Jọwọ dúró lákòkò tí à ń wá àwọn ìnájà tí ó dára jùlọ fún ọ.

Buy from

Sanwó pẹ̀lú

Price per Tether

Bíí ó ṣe Le Ra Tether lórí Paxful

Àwọn ìfọkansí Paxful ni láti jẹ kí àwọn iṣẹ ìṣúnádé ọdọ mílíọnù àwọn ènìyàn tí kò ní báǹkì káríayé. A fún ọ ní òmìnira láti ṣe pàṣípààrọ owó rẹ fún Tether (USDT) àti lò bí o ti ríí pé o yẹ; jẹ fún sísanwó fún àwọn ẹrù àti àwọn iṣẹ, ààbò àwọn ohun-ìní rẹ lòdì sí àfikún, rírà àwọn Kọ́rẹ́ńsì Onídíjítà, tàbí láti dáàbòbò lòdì sí ìyípadà owó ti àwọn Kọ́rẹ́ńsì-kírípítò.

Lórí Ibi Ìtajà ènìyàn-lagbára ti Paxful, o lè ra Tether tààrà láti ọdọ àwọn aṣàmúlò ẹlẹgbẹ bíí ìwọ láti gbogbo àgbáyé. Kò sí àwọn báǹkì, àwọn ilé-iṣẹ, tàbí àwọn alágbàtà mííràn tí o kópa.

Èyí ni bí o ṣe lè bẹ̀rẹ̀:

  1. Ṣẹdá àkántì kan tàbí wọlé sí ọkan ti o wà tẹlẹ. Wíwọlé lórí Paxful wá pẹlú wálẹ́ẹ̀tì ọfẹ kan níbi tí o lè fi USDT rẹ pamọ sí.
  2. Yan ìlànà ìsanwó, tẹ iye tí o fẹ ná nínú kọ́rẹ́ńsì tí o fẹ jùlọ, lẹhìnna lu Wá àwọn ìnájà.
  3. Lọ sórí ìnájà kọọkan kí o ṣe àtúnyẹwò àwọn àdehùn àti Kání. Máa fi ọkàn bá àwọn òṣùwọn ti àwọn olùtajà náà ṣètò lọ, àti àwọn èsì ìgbayìsí wọn àti àwọn ìjábọ̀ láti wọn ìgbẹ́kẹ̀lé wọn.
  4. Ní kété tí o bá ríí ìnájà kan tí ó bá àwọn ìbéèrè rẹ mu dáradára, jẹ́rìsí iye tí ìwọ yóò san kí o bẹ̀rẹ̀ òwò náà. Èyí yóò ṣíí ìtàkurọ̀sọ ojutaye níbití o lè ṣe ìbásọ̀rọ̀ pẹlú olùtajà ní àkókò ti o ń ṣẹlẹ̀.
  5. Lákòkó òwò, olùtajà yóò pèsè àwọn àlàyé síwájú sií lórí bíí o ṣe lè tẹsíwájú. Tẹlé àwọn ìtọ́nísọ́nà wọn dáradára kí o jẹ́rìsí ìdúnàádúrà ní kété tí o bá ti sanwo náà.
  6. Ní kété tí olùtajà náà fìdí owó sísan múlẹ, wọn yóò fi USDT rẹ sílẹ tí o wáyé láìléwu nínú ẹsíkírò wa, tààrà sínú wálẹ́ẹ̀tì Paxful Tether rẹ.

Lọ́gán tí o bá ti parí òwò, o lè lo aṣẹ́kú owó Tether rẹ lórí ohunkóhun tí o fẹ, tàbí gbé sí wálẹ́ẹ̀tì mííràn.

Pẹlú àwọn ìlànà ìsanwó tí ó ju 300 lọ láti sanwó pẹlú owó, àwọn ìfiránṣẹ́ báǹkì, àti àwọn káàdì ẹ̀bùn, ríra USDT kò rọrùn rárá. O kò rí ìlànà ìsanwó tí o fẹ jùlọ? Jẹ kí a mọ àti pé a yóò gbìyànjù láti ṣàfikún rẹ lórí ìkànnì wa. Fún àlàyé diẹ síí, ṣàyẹwò Ibi àmúsọgbọ́n wa tàbí kàn sí ẹgbẹ àtìlẹyìn wa.