Pààrọ owó Riel ti Cambodia (KHR) rẹ sí BTC ní ààbò nípasẹ̀ lílo Paxful, ọ̀kan lára àwọn aṣíwájú àwọn ibi ìtajà Bitcoin ní àgbáyé tó ń lo agbára àwọn ènìyàn—ti wà ní Cambodia.
Paxful has a strong security system in place and KYC (know your customer) policies in place, helping you feel at ease when you buy BTC. We pride ourselves in giving you ultimate flexibility as there are over 450 payment methods available for you to use, allowing you to buy BTC on your terms.
Kíni ìwọ́ n dúró dé? Bẹ̀rẹ̀ nísín! Ṣẹ̀dá àkántì, gba wálẹ́ẹ́tì Bitcoin rẹ, kí ìwọ́ sì dókoòwò Bitcoin lóri ẹ̀rọ àgbékalẹ̀ tàbí alágbèéká rẹ lónìí!
Olùtàjà | Sanwó pẹ̀lú | Tó kéré jù — Iye tó pọ̀ jùlọ |
Tí ó kéré jù
láti san |
láti san
Lórí dọ́là |
Òṣùwọn fún Bitcoin ẹyọkọ̀ọ̀kan
Ìwọ́ lè ra èyíkèyí ìdá |
|
---|---|---|---|---|---|---|
BLACKPINKLisa
+5
Ti ríi wákati 1 kọjá |
Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì — All banks in Cambodia |
$41,500.00-$730,618.00 KHR | $41,500.00 KHR | $$0.81 Rà | Rà | |
ClearStarrySky03
+211
Ti ríi ìsẹjú 15 kọjá |
Western Union — Secured and reliable |
$1,000,000.00-$5,765,797.00 KHR | $1,000,000.00 KHR | $$0.77 Rà | Rà | |
Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì lónì.
Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú PayPal lónì.
Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú ÈYÍKÉYÌ Káàdì kírẹ́dítì/Dẹ́bítì lónì.
Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Payeer lónì.
Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowósórí Ẹ̀rọ-alágbèéká lónì.
Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon lónì.
Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.
Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.
Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn èèyàn mìíràn ní Cambodia láti rí Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó tó 60% lórí títa ẹyọ kọ̀ọ̀kan. Bẹ̀rẹ̀ títa pẹ̀lú àkántì báǹkì abẹ́lé rẹ báyìí, wo ìtọ́nisọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful yóò ní 1000's olùrajà Bitcoin láti Cambodia ní ojoojúmọ́.
Ṣé o ma ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó fẹ́ ra Bitcoin ní Cambodia? Pẹlú Kíọ̀sì Bitcoin àti ètò Ìbánipolówó rẹ ìwọ yóò gba 2% lórí òwò kọ̀ọ̀kan títí láyé nípa pínpín ìtọ́kasí. Bẹ̀rẹ̀ Báyì.