Ta Bitcoin lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ní Afghanistan

Pààrọ owó Afghani ti Afghanistan (AFN) rẹ sí BTC lónìí nípasẹ̀ lílo Paxful, ibi ìtajà Bitcoin ti agbára-ènìyàn tó ń ṣíwájú ní àgbáyé. Yàtọ̀ sí àwọn pàsípààrọ̀ Bitcoin ti ìbílẹ̀, a ti múu ṣeéṣe fún ìwọ láti ra BTC lábẹ́ ìdíyelé ìtajà lọ́wọ́lọ́wọ́ láì sí àwọn owósan àfikún.

Dídáàbò bo owó rẹ ni àwá yàn láàyò ìyẹn ló sì fi jẹ́ wípé àkántì rẹ wà ní ààbò pẹ̀lú àwọn ìlànà ààbò tán gbópọn bíi ìfàṣẹsí onígbẹ̀èsẹ̀-2. Gbati àwọn àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Chainalysis àti Group-IB, ìwọ́ lè fi ẹ̀mí rẹ balẹ̀ nígbàtí ìwọ́ mọ̀ wípé Paxful jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìkànnì tán ní ààbò jù láti ra Bitcoin.

Fún ìdí èyí, má jáfàra kí ìwọ́ sì ṣẹ́dá àkántì lórí Paxful. Mú lára àwọn ìnájà Bitcoin àìmọye kí ìwọ́ sì bẹ̀rẹ̀ ìdókoowò tí kò ní wàhálà nísín láti orí kọǹpútà àgbékalẹ̀, kọǹpútà alágbèéká, iOS, tàbí ẹ̀rọ Andrọidi!

Àwọn ìnájà tí wọ́n lékè fún Afghan Afghani ní Afghanistan

Olùtàjà Sanwó pẹ̀lú Tí ó kéré jù

láti san

láti san

Lórí dọ́là

LegitDaily +4
Ti ríi ìsẹjú 1 kọjá
PayPal Instant release
5,000.00 AFN $0.84
kò nílò ìjẹ́rìísí àwọn ìsanwó orí ayélujára kò sí àwọn ẹnìkẹta

Àwọn ìlànà ìsanwó tí wọ́n lékè ní Afghanistan

Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

PayPal

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú PayPal lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú PayPal

Western Union

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Western Union lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Western Union

ÈYÍKÉYÌ Káàdì kírẹ́dítì/Dẹ́bítì

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú ÈYÍKÉYÌ Káàdì kírẹ́dítì/Dẹ́bítì lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú ÈYÍKÉYÌ Káàdì kírẹ́dítì/Dẹ́bítì

Ìfowóránṣẹ́ orí Wáyà Àgbáyé (SWIFT)

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ orí Wáyà Àgbáyé (SWIFT) lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Ìfowóránṣẹ́ orí Wáyà Àgbáyé (SWIFT)

Payoneer

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú Payoneer lónì.

Ra Bitcoin pẹ̀lú Payoneer

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.

Ṣé mo lè ta Bitcoin lórí Paxful?

Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn èèyàn mìíràn ní Afghanistan láti rí Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó tó 60% lórí títa ẹyọ kọ̀ọ̀kan. Bẹ̀rẹ̀ títa pẹ̀lú àkántì báǹkì abẹ́lé rẹ báyìí, wo ìtọ́nisọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful yóò ní 1000's olùrajà Bitcoin láti Afghanistan ní ojoojúmọ́.

Ṣẹda àkántì ki o bẹ̀rẹ̀ títà

Owó Àìlágùnjìnàfún

Ṣé o ma ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó fẹ́ ra Bitcoin ní Afghanistan? Pẹlú Kíọ̀sì Bitcoin àti ètò Ìbánipolówó rẹ ìwọ yóò gba 2% lórí òwò kọ̀ọ̀kan títí láyé nípa pínpín ìtọ́kasí. Bẹ̀rẹ̀ Báyì.