Jọwọ dúró lákòkò tí à ń wá àwọn ìnájà tí ó dára jùlọ fún ọ.

Buy from

Sanwó pẹ̀lú

Price per Bitcoin

Bí o ṣe lè ra Bitcoin pẹ̀lú Apple Pay

Sísọ àṣẹ́kù Apple Pay rẹ di Bitcoin rọrùn ó sì ní ààbò lóri Paxful. Ẹ́síkírò ń dáàbò bòó, ibi ìtajà ẹnìkan-sí-ẹnìkejì wa gbà ọ́ láàyè láti ṣ'òwò pẹ̀lú ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn olùtajà Bitcoin káàkiri àgbáyé, ní èyíkèyí ọjọ́ ọ̀sẹ̀sẹ, láìní láti san àwọn owósan àfikún. O lè ra Bitcoin nípa lílo Apple Pay ní àwọn ìgbésẹ díẹ̀ tí wọ́n rọrùn:

Kọ́kọ́ wọlé sí àkántì Paxful rẹ tàbí ṣ'èdá ọ̀kan tí o bá jẹ́ àjèjì sí ìkànnì náà. Lọ́gán tí o bá wọlé, tẹ Ra Bitcoin kí o sì sètò "Apple Pay" bíi ìlànà ìsanwó tí o yàn láàyò láti fi gbogbo ìnájà tó bá àwọn ìnílò rẹ mu hàn.

Ní àkọ́kọ́, a dábàá wíwọ asàpèjúwe olùtajà kọ̀ọ̀kan àti kíkà àwọn àtúnyẹwò láti ọ̀dọ̀ àwọn olùrajà àtẹ̀yìnwá láti ṣàyẹ̀wò ìgbẹkẹ̀lé wọn.

Nígbàtí ìwọ́ bá rí ìnájà ńlá láti ọ̀dọ̀ olùtajà tó ṣeé fọkàntán, tẹ láti ka àwọn àdéhùn ìnájà wọn. Olùtajà kọ̀ọ̀kan ní àwọn àlàálẹ̀ ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ sùgbọ́n púpọ̀ nínú wọn yóò nílò rẹ láti fi ẹ̀dà onídíjítà Ìdánimọ̀ tí o gbà láti ọwọ́ ìjọba àti agbàwòrántán tó ń ṣ'àfihàn pé àwọn owó náà gangan ti wà ní Apple Pay ránṣẹ́.

Tí o bá faramọ́ àwọn àdéhùn náà, tẹ Gba Àwọn Àdéhùn kí o sì Ra Bitcoins Nísìín! láti bẹ̀rẹ̀ ìtàkurọ̀sọ ààyè pẹ̀lú olùtajà náà. Fi ìsanwó ránṣẹ́ nígbàtí olùtajà bá sọ fún ọ nìkan kí o sì yára tẹ Ṣàmì síi bíi Ti Sanwó léyìn tí o bá ti fi àwọn owó náà ránsẹ́ láti àkántì Apple Pay rẹ. Lọ́gán tí olùtajà bá ṣ'àrídájú ìdúnadúrà náà, wọn yóò fa BTC sílẹ̀ sí Wálẹ́ẹ̀tì Bitcoin Paxful rẹ.

Òhun nìyí, o ṣẹ̀ṣẹ̀ ra BTC pẹ̀lú Apple Pay! O lè wá lòó láti sanwó fún àwọn iṣẹ́, pàṣẹ àwọn ọjà, tàbí lòó fún àwọn ìdí àsọtẹ́lẹ̀. Fún àwọn ìbéèrè, èsì, tàbí àwọn ìfiyèsí nípa ìkànnì wa, tẹ Kàn sí Wa láti kàn sí ẹgbẹ́ àtìlẹ́yìn alábàárà wa.