Jọwọ dúró lákòkò tí à ń wá àwọn ìnájà tí ó dára jùlọ fún ọ.

Buy from

Sanwó pẹ̀lú

Price per Bitcoin

Bí o ṣe lè ra Bitcoin pẹ̀lú Revolut

Àwọn alábáárà tí wọ́n ju míllíọ̀nù 2 lọ ni wọ́n lo Revolut ó sì pèsè ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn iṣẹ́ ìfowópamọ́, pẹ̀lú àwọn ìfiránṣẹ́ owó káríayé àti àwọn ìsanwó ẹnìkan-sí-ẹnìkejì. Báyìí, o lè lo Revolut láti ra Bitcoin lóri Paxful láìsí àwọn owósan àfikún. Èyí ni bí ó ṣe jẹ́:

Ohun àkọ́kọ́ tí o nílò láti ṣe ni kí o wọlé sí àkántì Paxful rẹ tàbí ṣẹ̀dá ọ̀kan nípa títẹ Ṣẹ̀dá àkántì . Lẹ́yìn tí o bá parí ìlànà ìjẹ́rìísí àkántì, tẹ Ra Bitcoin ṣètò Revolut bíi ìlànà ìsanwó tí o yàn láàyò láti wo àwọn ìnájà tí ó yẹ. Àwọn ìnájà tí wọ́n dára jùlọ wá láti ọ̀dọ̀ àwọn olùtajà tí wọ́n gbayì ọ̀nà kan láti wá wọn sì ni láti wo asàpèjúwe olùtajà náà pẹ̀lú àwọn ìjábọ̀ tó gbayì tí ó ga jùlọ. Kàn tẹ orúkọ olùtajà láti wo ìtàn òwò wọn àti àwọn àtúnyẹwò láti ọ̀dọ̀ àwọn olùbádòwòpọ̀ wọn.

Lọ́gán tí o bá rí ìnájà tí o fẹ́ láti ọ̀dọ̀ olùtajà tó ṣeé fọkàntán, tẹ láti wo àwọn ìbéèrè òwò wọn. Ka àwọn àlàálẹ̀ òwò náà fínnífínní kí o tẹ̀lé wọn dé ìparí. Tẹ bọ́tìnnì "Gba Àwọn Àdéhùn kí o sì Ra Bitcoins Báyìí!" tí o bá fẹ́ àwọn àdéhùn ìnájà náà. Àpótí ìtàkurọ̀sọ ààyè yóò hàn ní ibití o ti lè ní ìbásọ̀rọ̀ pẹ̀lú olùtajà kí o sì bèrè bóyá wọ́n ní àwọn ìbéèrè mííràn.

Ṣe àkíyèsí pé Paxful ńlo ètò ẹ́síkírò láti ti BTC olùtajà lọ́gán tí òwò bá ti bẹ̀rẹ̀ —nítorínáà owó rẹ ní ààbò.

Lọ́gán tí o bá fi ìsanwó ránṣẹ́ sí àkántì Revolut ti olùtajà, tẹ Ṣàmìsíi bíi Ti Sanwó kí olùtajà náà lè fa BTC kalẹ̀ kúrò ní ẹ́síkírò. Òhun nìyẹn! O ti ra Bitcoin ní àṣeyọrí nípasẹ̀ lílo àkántì Revolut rẹ.