Ra àti ta Bitcoin (BTC) ní China

Kó owó s'óri Bitcoin ní ìrọ̀rùn pẹ̀lú ààbò. Paxful nibi to dára jù láti ra, ta àti fi Bitcoin ránṣẹ́ pẹ̀lu ọ́nà t'ó lé ní 300 láti sanwó fún Bitcoin pẹ̀lú ìfiránṣẹ́ nípaṣẹ̀ ilé ìfowópamọ́ àti WeChat Pay!

Kà síwájú

Ra Bitcoin nísín

Padà sí èdè Sinko (简体中文(SC))

Ra Bitcoin pẹ̀lú

 • Ìfowóránṣẹ́ Báǹkì
 • Ìsanwó WeChat
  Owó ọjà tí o dárajù—O lè nílò ìdánimọ̀
 • PayPal
  Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀—O nílò ìdánimọ̀
 • Payoneer
  Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀—O lè nílò ìdánimọ̀
 • Litecoin LTC

1. Yan ọnà láti sanwó láti apá òsì

Yàn láti àwọn ìlànà ìsanwó tí wọ́n léwájú ní China. Tàbí wa èyíkèyí ọ̀nà ìsanwó mííràn láti yíyàn ní ìsàlẹ àwọn ìlànà tí wọ́n léwájú.

2. Tẹ iye láti ná

2,000,000+
Wálẹ́ẹ̀tì Paxful
6,000,000+
Àwọn oníbàárà aláyọ̀
12,000+
Àwọn ìnájà tí ó ṣéé gbẹ́kẹ̀lé

O lè ra Bitcoin ní àwọn ọnà púpọ

Kíni Paxful?

Paxful jẹ ibi Ìtajà Bitcoin ẹnìkan sí ẹnìkejì tó ń so àwọn olùrajà papọ̀ pẹ̀lú àwọn olùtajà. Kàn yan bí ìwọ́ ṣe fẹ́ sanwó kí o sì tẹ iye Bitcoin tí ìwọ́ nílò.

Ìṣe wa ni láti fún àwọn ènìyán tí ń ṣiṣẹ ní ìkànnì tí o rọrùn, àìrẹ́nijẹ àti ààbò fún ìdókowò iye iṣẹ wọn. Nígbàgbogbo àwọn ìṣòrò wa tí o tóbi jùlọ wà ní àyíká owó, gbígbà àti gbígbé lọ rẹ . A farajìn fún ṣíṣí agbára ti àwọn ènìyàn nípa ṣíṣẹ̀dá ìkànnì ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì ti àgbáyé fún ọjọ iwájú. Paxful jẹ PayPal + Uber àti àwọn ènìyàn Wall Street.

Ṣé mo lè ta Bitcoin lórí Paxful?

Ṣe ìrànlọwọ fún àwọn ará China láti ní Bitcoin àti pé o lè jèèrè GIDI tí ó 60% lórí títa ẹyọ kọ̀ọ̀kan. Bẹ̀ẹ̀rẹ títà pẹ̀lú àwọn àkántì Ìsanwó WeChat rẹ tàbí àkántí bánkì Chinese ní báyìí! Wo ìtọ́sọ́nà ọ̀fẹ́ wa. Paxful yóò ní 1000's olùrajà Bitcoin láti China ní ojoojúmọ́.

Ṣẹda àkántì ki o bẹ̀rẹ̀ títà

Owó Àìlágùnjìnàfún

Ṣé o mọ èèyàn púpọ̀ tí wọ́n fẹ́ ra Bitcoin ní China? Pẹ̀lu Kíọ́sì Bitcoin rẹ àti ètò Alábáṣepọ̀ ọ yóò gba 2% lórí òwò kọ̀ọ̀kan títí láyé nípa kí o kàn pín línkì. Bẹ̀ẹ̀rẹ̀ nísín.

Kínlódé tó jẹ́ Bitcoin?

Bitcoin jẹ dúkìá onídíjítà àti ìlànà ìsanwó. Paxful jẹ kí o rọrùn láti rà àti tà Bitcoin WeChat Pay, ìfiránṣẹ́ nípaṣẹ̀ ilé ìfowópamọ́ àti káàdì ẹ̀bùn. Bitcoin ti di dúkìá iyebíye ní ayé onidijita wa. O lè ronú rẹ bí ẹyà wúrà ayélujára. Bíí góòlù, owó Bitcoin ti ń lọ sílẹsókè àti pé a nírètí láti rí ìdàgbásókè díẹ̀díẹ̀ owó Bitcoin, pàápàá nígbàtí àwọn àkókò ètò ọrọ ajé bá jẹ ẹlẹgẹ.

Lẹ́yìn gbígba Bitcoin o lè ṣe ohunkohun ti o fẹ. O ní àṣàyàn láti fi wọ́n kalẹ̀ sí inú wálẹ́ẹ̀tì Paxful rẹ, ta Bitcoin fún awọn dọlà US tàbí èyíkèyí owó mííràn. O tún lè fi Bitcoin rẹ ránṣẹ́ sí èyíkèyí wálẹ́ẹ̀tì Bitcoin mííràn.

Níbo ni a tì lé ná Bitcoin?

Láti wo àtòkọ ńlá ti àwọn Olùtajà tí wọ́n n gba Bitcoin lọ si https://spendabit.co/merchants.

Ná Bitcoin nípasẹ̀ àwọn ànfààní rẹ

Bitcoin nínú àwọn ìròyìnÀwọn ìṣòwò ńlá ń gba Bitcoin