Ra àti ta Bitcoin (BTC) ní Nàìjíríà

Dáàbòbò owó rẹ láti Náírà tí o ṣubú àti ààbò kọ́rẹ́ńsì rẹ ní Bitcoin. Ra Bitcoin pẹlú èyíkèyí àṣàyàn ìsanwó pẹlú Káàdì Ẹ̀bùn Amazon, Káàdì Ẹ̀bùn iTunes àti Ìfiránṣẹ́ Báǹkì!

Ju 1000 Bitcoin ní o ti jẹ́ títà ní Nàìjíríà!

Wo àtúngbéyẹ̀wò ẹ̀kọ́ wa bí o ṣe rọọrùn láti ra Bitcoin

Kà síwájú

Ra Bitcoin báyì

Ra Bitcoin pẹ̀lú

  • Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì
  • Owó Alágbèéká MTN
  • Owó Chipper
  • Perfect Money
    Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀—O lè nílò ìdánimọ̀
  • Àsansílẹ̀ owó sí báǹkì
    Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀—Owó ọjà tí o dárajù

1. Yan ọnà láti sanwó láti apá òsì

1. Yan ọnà láti sanwó láti òkè

Yàn láti àwọn ìlànà ìsanwó ti ó ń léwájú ní Naijiria. Tàbí wa èyíkèyí ìlànà ìsanwó mííràn láti yíyàn ní ìsàlẹ àwọn ìlànà tó ń léwájú.

2. Tẹ iye rẹ sí

2,000,000+
Wálẹ́ẹ̀tì Paxful
6,000,000+
Àwọn oníbàárà aláyọ̀
12,000+
Àwọn ìnájà tí ó ṣéé gbẹ́kẹ̀lé

O lè ra Bitcoin ní àwọn ọnà púpọ

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà ẹnìkan sí ẹnìkejì Bitcoin sísopọ àwọn olùrajà pẹlú àwọn olùtajà. Kàn yan bí o ṣe fẹ sanwó ati tẹ iye Bitcoin tí o nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.

Ṣé mo lè ta Bitcoin lórí Paxful?

Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn ọmọ Nàíjírìa láti ní Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó tó60% lórí títa ẹyọ kọọkan. Bẹ̀rẹ̀ títa pẹ̀lú àwọn àkántì báǹkì Nàìjíríà rẹ báyì, wo ìtọ́sọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful ń ní ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ 1000 àwọn olùrajà Bitcoin láti Nàìjíríà ní ojoojúmọ́.

Ṣẹda àkántì ki o bẹ̀rẹ̀ títà

Owó Àìlágùnjìnàfún

Ṣé o mọ àwọn ènìyàn tí ó fẹ ra Bitcoin ní Nigeria? Pẹlú Kíọ́sì Bitcoin àti ètò Ẹnìkejì rẹ ìwọ yóò gba2% lórí òwò kọọkan láilái nípa pínpin ọnà àsopọ kan. Bẹ̀rẹ̀ Báyì.

Ìtumọ̀ Bitcoin?

Bitcoin jẹ dúkìá onídíjítà àti ìlànà ìsanwó. Paxful jẹ kí o rọrùn láti yí àwọn káàdì ẹ̀bùn rẹ padà sí Bitcoin àti jáde kúrò ní Bitcoin. Bitcoin ti di dúkìá iyebíye ní àgbáyé onidijita wa. O lè ronú rẹ bí ẹyà ayélujára ti wúrà. Bíí góòlù, owó Bitcoin ti ń lọ sílẹsókè àti pé a nírètí láti rí ìdàgbásókè díẹ̀díẹ̀ owó Bitcoin, pàápàá nígbàtí àwọn àkókò ètò-ọrọ ajé bá jẹ ẹlẹgẹ.

Lẹ́yìn gbígba Bitcoin o lè ṣe ohunkohun ti o fẹ. O ní àṣàyàn láti mú wọn nínú wálẹ́ẹ̀tì Paxful rẹ, ta Bitcoin fún awọn dọlà AMẸRÍKÀ tàbí èyíkèyí owó mííràn. O tún lè fi Bitcoin rẹ ránṣẹ sí èyíkèyí wálẹ́ẹ̀tì Bitcoin mííràn.

Níbo ni a ti lè ná Bitcoin?

Láti wo àtòkọ ńlá ti àwọn Olùtajà lórí ayélujára ti ó gba Bitcoin lọ si https://spendabit.co/merchants.

Ná Bitcoin nípasẹ àwọn ànfàní rẹ

Bitcoin nínú àwọn ìròyìn

Ibi Ìtajà Bitcoin tutun fojúsí Nàìjíríà lára
http://www.itwebafrica.com/home-page/e-commerce/700-nigeria/237389-new-bitcoin-marketplace-focuses-on-nigeria

Rira àti tità Bitcoin nípasẹ Paxful rọrùn
http://www.newsbtc.com/2016/09/21/buying-and-selling-bitcoins-made-easy-by-paxful/

Àwọn ìṣòwò ńlá ń gba Bitcoin