Buy from
Sanwó pẹ̀lú
Price per Tether
Bíí ó ṣe Le Ra Tether lórí Paxful
Àwọn ìfọkansí Paxful ni láti jẹ kí àwọn iṣẹ ìṣúnádé ọdọ mílíọnù àwọn ènìyàn tí kò ní báǹkì káríayé. A fún ọ ní òmìnira láti ṣe pàṣípààrọ owó rẹ fún Tether (USDT) àti lò bí o ti ríí pé o yẹ; jẹ fún sísanwó fún àwọn ẹrù àti àwọn iṣẹ, ààbò àwọn ohun-ìní rẹ lòdì sí àfikún, rírà àwọn Kọ́rẹ́ńsì Onídíjítà, tàbí láti dáàbòbò lòdì sí ìyípadà owó ti àwọn Kọ́rẹ́ńsì-kírípítò.
Lórí Ibi Ìtajà ènìyàn-lagbára ti Paxful, o lè ra Tether tààrà láti ọdọ àwọn aṣàmúlò ẹlẹgbẹ bíí ìwọ láti gbogbo àgbáyé. Kò sí àwọn báǹkì, àwọn ilé-iṣẹ, tàbí àwọn alágbàtà mííràn tí o kópa.
Èyí ni bí o ṣe lè bẹ̀rẹ̀:
- Ṣẹdá àkántì kan tàbí wọlé sí ọkan ti o wà tẹlẹ. Wíwọlé lórí Paxful wá pẹlú wálẹ́ẹ̀tì ọfẹ kan níbi tí o lè fi USDT rẹ pamọ sí.
- Yan ìlànà ìsanwó, tẹ iye tí o fẹ ná nínú kọ́rẹ́ńsì tí o fẹ jùlọ, lẹhìnna lu Wá àwọn ìnájà.
- Lọ sórí ìnájà kọọkan kí o ṣe àtúnyẹwò àwọn àdehùn àti Kání. Máa fi ọkàn bá àwọn òṣùwọn ti àwọn olùtajà náà ṣètò lọ, àti àwọn èsì ìgbayìsí wọn àti àwọn ìjábọ̀ láti wọn ìgbẹ́kẹ̀lé wọn.
- Ní kété tí o bá ríí ìnájà kan tí ó bá àwọn ìbéèrè rẹ mu dáradára, jẹ́rìsí iye tí ìwọ yóò san kí o bẹ̀rẹ̀ òwò náà. Èyí yóò ṣíí ìtàkurọ̀sọ ojutaye níbití o lè ṣe ìbásọ̀rọ̀ pẹlú olùtajà ní àkókò ti o ń ṣẹlẹ̀.
- Lákòkó òwò, olùtajà yóò pèsè àwọn àlàyé síwájú sií lórí bíí o ṣe lè tẹsíwájú. Tẹlé àwọn ìtọ́nísọ́nà wọn dáradára kí o jẹ́rìsí ìdúnàádúrà ní kété tí o bá ti sanwo náà.
- Ní kété tí olùtajà náà fìdí owó sísan múlẹ, wọn yóò fi USDT rẹ sílẹ tí o wáyé láìléwu nínú ẹsíkírò wa, tààrà sínú wálẹ́ẹ̀tì Paxful Tether rẹ.
Lọ́gán tí o bá ti parí òwò, o lè lo aṣẹ́kú owó Tether rẹ lórí ohunkóhun tí o fẹ, tàbí gbé sí wálẹ́ẹ̀tì mííràn.
Pẹlú àwọn ìlànà ìsanwó tí ó ju 300 lọ láti sanwó pẹlú owó, àwọn ìfiránṣẹ́ báǹkì, àti àwọn káàdì ẹ̀bùn, ríra USDT kò rọrùn rárá. O kò rí ìlànà ìsanwó tí o fẹ jùlọ? Jẹ kí a mọ àti pé a yóò gbìyànjù láti ṣàfikún rẹ lórí ìkànnì wa. Fún àlàyé diẹ síí, ṣàyẹwò Ibi àmúsọgbọ́n wa tàbí kàn sí ẹgbẹ àtìlẹyìn wa.