Káàbọ̀ sí Ẹgbẹ́-Ìṣọ̀kan Paxful Jẹ ki a gbìmọ̀ ṣàgbékalẹ̀ ìgbé ayé tó dara julọ

Jẹ olùkópa ti ètò ilolupo ti o ṣe ìrànlọwọ fún ọ láti pèlé agbára rẹ, kí o wá àwọn ẹni tí o èrò ìfarajìn bí tìrẹ láti báṣepọ . Kó àwọn ohun èlò rẹ pọ, pín ìran rẹ, ṣiṣẹ pọ, àti ṣàgbékalẹ̀ àwọn ohun ńlá fún àwọn agbègbè rẹ.

Jẹ́ká ṣíṣẹ́ papọ̀

Kíni ìdí ti o fi darapọ mọ Ẹgbẹ́-Ìṣọ̀kan Paxful ?

À ń mú àwọn àjọ àti àwọn ẹnì-kọọkan jọ láti gbogbo àwọn ìgbésí ayé. Àwọn ìṣòwò, àwọn ẹnì-kọọkan, àti àwọn aláìwáèrè lè báyì ṣe ìfọwọ́sowọ́pọ̀ lórí àwọn ibi-afẹdé ti wọn pín àti àwọn ìwòye fún àwọn agbègbè wọn. Ọpọlọpọ wà láti jèrè nínú ìsopọ̀ yíí:

Ṣe dáadáa tó pọ

Wá àwọn ènìyàn bi-ọkan mííràn kí o fi ọwọ kan àwọn ìgbésí ayé púpọ̀ síi pẹlú iṣẹ tí ó nílárí lórí àwọn àwùjọ tí o ní ìfẹ́.

Ṣe àtànká ọ̀rọ̀ rẹ

Ṣe ìfọwọsówọpọ lórí àwọn ìpolongo PR àti tàn káàkiri àmì ìyàsọtọ nípa rẹ ju ti tẹlẹ lọ.

Ṣe ìhìnrere àti kọ ẹ̀kọ́

Ṣẹdá ìmọ ti àwọn ọjà rẹ tàbí àwọn ìṣòwò ní àwọn agbègbè-ayé tuntun àti kí o wà ní iwájú ṣiṣe ètò ìmúlò ti ó jẹmọ́ iṣẹ́ rẹ.

Dúró ní ìṣọkan lòdì sí ìpọnjú

Parapọ̀ tako ìdíje ti o wọpọ kí o fi wọn sílẹ nínú dígí ìwò-ẹyìn rẹ. Ìṣọ̀kan jẹ́ agbára.

Gbọ́ àgbọyé àwọn òfin agbègbè

Wá ìrànlọwọ tó tọ láti jẹ kí ìṣòwò rẹ pa àwọn òfin agbègbè mọ ní àwọn ọjà tuntun.

Ṣe ìmúgbòòrò àwọn olùgbọ́ rẹ

Lọ ní káríayé, wọ àwọn ọjà tuntun, kí o ní ìráyè sí ìpìlẹ aṣàmúlò tí ó tóbi púpọ fún àwọn ọjà tàbí iṣẹ rẹ.

Wá Alábàákẹ́gbẹ́ rẹ

Gbogbo ẹ dun létí, ṣùgbọn o sì ń ṣiyèméjì ibití ó yẹ ọ? Bóyá o wá ní fintech tàbí philanthropy, Alábàákẹ́gbẹ́ Paxful wà fún ọ. Èyí ni àwọn oríṣiríṣi àgbáríjọ fún ọ láti ṣepọ àti ànfàní.

Ètò ẹ̀kọ́

Ṣe ìrànlọwọ láti kọ àwọn àwùjọ lẹ́kọ̀ nípa àwọn àṣà tuntun ní kíripítò àti tẹkinọ́lọ́jì

Báǹkì àti ìṣùná

Ìgbàjọbà àwùjọ́ àwọn ètò ìṣúná pẹlú àwọn ìmọràn ìmọ̀tuntun rẹ àti ṣàgbékalẹ̀ àwọn ojúlówó ọjà títà ti yóò mú àyípadà rere bá ọjọ iwájú owó.

Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ & PR

Tan ọrọ rẹ ká sí gbogbo àgbáyé, pẹlú ìfiránṣẹ tì ó tọ, dé ibi tí ó jìnnà ju ti àtẹ̀yìnwá lọ

Ọjà Kọ́rẹ́ńsì-kírípítò

Kojú ọpọlọpọ àwọn ìpènijà ni ààyè kírípítò, ṣàwárí àwọn ọjà àti àwọn ànfàní tuntun

Ìdánilárayá àti èré

Léwájú nínú eré àti idanilaraya tí ó dà lórí kírípítò. Mú gbogbo àwọn ìmọràn eré ìtura rẹ wá sí ayé.

Àwọn mìíràn

Ohùnkan mííràn tí ó ń wá láti ṣè ìfọwọ́sowọ́pọ̀ lórí. Ìwọ kò mọ àwọn ìfẹ ẹniti àwọn ìmọràn rẹ yóò tají!

Ṣetán láti gbéra? Jẹ́ká ṣíṣẹ́ papọ̀