Kíọ̀sì Paxful

Kọ̀rẹ́nsì fíàtì tí ó lágbára ní ìlànà-àbùjá láti gbé agbára wọ àwọn ìlàkààkà rẹ lórí díjítà

Paxful jẹ ibi ìtajà ẹnìkan-sí-ẹnìkejì Bitcoin tí ńfi òmìnira owó sí gbogbo igun àgbáyé. Kíọ́sì wa ṣe àfikún òmìnira yíí sí àwọn pàṣípààrọ̀ kọ́rẹ́ńsì onídíjítà láti ṣe ìrànlọwọ fún àwọn oníbárà láti ṣe agbátẹrù ìfowónàá sí àwọn àkántì Bitcoin wọn. Kò tán ṣíbẹ̀? Wàá gba owó ìbanipolówó àdáṣe lórí gbogbo àwọn rírà ti àwọn oníbárà tuntun tí o mú wá sí Paxful bá ṣe, títí láíláí.

Àwọn ìgbésẹ 3 péré tí ó rọrùn

  • 1. Ṣẹ̀dá kíọ́sì Bitcoin àifójúrí rẹ

  • 2. Gbé sori wẹ́búsáìtì rẹ tàbí ìkànnì rẹ

  • 3. Gba àṣàyàn owó-èrè 2% lórí gbogbo títà

Ṣẹda Kíọ̀sì Paxful kí o gbé òwò rẹ ga lónì!

Nipa fiforukọṣilẹ o gba fún Ìfẹnukò Ìlò, Ètò ìbanipolówó Ìfẹnukò Ìlò, àtiìfitónílétí Onípamọ́

Àwọn orúkọ tó làmìlaaka nínú kírípítò lo n lò ó

Pẹlú ìwà wíwà ojútù sí ìṣòro lọ́nà tóyá wa ó yára gaan àti rọrùn láti mú aṣàmúlò tuntun wọ inú wa láti bẹrẹ pẹlú Bitcoin. Díẹ nínú àwọn orúkọ ńlá jùlọ nínú ìṣòwò tẹlẹ ńlo kíọ́sì wa àtí nítorínáà o yẹ kí ìwọ́ náà lè ṣe bẹ́ẹ̀!

Bitmart

Àjọṣepọ wa pẹlú Bitmart báyì ń jẹ ki àwọn aṣàmúlò ra àti ta àwọn kọ́rẹ́ńsì onídíjítà nípa lílo Kíọ̀sì Bitcoin Paxful

Àwọn ànfàní pàtàki fún lílo kíọ́sì Bitcoin

Àwọn ànfàní pàtàki fún lílo kíọ́sì Bitcoin

Yíyára ìṣètò àti ìrọrùn láti ṣe àkànṣe

O lè ṣe àkànṣe kíọ́sì rẹ pẹlú àwọn iye tí a ṣe ìpìlẹ̀, àwọn ìlànà ìsanwó, àti bẹbẹ lọ, àti tún àwọn àyípadà ìkunra bíí àwọ àti àmi ìyàsọtọ.

Kò si jìbìtì ìdíyelé padà

Gẹgẹbí olùtajà órí ayélujára kò sí eewu àwọn jìbìtì ìdíyelé padà nítorí àwọn ìsanwó àwọn oníbárà rẹ ibi Ìtajà p2p lo ń ṣaáyan rẹ

Àtìlẹ́yìn fún àwọn olùgbéejáde

A ń pèsè ààyè àkànṣe ojúlówó ti ẹrọ àìlórúkọ fun wẹ́búsáìtì ati awọn áàpù. Ṣe ìwádì síwájú sii ninu awọn ìwé-ìpamọ Olùgbéejáde wa.

Ju àwọn ìlànà ìsanwó 300 lọ

Awọn oníbárà rẹ le lo èyíkéyí ninu awọn ìlànà ìsanwó 350 + láti fi owónàá sínú àwọn àkántì Bitcoin láìsí àwọn jìbìtì ìdíyelé padà.

Ìfinimọ̀nà àbáyọ

Ṣé o jẹ ènìyàn tí ó ní ìmọ àtì dá ńkan ṣe láì kọọ? A gbà. Ati pé o ti ní ààbò wà! Èyí ní ìfinimọ̀nà àbáyọ ìyára tí a ṣẹdá láti ṣe ìrànlọwọ fún ọ láti lóye bí gbogbo rẹ ṣe ń ṣiṣẹ. Èyí yóò fún ọ ní ìyára ní kíákíá.

