Gba wálẹ́ẹ̀tì bitcoin ọ̀fẹ́, aláàbò rẹ

Ọnà tí ó rọrùn àti àìléwu láti ra, ta, firánṣẹ, àti tọjú Bitcoin rẹ.

Gba wálẹ́ẹ̀tì bitcoin ọ̀fẹ́ rẹ

Gba wálẹ́ẹ̀tì bitcoin ọ̀fẹ́, aláàbò rẹ

Àwọn àlàyé síwájú sí

Wálẹ́ẹ̀tì Bitcoin tí o lè fọkàntán

Ju àwọn ènìyàn mílíọnù 3 lọ ló ti lo wálẹ́ẹ̀tì Paxful láti fi ránṣẹ àti gbà ju 40,000 BTC lọ. Àwọn ẹyà ààbò tí ó dára jùlọ lákẹgbẹ́ jẹ kí ó jẹ ọkan nínú àwọn wálẹ́ẹ̀tì tí ó gbẹkẹle jùlọ ní àgbáyé - nítorínáà ìwọ kìí yóò nílò látí yan láàrín ààbò àti ìrọrùn.

Wálẹ́ẹ̀tì Paxful n ṣíṣẹ, àìléwu, àti rọrùn láti lò lórí gbogbo àwọn ẹrọ rẹ. O lé ṣàkóso àwọn ìṣúná owónàá rẹ ní rọọrùn àti gbé owó sórí ẹ tààrà nípasẹ ibi ìtajà ẹnìkan-sí-ẹnìkejì wa, àti firánṣẹ tàbí gba Bitcoin, nípa títẹ àwọn bọ́tìnì díẹ .

0% Kò sí àwọn owó-èrè sísan
$6,000,000 Àwọn oníbàárà aláyọ̀
+$2,000,000 Wálẹ́ẹ̀tì Paxful

Àwọn ànfàní

kò tíì dá ọ lójú? Ó yé wa. Èyí ní díẹ nínú ìdí tí ó fi yẹ kí o gba Wálẹ́ẹ̀tì Paxful.

Ààbò

Ní Paxful, a mú ààbò owó rẹ ní òkúnkúndùn. Ìjẹ́rìísítí ó múná àti àwọn ìbéèrè ọrọ ìgbaniwọlé ríi dájú pé ìwọ nìkan ní ènìyàn tí ó ní ìráyè sí owó rẹ.

Ẹ̀rọ̀

Gbádùn òmìnira ti àwọn ọnà tí ó ju 300 lọ láti ra tàbí ta Bitcoin rẹ. Ibi ìtajà ẹnìkan-sí-ẹnìkejì wa so ọ pọ láìléwu àti ní ìkọkọ pẹlú àwọn ènìyàn gidi gẹgẹ bí ìwọ.

Òmìnira

Wọlé sí owó rẹ ní ààbò níbikíbi, nígbàkugbà. Ọpẹ lọ́wọ́ agbára awọsanma, ìwọ kìí yóò pàdánù owó rẹ pàápàá tí o bá pàdánù ẹrọ rẹ.

Àwọn aṣàmúlò wa fẹràn wa!

Wo ohun tí ènìyàn ní láti sọ nípa wa.

Bí a ti ríi lórí ...

Gba wálẹ́ẹ̀tì Bitcoin Paxful ọ̀fẹ́ kan báyì!

Ṣe ìdúnàádúrà lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, kí o ra Bitcoin lóní láìsí wàhálà!

il Forúkọsílẹ̀ fún wálẹ́ẹ̀tì ọ̀fẹ́ rẹ.