Ra Bitcoin (BTC) pẹ̀lú NEM

Paxful jẹ kí ó rọrùn tí o si pèsè ààbò fún ọ láti ra àti di kọ́rẹ́ńsì-kírípítò mú. Wá ìnájà tí ó dára jùlọ ní ìsàlẹ kí o ra kọ́rẹ́ńsì-kírípítò pẹ̀lú NEM lónì.

Jọwọ dúró lákòkò tí à ń wá àwọn ìnájà tí ó dára jùlọ fún ọ.

Rà Láti

Sanwó pẹ̀lú

Òṣùwọn fún Bitcoin

Bíí ó ṣe Le Ra Bitcoin lórí Paxful

Níbí ní Paxful, ibi-afẹdé wa ní láti jẹ kí àwọn iṣẹ ìṣúná wọlé sí mílíọnù ènìyàn kákìri ayé. A fẹ láti fún àwọn ènìyàn ní àyè láti lo owó níbikíbi tí wọn ríí pé o yẹ kí o mú ìlọsíwájú dára sí ìgbésí àyé wọn lójoójúmọ.

Ìkànnì wa ń ṣiṣẹ lórí ìlànà ti inawo ẹnìkan-sí-ẹnìkejì, èyítí o fún ọ láàyè láti ra Bitcoin tààrà láti ọdọ àwọn aṣàmúlò mííràn bíí ara rẹ, láìsí pẹlú àwọn báǹkì tàbí àwọn ilé-iṣẹ. Ìwọ yóò di apákan ti agbègbè tí ó ní àwọn aṣàmúlò tí ó jú mílíọnù mẹta lọ, gbogbo wọn ti wá sí ọdọ wa pẹlú ìpinnu ti níní ìṣàkóso lórí àwọn ètò-ìṣúnáwọn.

Rírà kírípítò lórí Paxful jẹ́ irọrun; kàn tẹle àwọn ìgbésẹ̀ wọ̀nyí:

  1. Forúkọsílẹ̀- Ṣẹdá àkántì kan àti pé ìwọ yóò gba wálẹ́ẹ̀tì Bitcoin ọ̀fẹ́ tìrẹ láìsí ìdíwọ́.
  2. Àwọn àdéhùn ìfẹnukò - Lọgán tí o bá ní àkántì kan, yan ọnà ìsanwó, iye Bitcoin tí o fẹ láti rà àti kọ́rẹ́ńsì tí o fẹ, kí o tẹ Wá àwọn ìnájà. Ṣàwàrí nípasẹ àtòkọ ti àwọn ìnájà tí o wà, yan èyí ti o bá àwọn ìbéèrè rẹ mu júlọ, kí o ṣe àtúnyẹwò àwọn àdéhùn ìfẹnukò olùtajà náà.
  3. Bẹ̀rẹ̀ òwò - Tí o bá ní ìtẹlọrùn pẹlú àwọn àdéhùn ìfẹnukò olùtajà náà, tẹ iye Bitcoin ti o fẹ rà, kí o bẹrẹ òwò náà. Èyí yóò ṣíí ìtàkurọ̀sọ ojutaye pẹlú olùtajà náà. Tẹlé àwọn ìtọ́nísọ́nà ti olùtajà láti sanwó náà kí o sí ṣe ìjẹrisi rẹ.
  4. Gba Bitcoin náà - Lẹ́yìn èyí olùtajà yoo fi Bitcoin silẹ taara sinu Wálẹ̀tì Paxful rẹ.

O tún lè wo fídíò alálàyé wa lórí bí o ti lè ra Bitcoin lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀.

Lẹ́yìn ìparí òwò Aláṣeyọrí kan, o lè fi ránṣẹ tàbí kí o ná Bitcoin sí wálẹ́ẹ̀tì èyíkéyì tàbí kí o mu tààrà láti inú Wálẹ̀tì Paxful rẹ.

Pẹlú àwọn ìlànà ìsanwó tí ó ju 300 lọ ti ó wà, ríra Bitcoin lórí ayélujára kò rọrùn rárá. Láti owó àti àwọn ìfiránṣẹ́ báǹkì sí àwọn káàdì ẹ̀bùn àti àwọn áàpù ìsanwó, o lè yan àṣàyàn tí ó báamu jùlọ fún ọ. Tí o bá ní ìlànà ìsanwó ó tí o fẹ ti ìwọ kò ríí, jẹ kí a mọ àti pé a yóò tiraka láti jẹ kí o ṣẹlẹ.

Yára ṣòwò, ní àiléwu tí ó sì láàbò pẹlú ibi ìtajà enìkan-sí-ẹnìkejì ti Bitcoin lórí Paxful. Bẹ̀rẹ̀ lóní!