Wòó lẹ́nu iṣẹ́
Ìfinimọ̀nà àbáyọ Ìfinimọ̀nà àbáyọ
Ìfinimọ̀nà àbáyọ Ìfinimọ̀nà àbáyọ

Ju kọ́rẹ́nsì fìátì on-ramps 300 ti wà nílẹ̀

Awọn oníbárà rẹ le lo eyikeyi ninu awọn aṣayan isanwo 350 + ti a gba. Bitcoin ti wa ni àsansílẹ̀ taara sinu àkántì rẹ lori paṣipaarọ rẹ tabi ìkànnì.

Àwọn ìfowóránṣẹ́ Báǹkì

Paxful ń ṣe àtìlẹ́yìn fún gbogbo àwọn nẹ́twọọ̀kì bánkì àgbáyé. Ìfowóránṣẹ́ bánkì ma ń sábà wà ní àgbègbè, àsansílẹ̀ owó dẹ̀ ma ń ṣẹlẹ̀ láàrín ọjọ́ kan.

Àwọn wálẹ́ẹ̀tì ayélujára

Àwọn aṣàmúlò rẹ lè sanwó nípasẹ èyíkèyí nínú àwọn wálẹ́ẹ̀tì onídíjítà olókìkí fún Bitcoin wọn.

Ìsanwó àgbàsọ́wọ́

Gba àsansílẹ̀ owó àgbàsọ́wọ́ agbègbè lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ní àgbáyé pẹ̀lú on-ramps owó àgbàsọ́wọ́ ẹnìkan sí ẹnìkejì ti Paxful tó n rẹ̀síi. Ó dára jùlọ fún àwọn tí kìí lo bánkì.

Àwọn Káàdì Dẹ́bítì/Kírẹ́ditì

Ọnà tó rọrùn, ààbò àti ìrọrùn fún àwọn aṣàmúlò láti ra Bitcoin lórí ayélujára.

Àwọn kọ́rẹ́ńsì onídíjítà

Àwọn aṣàmúlò le pẹ̀lú ìrọrùn àti fì ìrọrùn rọpò ọjà wọn pẹ̀lú àwọn kọ́rẹ́ńsì-kírípítò tí ó gbajúmọ mííràn fún Bitcoin díẹ.

Àwọn Ìbéèrè tí wọn Ma ń Sábà Béèrè

Ṣé kòyéwa? Èyí ni díẹ nínú àwọn ìbéèrè tí ó wọpọ jùlọ tí àwọn aṣàmúlò Kíọ́sì mííràn ṣáájú rẹ máa ń béèrè, àti àwọn ìdáhùn wa fún wọn, láti ṣàlàyé ohun gbogbo ní yékéyé fún ọ.

Bẹ́ẹ̀ni. Kíọ́sì ti Paxful jẹ ojútù ti ó bójúmu fún ọ. Nípa ṣíṣètò Kíọ́sì wa lórí pàṣípààrọ rẹ, wàá pèsè kọ̀rẹ́nsì fíàtì ní ìyára àti ìrọrùn ní ìlànà-àbùjá fún àwọn Oníbárà rẹ.

Ṣètò àkántì kan ní Paxful.com , lẹhinna fọwọsí ìgbékalẹ fọọmù KYC.

A lè fi Bitcoin Oníbárà rẹ ránṣẹ sí wálẹ́ẹ̀tì àpapọ̀ tí o ní, tàbí sí àdírẹ́ẹ̀sì wálẹ́ẹ̀tì aláìlẹgbẹ wọn lórí ìkànnì rẹ.

Bẹ́ẹ̀ni. O lè ṣè àkànṣe àwọ̀ kí o ṣàfikún ìyàsọtọ ti ara rẹ síi.

Kíọ́sì gba ìráyè sí gbogbo àwọn kọ́rẹ́ńsì ti Paxful ṣe àtìlẹyìn fún àti àwọn ìlànà ìsanwó.

Bẹ́ẹ̀ni, o lè ṣètò Kíọ́sì pẹlú àwọn ìnájà tìrẹ.

