọ́, káàdì ẹ̀bùn, Paypal, Western Union, Moneygram, àwọn káàdì ìsanwó/ìpawó rẹ àti bẹ́ẹ̀ lọ!

Àwọn ìnájà tí wọ́n lékè fún Cape Verdean Escudo ní Cape Verde

Olùtàjà Sanwó pẹ̀lú Tí ó kéré jù

láti san

láti san

Lórí dọ́là

Miatan254 +153
Ti ríi wákati 1 kọjá
Western Union Mobile wallet
$1,057.00 CVE $$0.85
kò nílò ẹ̀rí ìsanwó kò nílò ìjẹ́rìísí
JosephNduati +443
Ti ríi ìsẹjú 15 kọjá
Western Union To mpesa cashpick or bank
$20,000.00 CVE $$0.75
kò nílò ìjẹ́rìísí
JosephNduati +443
Ti ríi ìsẹjú 15 kọjá
MoneyGram To mpesa cashpick or bank
$30,000.00 CVE $$0.75
kò nílò ìjẹ́rìísí

Àwọn ìlànà ìsanwó tí wọ́n lékè ní Cape Verde

Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

PayPal

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú PayPal lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú PayPal

ÈYÍKÉYÌ Káàdì kírẹ́dítì/Dẹ́bítì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú ÈYÍKÉYÌ Káàdì kírẹ́dítì/Dẹ́bítì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú ÈYÍKÉYÌ Káàdì kírẹ́dítì/Dẹ́bítì

GCash

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú GCash lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú GCash

Káàdì Ẹ̀bùn Wálẹ́ẹ̀tì Steam

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Wálẹ́ẹ̀tì Steam lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Wálẹ́ẹ̀tì Steam

Káàdì Ẹ̀bùn Amazon

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.

Ṣé mo lè ta Bitcoin lórí Paxful?

Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn èèyàn mìíràn ní Cape Verde láti rí Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó tó 60% lórí títa ẹyọ kọ̀ọ̀kan. Bẹ̀rẹ̀ títa pẹ̀lú àkántì báǹkì abẹ́lé rẹ báyìí, wo ìtọ́nisọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful yóò ní 1000's olùrajà Bitcoin láti Cape Verde ní ojoojúmọ́.

Ṣẹda àkántì ki o bẹ̀rẹ̀ títà

Owó Àìlágùnjìnàfún

Ṣé o ma ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó fẹ́ ra Bitcoin ní Cape Verde? Pẹlú Kíọ̀sì Bitcoin àti ètò Ìbánipolówó rẹ ìwọ yóò gba 2% lórí òwò kọ̀ọ̀kan títí láyé nípa pínpín ìtọ́kasí. Bẹ̀rẹ̀ Báyì.