Àwọn olùtajà lori ìkànnì Paxful ni ó máa n faragbá eewu jìbìtì ìdíyelé padà . Lọgán tí a bá ti fi Bitcoin Oníbárà rẹ ránṣẹ sí ọ, kò sí eewu jìbìtì ìdíyelé padà fún ìṣòwò rẹ.

A ní òṣìṣẹ ńlá, tí ó mọ dáradára tí ó ju ènìyàn 100 lọ lágbára. Wọn wà déédé àti yánjú àwọn àríyànjiyàn 24/7.

Ó jẹ ìlànà ìgbésẹ-3 tí ó rọrùn àti pé ó yẹ kí o ní ànfànì láti múu ṣiṣẹ́ láàrin àwọn ìṣẹjú péré díẹ̀.

Ó jẹ àìléwu kanná bí ìdókòwò lórí Paxful.

Dáṣìbọọ̀dù Kíọ̀sì lóri àkántì Paxful rẹ yóò fún ọ ní gbogbo àwọn àlàyé àti àwọn ìṣirò ti àwọn kióósi rẹ àti àwọn owó-àpawolé wọn.

Àwọn owo-apáwọlé rẹ ní a san ní Bitcoin lẹyìn ìdúnàádúrà ríra kọọkan, tààrà sí wálẹ́ẹ̀tì Paxful rẹ.

Rárá, àwọn Oníbárà rẹ kìí yóò lọ kúrò ní wẹ́búsáìtì rẹ. Wọn lè ra Bitcoin wọn láti ọtún láàrín wẹ́búsáìtì rẹ.

A ní ètò KYC tí a ṣe déédé àti ti àdáni tí o dà lórí sọfitiwìa ẹnìkẹta Jumio. Àwọn aṣàmúlò KYC’d nílò ìdánimọ̀, fọ́tò-àdáyà, àti POA. Àwọn ẹyà tí o wà tí o dà lórí ìwọn dídún àti ẹkọ-ayé tí ó nílò àwọn aṣàmúlò sí KYC.

Àwọn Oníbárà rẹ yóò ní yíyàn láti lo èyíkèyí nínú àwọn ìlànà ìsanwó tí ó ju 300 lọ tí a gbà lórí Paxful. A ń ṣe àfikún àwọn ìlànà ìsanwó tuntun púpọ̀ sí àtòkọ yíí.

Àwọn ìlànà ìsanwó tí ó ń léwájú ní àwọn ìfiránṣẹ́ banki agbègbè, Paypal, SEPA, kírediti Káàdì, Western Union, Alipay, ati Káàdì Vanilla.

Kíọ́sì wà fún lílò lórí àwọn wẹ́búsáìtì ti ara rẹ, àwọn búlọọgì, àwọn ìkànnì YouTube àti bẹbẹ lọ.

Bẹ́ẹ̀ni, a lè ṣiṣẹ pẹlú ẹgbẹ títà wa láti wá àwọn ọnà oríṣiríṣi láti ṣe ìkéde ìbátan tuntun.

Kíọ́sì ń sin gbogbo àwọn oníbárà káríayé ní àwọn orílẹ-èdè tí kìí ṣe ti OFAC, gẹgẹ bí ìkànnì àkọkọ wa ṣe hùwà. A ní àwọn ìpílẹ aṣàmúlò tí ó lágbára ní gbogbo orílẹ-èdè pàtàkì àti kọ́rẹ́ńsì orílẹ-èdè.

Àwọn Ìbéèrè tí wọn Ma ń Sábà Béèrè Àwọn Ìbéèrè tí wọn Ma ń Sábà Béèrè
Ṣetán fún kíọ́sì Bitcoin tìrẹ? Ṣetán fún kíọ́sì Bitcoin tìrẹ?

Ṣetán fún kíọ́sì Bitcoin tìrẹ?

Ṣíṣètò Kiosk Bitcoin Paxful rẹ jẹ ìyára àti ìrọrùn. Kàn ṣẹdá akọọlẹ kan, fún kíọ́sì rẹ ní orúkọ, àti pé ètò gbogbo ti tó láti bẹ̀rẹ̀. Bẹ̀rẹ̀ báyì!

Ṣẹ̀dá àkántì kan